Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara
[ Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara ]

·Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
·Arungun Loko Mi, Gbogbo Irinse Mi Lo Ti Baje, Mi O Fe e Mo Abigail
·Oko Mi Fi Pata Mi Soogun Owo Philomina
·Emi Atoko Mi Ko Ja, Nitori Omo Lawon Ebi Re Se Fee Le Mi Jade - Rafia
·Latodun Merin Seyin Loko Mi Ko Ti Ba Mi Lasepo, Mi o Se Mo - Folasade
·Odo Ni Wolii Moses Ti Ni Ki David Loo We Iwe Isegun, Lo Ba Fogbon Ji Moto Re Gbe
·Oro Buruku Toun Terin: Awon Omo Poli Ojere Mefa Daku Lakooko Ti Won Fee Sedanwo
·O Sele L'Egba! Seun Bimo Kan Fokunrin Meji L'Abeokuta
·Babalawo Fewon Jura Lori Esun Aini Salanga L'Ondo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Idajo Ku Si Dede: Awon Olomooba Kan Ni Dandan Ni Ki Ataoja Osogbo Lo
 
 
Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
Lati Owo Florence Babasola, Osogbo

Idajo Ku Si Dede: Awon Olomooba Kan Ni Dandan Ni Ki Ataoja Osogbo Lo

B o se din die losu kan bayii ti ile-ejo ko-temi- lorun to wa niluu Akure yoo dajo lori ejo ti awon afobaje ilu Osogbo gbe lo siwaju re, orisiirisii oro lo ti n waye lori ohun to le je atubotan ejo naa.

Bi awon kan lati idile olomooba marun-un to letoo si oye Ataoja niluu Osogbo se n so pe dandan ni ki Oba Olanipekun fi ori oye naa sile nitori pe ki i se ara awon, bee lawon afobaje ti won n dari eto yiyan oba niluu naa so pe otito to daju saka ni pe gbogbo ilana lawon tele lori yiyan Oba Olanipekun.

Awon olomooba naa, eleyii ti Alaaji Nasiru Oyeniyi lati ile Gbaemu, Pa Cladius Fayoyiwa lati ile Oluawo, Salami Mogaji lati ile Lahanmi Oyipi, Ashiru Oyewole lati ile Matanmi ati Pa Liasu Olateju lati ile Lajomo (to je apapo Olude ati Aderohunmu) soju fun salaye fun Iwe Iroyin Yoruba pe niwon igba ti ejo mejeeji to wa lati ile-ejo giga ilu Osogbo ti so pe ko si enikeni nipo Ataoja ilu Osogbo lowolowo, idajo kootu ko-te-mi-lorun ko le yato si eyi.Sugbon awon afobaje ni digbi ni Oba Olanipekun wa gege bii Ataoja ilu Osogbo. Won ni ilana fifi oba je niluu Osogbo tijoba ipinle Osun fowo si lodun 2005 lawon tele lati yan oba yii leyin ti Oba Oyewale Matanmi gbese lojo kerin, osu kejo, odun 2010.

Latigba ti Gomina tele nipinle Osun, Omooba Olagunsoye Oyinlola, ti gbe opa ase le Oba Olanipekun lowo lodun 2010 lawon idile olomooba ti gbe awon afobaje ilu Osogbo lo sileejo giga ilu Osogbo pe kin ni won ri lobe ti won fi waro owo nipa fifi eni ti ki i se ara awon je Ataoja.

Awon olomooba ohun salaye pe eegun ni iran Olanipekun gbe wa siluu Osogbo nigba iwase, won ko si lara awon olomooba rara. Won ni awon ti gba ase ile-ejo giga ohun pe ijoba igba naa ko gbodo gbe opa ase fun Ataoja ti won kede oruko re, sugbon tijoba ko eti ikun si idajo ile-ejo, ti won si gbe opa ase fun un lojo kejila, osu kesan-an, odun 2010.

Ninu idajo ile-ejo giga akoko lodo Onidajo Yinka Aderibigbe lojo kejidinlogun, osu keji, odun 2011, o so pe igbese yiyan ati gbigbe opa ase fun Oba Olanipekun ko le duro, ati pe se ni ki won loo bere eto naa lati ibere. Bakan naa ni Onidajo Jide Falola ti ile-ejo giga ilu Osogbo gbe idajo re kale lojo ketadinlogbon, osu kefa, odun 2011, lori ohun ti Onidajo Aderibigbe so saaju.

Sugbon awon afobaje ilu Osogbo mejeejo labe idari Ajagunna tiluu Osogbo, Oloye Gabriel Oparanti, gbe idajo naa lo sile-ejo ko-te-mi-lorun tilu Akure. Awijare won ni pe ko si asise kankan ninu ilana tawon fi yan Oba Olanipekun gege bii Ataoja ilu Osogbo. Oloye Oparanti ni ilana ifobaje odun 1960 niluu Osogbo lo pin awon idile to n joba si meji: Larooye to je okunrin ati Oyipi to je obinrin.

Oni, “Nigba to di odun 1981, ijoba tun gbe ilana mi-in jade, o si so awon idile to n joba Osogbo di merin, awon naa ni Larooye, Oyipi, Lajomo ati Matanmi. Odun 2005 nijoba Osun tun se ilana mi-in, eleyii ti gbogbo awon olomooba mo si, nibe ni won si ti fi idile Sogbo kun idile to n joba niluu Osogbo.

“Koda, awa afobaje o mo nnkan kan nipa eleyii titi di odun 2010 ti kabiyesi ana waja. Nigba ti a fee yan oba, won fi to wa leti pe ilana tuntun ti wa nile lati odun 2005. Mo ranse si ileese oro oye jije nipinle Osun, won si fi ranse si wa.”

Oba Jimoh Olanipekun, Ataoja Osogbo Lara awon ti won tun ba Iwe Iroyin Yoruba soro lori oro yii ni Eesa ti ilu Osogbo, Oloye Nasir Lanloye, Omooba Olasunkanmi Oladosu lati idile olomooba Oyipi, Omooba Mubarak Azeez lati idile Larooye ati Omooba Adebisi lati idile Lajomo.

Omooba Mubarak Azeez ni ko si eni to le so pe Oba Olanipekun ko letoo si ipo Ataoja ilu Osogbo to wa, ati pe ojulowo omooba ni ko too gun ori ite awon baba nla re.

Omooba Oladosu ti ile Oyipi ni tie so pe, “Gbogbo wa la mo pe idile Sogbo lo wa nidii gbogbo oro yii, idile temi gan-an lo si ye ka maa pariwo kaakiri, sugbon a faramo Oba Olanipekun nitori pe idile re lo kan. Bi awa idile to n joba l’Osogbo ba je merin, awa Oyipi lo kan, bi a si se di marun-un bayii, awa Oyipi lo kan.

Ko ti i kan awon Sogbo rara, se ni ki won loo sinmi.” Abalo ababo oro naa ni pe gbogbo awon eeyan ipinle Osun, paapaa awon omo bibi ilu Osogbo, ni won n

foju sona fun ohun ti yoo je abajade idajo ile-ejo ko-te-mi-lorun ilu Akure lojo kerinlelogun, osu to n bo.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Monday, November 25 @ 06:38:31 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· EsinIslam Media Yoruba
· Ekunrere Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere:
Oye Okere Tilu Saki, Ile-ejo Ni Mogaji Ko Gbodo Gbe Igbese Kankan Bayii


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere

"Idajo Ku Si Dede: Awon Olomooba Kan Ni Dandan Ni Ki Ataoja Osogbo Lo" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: