Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
[ Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue ]

·Afise Loroo Benjamen Yi O, Leyin To Jade Lewon Lo Tun Loo Ji Telifisan Pasito
·Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
·Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
·E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
·Milionu Merin Pere La Ri Latigba Ta a Ti n Lu Awon Eeyan Ni Jibiti - Hussein
·Friday Paro Pe Won Ja Tanka Epo Gba Lowo Oun, Lo Ba Loo Ta a Sona Jebba
·Tunmise Ji Kaadi ATM Ore e Ni Saki, Owo Nla Lo Fi Wo Jade
·Olusiro-owo Gbe Owo Awon Osise Sa Lo L'Akoko
·Dereba Bisoobu Fipa Ba Eni To Ja Lole Lo Po, Ladajo Ba Ran an Lewon N'Ilori

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Iyen Lawon Yii Naa Se N So Kantan-kantan
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Iyen Lawon Yii Naa Se N So Kantan-kantan

Awon ti won n se oselu PDP nile Yoruba wa naa nibi, awon yii naa ki i ronu, nibi ti aye ba koju si, awon yoo si keyin sibe, ohun tawon eeyan se n foju alainilaari ati ole lasan wo won niyen. Loooto si ni, iwa won jo iwa ole nigba mi-in, o maa n jo iwa ole, alapa-ma-sise, ati eni ti ko moju ti ko mora nitori ohun to fee je. E wo gbogbo bi nnkan se ri yii, e wo gbogbo wahala to ba egbe PDP yii, e wo ariwo tawon araalu paapaa n pa pe Jonathan ko kun oju osunwon, ko mo kinni kan i se, nise lo fi ete sile to n pa lapalapa, ti won si n so pe ijoba re lo fere buru ju nile yii, oto ni ironu to ba awon eeyan tiwa ti won n se PDP nile Yoruba o.

Awon ti won le ba Jonathan soro n loo ba a loru, won ko je ba a losan-an ki aye ma so won lenu, awon ti won ko si le ba a soro jinna si i, onikaluku n fori ara re pamo. Sugbon awon ti won n se PDP nile Yoruba nibi kora won jo, won sepade pajawiri, won waa gbe iwe jade pe inu awon dun, awon si faramo ijoba Jonathan, awon gbe osuba fun un, awon si fowo si i ko maa sejoba naa lo kanrinkese.Won ko duro nibe, won ni Tukur ti won n wo yen, oun gan-an logaa awon, awon ti feran e ju, awon si fe e nipo alaga egbe naa, ko si wahala fun un, bo ba ti boju weyin bayii, awon ni yoo ri nibi gbogbo. Awon oponu! Egbe n fo mo eeyan lori, okunrin naa yo gbogbo awon omo iya won ti won jo n se egbe nipo, o fi Oyinlola se yeye, o fi abuku kan awon Oni atawon to ku, iyen ko kan awon oniyeye ti won lawon PDP yii o, eyi to kan won ni ki Jonathan ati Tukur maa jo niso, nitori ijekuje ti won fee je.

Kontirakito kuku lo po ninu oloselu tele, ise ijoba ti won yoo gba ni won n le kiri. Bi ko ba se bee, o daju pe bi awon eeyan wonyi ba fi oro naa to awon omo egbe won to ku leti, ti won ba awon ti won dibo fun egbe naa soro, won yoo ri i pe ko senikan ti yoo tele won lati maa ki Jonathan laya, tabi lati maa fowo soya pe ijoba re dara, o te awon lorun. Bo ba ya, won yoo ni egbe awon ko wole nile Yoruba, oponu ko si nile Yoruba, ologbon lo wa nibe, bi won ba si ti ri awon ole ati onijekuje bayii, won da won mo latookan!
Iro niyen jare Eyi lo fa a ti oro gomina ipinle Niger, Muazu Babangida Aliyu, ko se gbodo jo enikeni loju.

Okunrin naa wa lara awon ti won fo egbe PDP, o wa lara awon gomina meje ti won n kiri tele pe awon ko fe Jonathan, o si wa lara awon gomina to ba Atiku lo. Sugbon gbogbo iyen lo daa, afi nigba to fi oro mi-in ti ko kan araalu bo oselu re, to so pe wahala PDP yii le da gbogbo Naijira ru, o le fo Naijiria si wewe. Nitori kin ni? Se eni ti ko je gbii a maa ku gbii ni. Sebi ibi ti e ba gbe amala de ni e oo jo de, ki eeyan ma ma jo ijo eleya de ita tiwa o. Afi to ba se pe Babangida Aliyu yii mo ohun tawon araalu ko mo, bo ba se pe awon Hausa elegbe re ti mura lati da Naijiria ru bi Jonathan ko ba gbejoba fun won, iyen nikan lo fi le so ohun to n so jade lenu. Sebi ki i se egbe PDP nikan lo wa niluu, bi oko kan ko si lo Oyingbo loni-in, egbeegberun re yoo lo.

Bi egbe PDP ko ba ni anfaani ti yoo se fun awon eeyan mo, sebi awon araalu yoo ba inu egbe oselu mi-in lo. Bi awon asaaju egbe naa funra won ba si lu u fo, ti won yo ponpo ti won fi n lu egbe won, ko si eyi to kan awon araalu nibe, sebi bi egbe won ba tuka tan, kaluku won yoo ba ibomi-in lo. Ona kan ko wo oja, bee ni iwofun ni itelorun, ohun to ba te ni lorun la a se. Sugbon lati maa waa so pe Naijiria yoo daru nitori egbe PDP fo, nitori pe tiwon ba won, nitori pe ojooro ati eru pelu etan ti won ti se fun gbogbo omo Naijiria lati ojo yii wa ja jo won loju, isokuso lasan gbaa ni.

Egbe PDP yoo fo, iyen ki i se iroyin mo nitori egbe ohun ti fo, Olorun nikan lo le da a pada. Sugbon ko si ohun ti yoo kan awon omo Naijiria ninu iyen, ko si si ohun ti yoo fo Naijiria, Olorun yoo kan fun won ni egbe mi-in ati awon oloselu mi-in ti won ki i se ole ati wobia, ti won ki i se awon ti won n re mekunnu je. Bi egbe PDP ba fo ti gbogbo awon oloselu inu re si fonka, ohun to dara fun awon omo Naijiria ni, nitoti eleyii yoo maa je kilokilo fun gbogbo awon asebaje ti won ba ko egbe oselu jo lati mo pe ohun ti i tan ni eegun-odun o, omo alagbaa paapaa yoo fowo ra akara jeko. Aliyu, loo jokoo jee, e bara yin sohun-un jare!

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, January 25 @ 02:18:13 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Iyen Lawon Yii Naa Se N So Kantan-kantan" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: