Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Niluu Ilora, Tipa Te Olokada Pa, Lawon Egbe E Ba Binu Dana Sun Moto Naa
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Niluu Ilora, Tipa Te Olokada Pa, Lawon Egbe E Ba Binu Dana Sun Moto Naa

Nnkan ko fararo niluu Ilora, nijoba ibile Afijio, nipinle Oyo, lojo Aje, (Monde) ose to koja, nigba ti tipa te olokada kan, Ogbeni Samson, pa, tawon emewa okunrin olokada yii si gbina je, ti won binu sun oko ohun. Ni nnkan bii aago mesan-an aaro ojo naa nijamba ohun waye nigba ti oko akoyanrin nla ohun ti nomba e je Oyo AA 215 EGB pelu okada naa fori so ara won. Lesekese la gbo pe eni to wa alupupu naa, Samson mi kanle, to si jade laye.

A gbo pe oju ese ni awako tipa ohun ti na papa bora. Eyi lo si mu ki awon elegbe re nidii ise yii faraya, ti won fi dana sun oko nla naa pelu ibinu.Gege b’Iwe Iroyin Yoruba se gbo, awon agbe olosin adie kan ni Samson gbe lo soko won laaaro kutu ojo yii, sugbon bo se de adugbo Isale Aro, lona ibi ti won n pe ni Folawiyo Farms nigba to n pada bo lo salabaapade oko nla ohun. Bo tile je pe ko seni tisele ohun soju e to le salaye ti aye fi le mo eni to jebi, sibe ohun to han si gbogbo eeyan ni pe awon ohun irinse mejeeji yii kolu ara won, oko tipa ohun si mu okada naa lori gun tere.

Iwe Iroyin Yoruba gbo pe awon agbofinro ti won sare lo sibi isele yii lati tesan olopaa Jobele ni won gbe oloogbe ohun lo sileewosan nla to sun mo itosi, iyen ileewosan ijoba ipinle Oyo, sugbon o se ni laaanu pe nibe lawon onisegun oyinbo ti fidi e mule pe okunrin naa ti lo.

Awon olopaa naa ni won lo seto bi won se gbe oku yii lo si yara ti won n gbe oku pamo si losibitu ohun ko too di pe awon ebi e loo gbe e lojo keji. Irole ojo Isegun, (Tusde), to koja la gbo pe won sinku oloogbe ohun si ona Odo Ogun, niluu Iloraa. Nise lekun n pe ekun ran nise nibi isinku Samson, nitori yato si pe ko ti i dagba rara, won ni inu oyun niyawo e wa, bee lomo to fi saye si kere jojo.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, October 27 @ 20:40:04 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"Niluu Ilora, Tipa Te Olokada Pa, Lawon Egbe E Ba Binu Dana Sun Moto Naa" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: