Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Nitori Wahala To Sele Niluu Agbonle, Akowe Ijoba Ibile Padanu Ipo Re
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
Lati Owo Olu-Theo Omolohun, Oke Ogun

Nitori Wahala To Sele Niluu Agbonle, Akowe Ijoba Ibile Padanu Ipo Re

Akowe ijoba ibile Ila-Oorun Saki, nipinle Oyo, Ogbeni Lawrence Adeojo ni won ti fun niwee gbele-e bayii nitori wahala to be sile niluu Agbonle lenu ojo meloo kan seyin, won lo si araalu lona.

Iwe Iroyin Yoruba gbo ni pe ni bii ose meji seyin, wahala be sile niluu naa laarin awon odo nibi ti won ti n gba boolu lori papa-isere ileewe alakoobere Onitebomi Kin-in-ni. Lasiko naa ni okan ninu awon oluworan hu pila ile ijosin naa lai nidii, eyi lo mu ki okan lara awon omo ijo naa fi oro ohun to adari ijo leti. Lesekese ni alufaa atawon omo ijo lo sibe, sugbon nise lawon odo ohun ti won to ogun ya bo won, won lu won, won si tun ba awon dukia ile Olorun je.Nigba ti eyi n lo lowo, okan lara omo ilu to sunmo ijoba pe Alaga ijoba ibile naa lori foonu lati pana aawo yii, sugbon nomba re ko lo. Leyin naa ni won pe akowe ijoba ibile naa, o si pe awon olopaa ti won loo pana wahala ohun.

Nigba to n ba akoroyin wa soro, Oba alaye ilu naa, Kabiyesi Jolade Adetunji Job koro oju si iroyin abanilorukoje ti akowe ijoba ibile naa fi sita fun awon akoroyin pelu afikun pe awon odo ti le oun kuro laafin baba oun. O ni awon oloselu kan to ti n ba oun du oye ni won ko si awon odo ninu lati da rukerudo sile niluu naa.

Ninu oro tie, Alaga ijoba ibile naa, Ogbeni Niyi Olabiyi kominu si atejade akowe ijoba ibile naa lai gba ase lowo re. O ni atejade naa le da rukerudo sile ninu ilu, ati pe oro naa ti si ijoba lona, eyi lo mu ki ase wa lati oke pe ki won fun un niwe gbele-e lesekese.

Ni bayii, won ti yan akowe tuntun fun ijoba ibile naa, iyen Omooba Oyediran Yunus Idowu, won si ti se ibura fun un ni olu-ileese ijoba ibile ohun ni Ago-Amodu, lose to koja. Won se eyi pelu ikilo pe ko gbodo fi asiri ijoba han enikeni, ko si je olooto ati olufokansin ninu ise re.

Omo bibi ilu Sepeteri, nijoba ibile naa ni akowe tuntun ohun, o si ti ni orisiirisii iriri ninu oro oselu ko too di ipo yii mu.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, January 25 @ 02:19:52 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"Nitori Wahala To Sele Niluu Agbonle, Akowe Ijoba Ibile Padanu Ipo Re" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: