Gbagede Yoruba
 



Asasi Abi Eedi! Fijilante Yinbon Pa Wale N'Iperu
 
Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
Lati Owo Johnson Akinpelu, Abeokuta

Asasi Abi Eedi! Fijilante Yinbon Pa Wale N'Iperu

Afi bii eedi loro naa fawon to wa ni garaaji Iperu lose to koja nigba ti okunrin kan ti won n pe ni Akimu Adegboyega, to n sise fijilante lo sibi tawon kan ti n fa oro ti ko to nnkan lowo, to si yinbon pa okan ninu won.

Gege b'Iwe Iroyin Yoruba se gbo, ni nnkan bii aago mejo aabo ale ojo Eti, Fraide, ose to koja lohun-un nisele naa waye ninu garaaji Iperu nigba tawon eeyan sadeede gburoo ibon, ki won si too mo ohun to sele, won ti ba Wale nileele nibi to ti n japoro.



Iwadii fi ye wa pe ounje ni Wale n ba iya e to n je Tawakalitu ta, ko si seni ti ko mo won ninu garaaji naa. Sugbon lale ojo tisele buruku naa waye, won ni olokada kan ni oun ati Wale jo n fa oro laarin ara won, owo lo fa ariyanjiyan naa.

Ariwo yii ni Akimu fijilante gbo to fi loo ba won. Awon kan to ba akoroyin wa soro so pe afi bii igba ti egun n gun eeyan lo se gun okunrin yii to fi da si oro ti won ko pe e si.

Won ni ko ti i so nnkan kan to fi yinbon mo omo naa lese mejeeji, boya o fee fi hale ni sugbon ibon re ti wa ni kike sile, bo saa se yinbon mo omokunrin to ku die ko pe ogun odun naa niyen.


 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, October 27 @ 20:34:33 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam



Comments 💬 التعليقات
 

For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا

Awọn ọna asopọ ti o jọmọ

· Die sii Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
· Iroyin Nipasẹ MediaYorubaTeam


Ọpọlọpọ Itan Ka Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise:
Orin Ewi ni Yoruba - Yoruba Poems: Awon Owe Yoruba Proverbs Alo Oro


Iwọn Abala

Apapọ Dimegilio: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

Jọ̀wọ́ Gba Ẹ̀ẹ̀kejI ki o sI dIbo fun Abala YIi:

O tayọ
O dara pupọ
O dara
Deede
Buburu


Aṣayan


 Ọrẹ-itẹwe Ọrẹ-itẹwe





Akole Atoka Agbo-Oro

Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise



"Asasi Abi Eedi! Fijilante Yinbon Pa Wale N'Iperu" | Buwolu wọle/Ṣẹda Eto Akọsilẹ | 0 Awon Alaiye


Awọn asọye jẹ Ohun ini nipasẹ Iwe ifiweranṣẹ. A Ko Lodidi Fun Akoonu wọn. Nibayi, A Pe Awọn oluka lati jabo Eyikeyi Abusive, Unsuitable And/tabi Islamophobic Content



Ko si awọn ọrọIwoye Ti o gba laaye Fun Aisinisi, Jọwọ Forukọsilẹ
 

Gbagede Yoruba
Akọọlẹ Tirẹ
Ojule Akọkọ  | Awọn Itan Yoruba  | Gbagede Yoruba  | Ifiranṣẹ Ara-ẹni  | Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba  | Koko Mẹwa  | Ẹka Abule  | Ifirohin-Ransẹ  | Iwadi  | Agbeyẹwo  | Ifimufilẹ  | Iwe Akọọlẹ  | Apoti Akọsilẹ  | Isopọ Ọpọnlujara  | Ẹgba Ayelujara  | Ipolongo Wa


Ẹsin Islam الدين الإسلامي Religion of Islam Addinin Musulunci Agama Islam Religión del Islam 伊斯兰教 Dini ya Kiislamu Религия Ислам Religião do Islã イスラム教 Esin Islam 이슬람의 종교 Portal African Muslim Website - Arabic English African Islamic Website For World News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Articles, Radio, Audio, Video, Quran, Hadith, TV Channels, Fatwas, Muslim News, Newspapers, Magazines Headlines, Forums, College, Schools, Universities, Mosques, Quranic, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Ramadan, Vidoes, Books, Fasting, PDFs On EsinIslam.Com And IslamAfrica.Com