Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
[ Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu ]

·Iwosi Yii Si Ti N Po Ju Fun Yoruba, Ibi Ti Won Ba Wa De Ree O
·Bo Se Daa Niyen... Sugbon Kan Naa Lo Wa Nibe
·Bi Iro Ba Lo Logun Odun...
·Sebi Eyin Naa Gbo Ti Dino Melaye Ni Kogi
·Won Ni Alaga PDP Ku Sori Asewo N'Ipokia
·Awon Asofin Ni Kijoba Apapo Se Afara Elese Si Osodi-Apapa
·E Gbo! Kin Ni Fayose Wa Lo Si China?
·E Ko Sekeseke Si Won Lowo Jare
·Bee Ni Buhari Ko Wi Nnkan Kan

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Loooto Ni Mo Wi Fun Yin, Adelabu Ko Girigiri Ba Awon Awolowo Pelu Akintola
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
Lati Owo Yemi Ogunjobi

Loooto Ni Mo Wi Fun Yin, Adelabu Ko Girigiri Ba Awon Awolowo Pelu Akintola

Laarin odun 1951 si odun 1958, ko sibi ti oselu ti gbona ni gbogbo Naijiria yii to ju ilu Ibadan nile Yoruba lo, kinni ohun gbona jan-in jan-in. Awon meji naa lo si n gbe e gbona o, Adelabu Adegoke Penkelemeesi ati Obafemi Awolowo ni. Sugbon Ladoke Akintola ni igbakeji Awolowo leyin iku Bode Thomas, ati pe nitori pe oun mo Adelabu, o si tun mo opolopo awon omo Ibadan, oun lo fori ko eyi to ju ninu oro naa, nitori nibi ti asaaju ko ba ti raaye dojuko ogun oselu ohun, Akintola ni yoo saaju ogun. Oro naa ko si rorun bee nitori Adelabu feran Akintola, oga re ni ko feran, bee ni Akintola paapaa ko feran Adelabu debii pe ko gbajoba lowo egbe oselu awon, iyen egbe Olope. Oro naa ti waa di aaya gbon Ogungbe gbon, aaya n tiro, Ogungbe n bere, enikan naa ni yoo si reyin enikan. Oro naa ni won n fa lowo nigba ti Salami Agbaje, Balogun ilu Ibadan ku ni ogbonjo, osu kewaa, odun 1953.

Bi oro ba ti je ti ilu Ibadan, gbogbo ara pata ni Adelabu yoo ko si i, ti yoo si maa se bii pe oun ni asoju ati agbenuso ilu Ibadan, eyi si ti je ki ati oba ati ijoye feran re, o ti so ara re di jafojo to n ja fun won, awon paapaa si ti ri i bii enikan naa to le gba won lowo Awolowo, nitori e ni won se n tele e. Bi ko se bee ni, ko sohun to ye ko fa ija ninu pe Balogun ilu Ibadan ku, ki won si yan Balogun tuntun. Bee ni oro naa ko ruju rara, bi won ti n se tele naa ni won fee se, iyen ni pe bi Balogun ba ku, nigba ti otun re wa laye, oun naa ni yoo bo sipo Balogun, iyen ni pe Otun Balogun ni yoo pada waa di Balogun nigba ti Balogun to wa nibe tele ba ku. Salami Agbaje ni Balogun, o ti ku. Oloye I.B Akinyele ni Otun Balogun, oun si ni ipo naa to si, ki won gbe e gori oye naa lo ku, ki oun si di Balogun gbogbo ilu Ibadan patapataSugbon oro ipo naa ju bee lo nigba naa, idi si ni pe odo awon Balogun yii ni ipo Olubadan fi si. Bo se je ni pe bi Oba Igbintade to n je Olubadan nigba naa ba dagba to si pa ipo da, eni to ba je Balogun ni yoo pada di Olubadan, nitori ilana meji naa ni won fi n joye ile Ibadan, ilana tawon ologun, ati ilana tawon oloye. Bo ba se pe ki i se bee ni, bi Oluadan ba waja nigba mi-in, eni to ba wa nipo Otun Olubadan ni yoo gori oye naa, ko ni wahala ninu rara, iyen to ba je ilana awon oloye ni ipo naa kan, ti ki i baa se ilana awon ologun. Sugbon Olubadan to wa loye bayii, odo awon oloye loun ti wa, eyi ti yoo ba si tun je tele e, odo awon ologun ni yoo ti jade. Awon Adelabu mo eyi, won mo pe eni to ba wa nipo Balogun ni yoo je Olubadan bi Igbintade to wa nipo ba wo moto ile lo, nitori re ni won ko se fe ko je enikan ti ko fe tiwon ni yoo di Balogun, koda ko je oun ni ipo naa to si. Bee Akinyele ko fe tiwon loooto, oun naa korira won nitori ariwo ati ija ainidii ti won maa n ja. Omowe ni Akinyele, o si ti di awon ipo pataki mu ninu eto ijoba ibile Ibadan, koda o ti de ipo adajo agba nibe. Bee ipo yii, awon Olubadan lo maa n wa nipo naa, tabi eni ti awon funra won ba fa kale, sugbon ofin tuntun ti wa, ofin naa si ni pe ki won ma gbe eni ti ko ba mowe de iru awon ipo bee yen, nigba ti Olubadan Igbintade ki i si i se omowe, Akinyele ni woon ni ko maa soe ipo naa loo. Akinyeole moo pe oun ko deede de ipo naa, ati pe bi awoon ti woon n soejooba nigba naa ko ba feoran oun, woon ko ni i jeo ki oun gbooorun iru ipo beoeo laelae. Nitori beoeo, oodoo awoon Awoloowoo ni gbogbo ookan reo wa, oomoo eogbeo woon ni ni kooroo, ko si sohun ti woon pa lasoeo fun un ti ko ni i soe. Ohun to n dun awoon Adelabu ree, woon ni bi Akinyeole ba di Olubadan, bii igba ti agbeo gbe oomoo aparo sabeo ti woon n gbin igbado ni o, oomoo eoyeo yoo ri asoiri awoon agbeo dandan.

Ni woon ba beoreo ija ti a n wi yii o, ija pe Akinyeole ko ni i di Balogun ilu Ibadan. Akinyeole sa gilagila, o di oodoo awoon Ladoke Akintoola, o ni ki woon ba oun ba Awoloowoo sooroo, ki eogbeo ma pada leoyin oun lasiko to le yii rara, o ni ki i soe pe oun feoeo fi tipatipa gba oye Balogun Ibadan tabi pe oun n wa ohun ti ko too si oun, oun gan-an ni ipo naa too si nitori oun ni O・tun Balogun ko too di pe Balogun Salami Agbaje ku. Awoon Akintoola ni ko fi ookan ara reo baleo, woon ni ija naa ki i soe ija oun nikan, ija eogbeo ni, nitori awoon moo pe nitori eogbeo O・loopeo, paapaa nitori Awoloowoo lawoon Adelabu ko soe feo eo rara pe ki oun Akinyeole di Balogun. Beoeo ni tootoo, nitori Awoloowoo lawoon ko soe feo Akinyeole nipo, woon ni bo ba gba ipo naa, bii eoni pe Awoloowoo funra reo lo wa nipo ni, agaga bo ba di Olubadan, bii igba pe awoon fi Awoloowoo jeo Olubadan ni, iyeon ni woon soe n fi gbogbo agbara ti woon ni ja si ooroo naa, woon ni ko ni i soee soe.

Loojoo kejila, osou kookanla, oodun 1953, Adelabu ati awoon Eogbeo Olowo-ori (Ibadan Tax Payers Association) reo koowe si awoon oyinbo mejeeji ti woon jeo olori ijooba ileo Yoruba nigba naa, ookan wa to jeo oun ni olori ijooba Ibadan, ekeji si wa to soe pe oun ni olori ijooba ileo Yoruba lapapoo, awoon mejeeji lawoon Adelabu koowe si, iwe naa si gboon-n-gboo;n. Woon ni oodaleo ni Akinyeole, ati pe eosun idaluru ati idoju-ijooba-boleo lawoon fi n kan an, nitori pe o ti wa gbogbo oona lati gbajooba loowoo Olubadan ko si maa gba ojusoe reo soe nitori awoon Awoloowoo to n teole, ti ko si fi bo pe oomoo eogbeo woon loun n soe. Woon ni yatoo siyeon, bawo ni Akinyeole to jeo pe oun ni alaga ijooba ibileo Ibadan igba naa, to si tun jeo oun ni olori ile-eojoo Ko-teo-mi-loorun ijooba ibileo naa yoo soe tun waa di Balogun, woon ni bi ipo naa ba boo si i loowoo, yoo maa fi Olubadan tayin ni, yoo soo ilu naa di tawoon eogbeo O・loopeo, ohun ti oun naa moo pe gbogbo awoon ara ilu Ibadan ko feo.

Awoon Adelabu ni bi Akinyeole ba gba ipo yii, eogbeo Action Group, eogbeo O・loopeo ni yoo maa lo o, woon yoo si maa koo oo si gbogbo oomoo Ibadan, nitori eogbeo naa ko feoran ilu Ibadan, eleyii si le da ogun sileo ti oopoo eeyan yoo ku, nitori beoeo nijooba oyinbo ko soe gboodoo gba, bi eogbeo O・loopeo tileo mu orukoo reo wa, ti woon si soo pe oun lo too si, ki woon ma gba, ki woon wa eoloomiran gbe ipo naa fun ni o, nitori bi woon ko ba tete soe beoeo, nnkan yoo bajeo kooja atunsoe. Bi leota naa ti de ti Awoloowoo ri i, awoon Akintoola lo pe pe ki woon tete maa ba isoeo loo lori reo, nitori oun geogeo bii eoni to wa nijooba, ati geogeo bii eoni ti awoon Adelabu n feosun kan ko le maa gbe ooroo naa ru, awoon ara Ibadan yoo soo pe ohun ti o wi soeo tabi ko soeo ni. Beoeo lo soe pe awoon Akintoola ni woon woogboro, ti woon si wa oona ati eto lati yanju ooroo yii, ti woon ti ile awoon ijoye de ile awoon ijoye, woon soaa n soo fun woon pe Akinyeole ni ki ipo Balogun ilu Ibadan too si.

Sougboon ooroo naa ti ju bi awoon ti mu un loo, nitori Adelabu ti soaaju woon ni gbogbo oona, o si ti gbin ooroo pe Akinyeole ko dara si gbogbo Ibadan sinu woon. Kia ni awoon kan tun ko ara woon joo, eogbeo awoon oomoowe kan bayii, woon ni awoon Ibadan Band of Unity, ko si si ohun meji ti woon n soe ju pe woon koowe si awoon oyinbo to n pasoeo ijooba ileo Yoruba yii pe ki woon ma tileo jeo ki Akinyeole jeo olori ile-eojoo Ko-teo-mi-loorun tijooba ibileo naa moo, ki woon yoo oo nipo naa nitori ko kun oju osounwoon to. Ati pe ki woon ma gba Awoloowoo ati awoon oomoo eogbeo reo laaye lati yan eoni ti yoo soe Balogun Ibadan fun Olubadan, niwoon igba to ti jeo agbalagba ooba ati asoaaju O・ba ni Olubadan, ki woon jeo ki Igbintade yan eoni to ba feo ko soe Balogun oun. Eogbeo Ibadan Band of Unity ni awoon Awoloowoo koriira Olubadan, bi ijooba ba si gba woon laaye ti woon gbe Akinyeole le e lori, woon yoo pada kabaamoo ooroo naa, nitori itajeosileo gidi yoo soeoleo loojoo iwaju ni.

Boya ooroo naa ko ba tileo ma le to beoeo bi ko jeo ofin tuntun ti awoon Awoloowoo n soe. Iyeon ofin tuntun to soo pe ki woon ma fi eoni ti ko ba moowe jeo olori ile eojoo Koteo- mi-loorun ti ijooba ibileo Ibadan. Ko too digba naa, O・ba Igbintade ni olori ileeojoo yii, nigbakigba to ba si jokoo sibeo ni awoon ijoye reo yoo yi i ka, nitori oun lo n dajoo. Bo ba jokoo si igbeojoo, Akinyeole ni yoo wa bii ootun reo, beoeo ni Balogun Agbaje naa yoo wa leogbeoeo reo tabi O・tun Olubadan, awoon ni woon yoo si joo yeo ooroo naa wo ki woon too gba Olubadan nimooran iru eojoo ti yoo da gan-an. Sougboon nigba ti woon ti soe ofin yii, woon ti gba agbara loowoo Olubadan

nitori woon yoo oo kuro nipo naa, woon si fi Akinyeole si i. Iyeon ni pe bi ooroo kan ba le koko, oowoo Akinyeole ni gbogbo agbara wa, eojoo to ba da nijooba yoo teole. Ohun ti awoon Adelabu si n soo niyeon pe bawo ni woon yoo soe soo ijoye Olubadan di ooga reo lojiji, awoon Awoloowoo kan feoeo maa fi O・ba naa wooleo nitori ti ko gba tiwoon ni.

Eyi to waa pabanbari ninu ooroo naa, iyeon ti Adelabu fi mu gbogbo oomoo Ibadan to si feoreo ko woon si abeo orule kan naa ni ariwo to beoreo si i pa kiri pe gbogbo ohun ti awoon Awoloowoo n soe yii, oogboon ni woon n da ki woon le yoo Olubadan Sunmoonu Igbintade kuro nipo reo. Ohun ti woon n gbe kiri fun awoon ara Ibadan ni pe bi woon ba ti le fi Akinyeole jeo Balogun, awoon Awoloowoo yoo sare wa eosun kan lojiji ti woon yoo fi kan Olubadan, nigba naa ni woon yoo yoo oo, ti woon yoo si gbe e loo si eoyin odi kan pe ko gboodoo woo Ibadan moo, niwoon igba to si ti jeo pe bi ko ba ti si Olubadan moo, Balogun reo ni ipo too si, woon yoo soo Akinyeole di Olubadan leoseokeoseo ni, iyeon yoo si di eoru woon, tabi booi booi, nitori ohun ti awoon Awoloowoo ba feo lo gboodoo maa soe. Gbogbo awoon oomoo Ibadan ti woon gbooroo yii ni woon pariwo he ̄on-eo;n-eo ̄n, woon ni ohun ti awoon Awoloowoo feoeo soe niyeon loootoo, oopeoloopeo Adelabu to tu asoiri woon.

Bi ooroo ba ti da bayii, ko seoni ti ko moo Adelabu, eegun reo yoo maa kan ni, oopooloopoo eelo-ija ni yoo si maa fa yoo. Gbogbo ara nija, ko si si ohun ti Adelabu ko ni i lo lati fi reoyin awoon ti woon ba dojukoo oo. Osoelu igba naa dara, ki i soe ka paayan tabi ka maa le oota eoni kiri peolu iboon, sougboon awoon nnkan mi-in wa ti woon maa fi n ba ara woon fa wahala nigba naa, eoni to ba si moo nipa reo ju eonikeji loo ni yoo bori. Loootoo Ladoke Akintoola le sooroo ni gbangba, eonu reo dun, o si moo owe lorisoiirisoii, sougboon eoyin lo fi n too Adelabu Adegoke, nitori oomoo ilu Ibadan ni, Ibadan lo gbe dagba, ko si kuro laarin woon loo siluu oyinbo ka baa soo pe iwa awoon oyinbo kankan yoo moo oon lara. Bi ooroo ba ka Adelabu lara tan, aarin ooja ni yoo boo si peolu ilu dundun ati soeokeoreo, bo ti n darin ni yoo maa jo, ti awoon iyalooja ati awoon oomoode ati agbaagba ilu yoo si beo jade, ibi yoowu to ba si n loo, woon yoo teo le e debeo dandan. Ko tun si iru osoelu beoeo nileo Yoruba leoyin Adelabu; osoelu alariwo, abero-leoyin-yooyoo.

Gbogbo igba ti awoon Akintoola si n mura, oun ati awoon Adisa Akinloye ati awoon oomoo Ibadan to wa ninu eogbeo O・loopeo, gbogbo igba ti awoon n mura lati loooo ba awoon ijoye ati eeyan pataki Ibadan sooroo nni, Adelabu ti kooja lara woon, o ti ya woon sileo, ere leoleo lo n sa loo peolu awoon oniroyin ti ki i fi beoeo sootoo, sougboon to soe pe iroyin ti meokunnu feoeo gboo, ti gbogbo awoon ijoye si feoeo gboo ni woon maa n koo. O・roo ti kari ile, o ti kari oko, lojoojumoo si ni Adelabu n rojoo awoon eeyan yii kiri, ko si oojoo kan ti ooroo naa ko ni i degboro. N ni gbogbo ilu Ibadan ba n roo roogbooroogboo nitori ooroo oye Balogun yii, Adelabu ko si gbe isoeo kankan fun ara reo moo ju isoeo naa loo, bo ba sooroo nibi, yoo sooroo loohun-un, bo si ti n sooroo ni yoo maa ko awoon onilu leoyin, ooroo naa a si maa woo awoon eeyan leti debii pe bi woon ba ri asoaaju eogbeo O・loope kan, boya awoon eeyan bii Ladoke abi Akinloye, woon yoo juko fun toohun ni.

Nigba tooroo naa si le de oju reo, Adelabu ko awoon onilu reo ati awoon olorin woon joo, woon si n lu ilu kiri ilu Ibadan, ni gbogbo ibi ni woon ti n jo ijo woon. Woon ko koorin meji, orin ooroo oye yii naa ni woon n koo, woon si pin orin naa si oona meji, ti woon ba koo ikan ti woon fi bu Akinyeole to feoeo joye funra reo, woon yoo koo omi-in ti woon yoo fi juko ooroo ransoeo si Awoloowoo atawoon eogbeo osoelu reo, ko si si ohun to maa n dun moo awoon eeyan naa ninu ju ki Adelabu darin loo. Bo ba ti darin ni woon yoo gbe e, awoon onisoeokeoreo yoo soo akengbe olowo-eoyoo naa soke, woon yoo tun han an, gbogbo awoon oodoo yoo si maa fo soke laulau, afi bii igba ti Adelabu ti fun woon looti mu.

Beoeo ko fun woon looti mu o, ooti osoelu lo roo si woon nikun, iyeon lo n pa woon bii ooti gidi. Orin ree, ijo ree, nitori ooroo a o jeo Balogun a ko jeo Balogun.

Ni gbangba ode ni Adelabu yoo ti le orin, orin ti yoo fi juko ooroo fun Akinyeole, awoon eeyan yoo si ba a gbe e. Lara orin oriki nla ti Adelabu maa n koo fun Akinyeole ree o: Moo;booroo ̄jeo; O・moo Akinyeole, ta ni yoo fi jeo eo, ta ni yoo fi jeo eo, eoni ti ko to Moogaji to loun yoo jeo Olubadan, ta ni yoo fi jeo eo. “Ma; ba ooroo ̄ jeo;” ni ookan ninu oriki Akinyeole, iyeon naa si ni Adelabu yoo fi boo si gbangba ti yoo maa fi ki i, ti yoo si maa forukoo reo jo kaakiri. Bi o ba si ti da orin kan bayii, leoseokeoseo ni orin naa yoo ja woo gbogbo igboro ilu Ibadan, ti woon yoo si maa koo oo nile-sile, ti woon yoo si maa koo oo nibikibi pe, “Moobooroojeo oomoo Akinyeole, ta ni yoo fi jeo eo, ta ni yoo fi jeo eo, eoni ti ko to Moogaji to loun yoo jeo Olubadan, ta ni yoo fi jeo eo.

Bi woon ba koo iyeon ti ko to woon, woon yoo tun koo orin mi-in fun un.

“Nibo ni yoo gbe e de, nibo ni yoo gbe e de, we;we; to loun yoo ree gbe peopeoyeo, nibo ni yoo gbe e de.≈ Sougboon eyi to maa n mu inu gbogbo awoon oomoo Ibadan dun ni awoon orin ooteo ti Adelabu maa n koo lati fi sooko ooroo si Awoloowoo ati awoon eeyan reo lasiko ti kinni yii n le. Bo ba ti boo si gbangba to sooroo sooroo, to si bu awoon Awoloowoo daadaa, yoo waa ki orin naa mooleo pe, “Eo ma ba oola wa jeo, eo ma ba oola wa jeo, oomoo aijeobeori to n japo saya, eo ma boola wa jeo. Baba yin o fara gbeotu beoeo ni ko fara gboota, eo ma ba oola wa jeo.” O・roo ki sinu orin ti Adelabu n koo yii, awoon awo lo le ye ni, ko le ye awoon oogbeori, eoni ti ki i baa soe oomoooobadan nigba naa, o sooro ki orin naa too ye e. Ohun ti Adelabu n forin soo ni pe awoon baba awoon n’Ibadan ni woon ja ogun lati gba ileo Yoruba sileo, awoon ni woon fi ara gba oota, ti woon fi ara gba eotu loju ogun lati ma jeo ki awoon Fulani ko Yoruba leoru, ati pe ki awoon oomoo aijeobeori kan ti woon ko ba woon de oju ogun ri ma waa ba oola awoon jeo loju awoon. Soe loootoo si ni, oopoo awoon olosoelu ti woon wa ni Ibadan nigba naa, oomoowe ni woon, oomoowe si lawoon baba woon, ko si baba eoni to ba woon loo soju ogun ninu woon, eyi lo si fa a to soe pe bi Adelabu ba ti koo orin naa bayii, gbogbo awoon oomoo Ibadan ni woon yoo fo soke, nitori bii eoni to n soo oriki woon fun woon ni.


Loootoo loootoo ni mo wi fun yin, Adelabu ko girigiri ba awoon Awoloowoo peolu Akintoola.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Monday, November 25 @ 06:43:06 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 3.33
Awon Ibo Ni Oniyi: 3


E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Loooto Ni Mo Wi Fun Yin, Adelabu Ko Girigiri Ba Awon Awolowo Pelu Akintola" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: