Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose
[ Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose ]

·Won Ni Akeem Pa Sajenti Opeyemi Iyawo Re, O Ti N Se Faaji Lewon Bayi
·Eyi Ni Bi Pasito Se Gbe Majele Je Ni Ipinle-Ogun
·Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
·Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
·Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
·Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
·Orekunrin Bukola Fee Fi i Soogun Owo N'Ibadan
·Nitori Wahala Ojoojumo, Igbeyawo Odun Mefa Tuka L'Osogbo
·Won Ti Ran Oga Ileewe To Fipa Ba Akekoo Re Lo Po Lewon Odun Mewaa L'Ekiti

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


A Tie Gbo Tawon Ti Won N Gbera Won Lenu Jo Lasan: Ta Ni Yoo Mu Awon Eleyii So Bi
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
Lati Owo Ademola Adejare

A Tie Gbo Tawon Ti Won N Gbera Won Lenu Jo Lasan: Ta Ni Yoo Mu Awon Eleyii So Bii Eran?

Bee ni won n gbe ara won lenujo lasan ni. Won kan n so ohun to wu won naa ni. Gbogbo e naa, ori ohun ti kaluku yoo je lo da le lori. Awon ara adugbo awon Jonathan kan ko ara won jo, won ni bi ko ba ti wole leekeji, ko gbodo pada wa si odo awon mo o. Won ni gbogbo ohun to ba fee se ni ko se, gbogbo ona to ba fee gba ni ko gba, o saa gbodo ri i pe oun di Aare Naijiria leekeji, ko si maa sejoba naa lo.

Sugbon kekere ni tawon yen o, awon oba ati awon agbaagba Urhobo waa dide ni tiwon, won ni bi Jonathan ko ba fi wole leekeji, awon yoo rin ihooho lati ilu awon de Abuja. E gbo, ta lo n di won lowo! Ta ni yoo so pe ki eni to ba fee rin ihooho ma rin in. Ta ni yoo so pe ki eni to ba fee sora re di were nitori oro ti ko modi ma se bee lawujo.

Awon eeyan wonyi ti gbagbe pe ki i se Jonathan ni yoo dibo funra e, bee ni ki i se iran won nikan ni won yoo dibo fun un, gbogbo Naijiria ni. Bo ba se daadaa, won yoo dibo fun un, bi ko si se daadaa, won ko ni i dibo fun un, nibi ti oro wa niyen.


Afi bo ba je ojooro ati eru loun ati egbe won se lo ku, eleyii naa ko si le lo bee lasan, yoo pada di wahala gidi leyin ola ni. Awon eeyan yoo maa ke tantan pe afi ki eeyan tiwon naa wa nile ijoba, won ko ni i mo boya eni naa kun oju osunwon tabi ko kunju osunwon, boya eni to le sejoba daadaa ni tabi eni ti ko le sejoba, won yoo saa ni ko maa lo sile ijoba nitori pe o ti je omo adugbo won. Aseyinwa aseyinbo, eni naa ko ni i wulo fun araale, ko ni i wulo fun araata.

 Ohun ti awon eeyan wonyi ko mo ni pe isoro to n koju Naijiria lowolowo yii ju eyi ti a o maa fi ja ija eleyameya lo, ija ti a n ja naa lo gbe wa debi ti a wa yii, bi a ko si sora, ohun ti yoo fo wa si wewe pata niyen, ti ko si ni i seni kan ti yoo ri kinni kan gba, ofo ni gbogbo e yoo si ja si fenikeni. E je yaa je ka sora wa gidi, nitori bo ba sele tan, ko ni i mo ni ti eni kan.

Ta Ni Yoo Mu Awon Eleyii So Bii Eran?

Nitori iru awon nnkan bayii naa ni awon eeyan ti ko ye ka gbohun won, awon to ye ki won wa nisale ewon, ki won ti so won sibi ti araalu ko ti ni i gbooorun won rara ti maa n ni enu oro, ti won yoo si maa so isokuso, ti won yoo si maa soro ti ko mu opolopo dani tabi oro to le di alaafia ilu lowo.

Ilu ti nnkan ba ti daru, ti eni to je olori ijoba ko ba mo eyi ti yoo se, iru won ohun to maa n sele nibe ree. Tabi eyin ko gboro ti okunrin kan ti won n pe ni Asari Dokubo n so, oro rirun, oro katikati, oro bii oro digbolugi.

Akoko ni pe o so pe ti Jonathan ko ba le wole leekeji, tabi ti won ko ba dibo fun un, awon yoo pin Naijiria si wewe ni. Bo ba je ni orile-ede ti nnkan ti lo deede ni, loju-ese lo ye ki won mu iru eni bee, loju-ese lo ye ki won ti ti i mole, loju-ese lo ye ki won ti sedajo e, bi oun ba ti wa logba ewon, yoo di eko fun awon to ku, ko si senikan ti yoo maa fenu re so isokuso bee kaakiri.

Sugbon Jonathan ko mu un, bee ni ko si je ki won de odo re, nitori loju tire, yoo ro pe awon ti won feran oun ni, ko ni i mo pe awon ti won kan n foruko oun jeun lasan, awon ti won n wa ohun ti won yoo je kiri ni. Nigba ti Jonathan ko mu Asari Dokubo, awon eeyan gba a nimoran, won ni ko mu un lo daa, bi bee ko, awon ti won yoo ba Naijiria je niyen.

Kin ni Asari Dokubo gbo bee si ni, nise lo tun fo dide, lo ba ni ko seni to le mu oun, enikeni to ba gbiyanju e, lojo ti won ba ti mu oun penren, lojo naa ni Naijiria yoo dopin ti ko ni i si ohun to n je bee mo.

Oro wo lo buru ju eleyii lo, sugbon nitori pe ilu ti baje, ko seni to le mu iru awon eeyan jakujaku bayii, awon ti ko nise gidi kan lowo, to je nibi ilu ti ko dara lawon ti n jeun. Bee bi nnkan ba n lo bo se n lo yii, afaimo ni a ko ni i fi oro Naijiria yii pitan buruku o.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, September 08 @ 17:28:01 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"A Tie Gbo Tawon Ti Won N Gbera Won Lenu Jo Lasan: Ta Ni Yoo Mu Awon Eleyii So Bi" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: