Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Nitori Oro Ti Ko Kan Won, Lateef Ati Ore E Lu Deborah Loja Iddo, N Lolopaa Ba Ko
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
Lati Owo Olayinka Adedayo

Nitori Oro Ti Ko Kan Won, Lateef Ati Ore E Lu Deborah Loja Iddo, N Lolopaa Ba Ko Won

Nitori ti won da omi alaafia oja White Sands ru, Lateefat Emilagba, eni odun mejidinlogbon ati Abiola Ahmed, eni odun marundinlogoji ti foju bale-ejo Majisreeti to wa l'Ebute-Meta. Deborah Sunday ni won lu bii bara.

Gege bi agbejoro fun ileese olopaa, Effiong Okon se wi, ojo ketala, osu kejo, odun yii, lawon mejeeji yii pitu owo won ninu oja White Sands to wa ni Iddo, l'Ekoo, pelu bi Abiola to loyun sinu ati Lateefat se da soro ti ko kan won, iyen lasiko tawon ti won maa n ja tikeeti fawon oloja n beere owo lowo Deborah to n ta bureedi ninu oja ohun.Nigba ti Deborah ko ri ogun naira naa san, to si fee maa salaye lawon obinrin mejeeji tawon naa je oloja bere si i bu u, ti won si n pe e lorisiirisii oruko. Eyi lo mu obinrin naa maa bu won pada, bee ni Abiola ati Lateefat dawo lu u titi to fi padanu egberun mokanlelogun naira to wa lara re.

Nigba towo awon to wa nibe ko ka won mo ni won pe awon olopaa adugbo naa, ti won si ko won lo si ago won. Bayii ni won dari oro won wa sile-ejo.

Lakooko ti agbenuso ijoba n ka esun sawon obinrin naa leti, o ni esun ole jija, igbimo-po lati sise ibi ati dida omi alaafia adugbo ru ni won fi kan won, eyi to ni o lodi sofin ipinle Eko todun 2011.

Adajo S.O Solebo gba beeli Lateefat ati Abiola pelu egberun meeedogbon naira eni kookan ati oniduuro kookan niye owo kan naa.

O waa sun igbejo mi-in siwaju.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Monday, November 25 @ 06:18:36 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"Nitori Oro Ti Ko Kan Won, Lateef Ati Ore E Lu Deborah Loja Iddo, N Lolopaa Ba Ko" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: