Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
[ Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu ]

·Iwosi Yii Si Ti N Po Ju Fun Yoruba, Ibi Ti Won Ba Wa De Ree O
·Bo Se Daa Niyen... Sugbon Kan Naa Lo Wa Nibe
·Bi Iro Ba Lo Logun Odun...
·Sebi Eyin Naa Gbo Ti Dino Melaye Ni Kogi
·Won Ni Alaga PDP Ku Sori Asewo N'Ipokia
·Awon Asofin Ni Kijoba Apapo Se Afara Elese Si Osodi-Apapa
·E Gbo! Kin Ni Fayose Wa Lo Si China?
·E Ko Sekeseke Si Won Lowo Jare
·Bee Ni Buhari Ko Wi Nnkan Kan

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


‘Ise Jibiti Yii Ko Wu Mi Mo, Ori Mi Gan-an Ko Ro Mo On Rara’
 
 
Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

‘Ise Jibiti Yii Ko Wu Mi Mo, Ori Mi Gan-an Ko Ro Mo On Rara’

Aanu eeyan yoo se okunrin yii pelu oro to ti enu e jade yii nitori oluware yoo ro pe o ti kabaamo iwa aburu owo e ni, sugbon awon to mo Adekunle Adesina daadaa ko je gba a gbo pelu oro tutu to n so naa rara, won ti mo pe jagunlabi ti giran-an ninu iwa ka lo ni lowo gba, jibiti lilu ni elekeru fi n sararindin.

Adesina to n soro taanu taanu yii, wahala re naa lo ran iyawo e lo sorun apapandodo. Esun jibiti lawon olopaa tori e so o si ahamo nigba naa, ori ifooro ati aajo tobinrin ohun n se lati yo oko e kuro nigbekun lo ku le. Sugbon dipo ki okunrin odaran yii ri iku iyawo e gege bii ona lati ronupiwada ninu iwa odaran, nise lo kuku so jibiti lilu di ise gan-an loju paali.Nigba ti okunrin eni odun mokanlelaaadota yii koko bere, oun nikan lo mona to n gba fi opolo e gba awon eeyan loju. Sugbon itesiwaju ti ba okunrin naa nidii ise ti ko bofinmu ohun, oun atawon emewa e si ti ni ofiisi kan ti won ti n sise buruku ohun.

Gege bi okan ninu awon ona t’Iwe Iroyin Yoruba gbo pe Adesina atawon egbe e maa n gba sise aburu won, won yoo so fun eni ti won ba fee lu ni jibiti pe awon ni opolopo owo dola ati owo poun ile okeere kan to n bo lati oke okun sugbon awon nilo owo naira ile wa die lati le gbowo naa jade lowo awon asobode eti omi. Bee ni oju awon eeyan to ba ni ojukokoro daadaa naa yoo bere si i sana waiwai loooto, awon naa yoo ba yaa maa kowo sile nireti pe awon yoo gba ilopo owo naa pada nigba ti awon ba ri owo ile okeere ohun gba loooto.

Leyin opolopo odun ti Adesina ti n pa awon ara ilu Ibadan lekun jaye, owo awon Operation Burst, iyen iko apapo soja ati olopaa tijoba ipinle Oyo gbe kale fun aabo ilu te oun atawon emewa e leyin ti won lu obinrin kan ni jibiti owo nla.

Nigba to n salaye bo se bere ise jibiti lilu naa fawon oniroyin nileese Operation Burst to wa ni Agodi, Gate, n’Ibadan, Adesina to pera e lomo bibi ilu Oyo so pe, “A maa n puro fun won pe owo dola nla kan de fun wa lati ilu oyinbo, o si wa leti omi, a waa nilo owo lati le gbe owo yen wole. To ba je eni to ni ojukokoro owo ni, aa sare maa wa owo kiri, aa ni oun naa nifee si owo yen. Ko si si nnkan kan to n je pe dola kan n bo lati oke okun kan.

“Ti won ba mu enikan waa ba wa, nibi ti eni yen ba ti jokoo ni a o ti maa soro nipa okoowo mi-in, a le so pe haa, epo robi ti won n ba wa gbe bo lote yii ma po gan-an o, owo lo ku ti a ni lati yara wa sile bayii o. Eni to je ara wa to mu eeyan wa yen lo maa waa so fun eni to mu wa yen pe owo ti awon eeyan mi yii n so nipa e naa si daa o, ti eyin naa ba le se e, o maa pe e yin gan-an ni o.’’ “Ba a se ba obinrin ta a lu ni jibiti gbeyin soro naa niyen, eni to maa n ba wa mu awon eeyan wa lo fi moto gbe eni yen lofee, o waa so fun un pe onisowo epo idana loun, ati pe to ba nifee si i lati maa sowo epo, oun le maa ja kerosiini fun un. Bi obinrin yen naa se fife han si owo yen niyen, o loun naa maa se e.

“Egberun metadinlogota naira la gba lowo eni yii. O koko fi egberun lona ogun naira sile, nigba to ya lo tun mu egberun metadinlogoji naira wa.”

Nje bawo lowo palaba won se segi, odaran yii so pe, “Obinrin yen naa lo loo so fawon Operation Burst, won mu gbogbo wa sugbon eni to mu obinrin yen wa sa lo ni tie.’’ Adesina funra e fidi e mule pe jibiti lilu yii ti so oun dero ewon nigba kan ri, ati pe ifooro tiyawo oun kan lori oro oun lobinrin naa ku si.

Gege bo se so, “Onisowo ni mi, mo maa n fi aga renti. Aburo ore mi kan lo mu baba kan waa ba mi to ni oun fe ki n mu baba yen mo ibi ti mo ti ra aga ti mo fi n renti. Baba yen saa fun mi ni egberun lona irinwo naira, mo si loo kowo naa fun okunrin kan to n je Jide to je osise ileese kan ti won ti n se ike l’Ekoo. Eni yen naa lo ta temi naa fun mi. Igba ti baba yii n yo mi lenu pe ki n ba oun gba oja oun wa, mo waa loo ba eni yen l’Ekoo sugbon won ni ko sise nileese yen mo. Bi baba yen se waa fi olopaa mu mi lati tesan Sango, n’Ibadan, niyen.

“Awon olopaa ni se mo setan lati da owo yen pada, mo ni ma a maa mu egberun lona aadota naira wa losoosu. Mo mu un lo ni osu kin-in-ni, mo mu egberun lona ogbon naira lo leekeji, nigba to di osu keta ni mi o ri owo kankan mu lo nitori mo n wa owo ileewe omo mi nigba yen. Mi o saa ri owo yen san deede, egberun lona aadojo naira (N150,000) ni mo ri da pada ninu owo naa. Iyen ni won se gbe mi lo si kootu.

Adajo waa ni ki won fi mi sewon.

“Ori wahala owo ti ile-ejo ni ki n san tiyawo mi n wa kiri yen lo ku le. Adajo agba ipinle Oyo lo ni ki won da mi sile kuro lewon nigba yen, ninu osu keta, odun 2012 ni.’’ Nigba to n kabaamo ibi ti iwa ojukokoro ati aife-kan-an-se gbe e de, okunrin afurasi odaran yii so pe, “Ise jibiti yii ko wu mi, adanwo ni o. Mi o fi owo yen gbe nnkan kan se laye, ori mi gan-an ko ro mo ise ohun rara.’’ Okunrin eni odun mokanlelaaadota yii so fun akoroyin wa pe Eko niyawo kan soso ti oun ni n gbe, o lobinrin naa ti bimo meta fun oun sugbon ko mo iru ise toun n se.

Afurasi keji ninu esun odaran yii, Opeola Hassan so ninu oro tie pe jibiti ti enikan ti lu oun ri lo mu ki oun naa pinnu lati maa lu awon eeyan ni jibiti.

Okunrin omo bibi ilu Ibadan to pera e leni odun merindinlogota yii salaye pe, “Igba ti mo jade ni Technical College, l’Oyoo, mo ri ise sileese aladaani kan, ibe ni mo wa titi di odun 2010. Ore mi kan to n je Fatai to waa ba mi lojo kan ni mo so fun pe mo fee lo siluu oyinbo, o waa ni ki n fi okan bale pe aburo oun kan wa to maa n ba awon eeyan seto irinajo naa lai mo pe o fee gba mi ni.

“O ni ki n mu egberun lona egbeta naira wa, leyin ti mo wa owo fun un tan lo so pe won ko fun mi ni fisa.

Leyin igba naa lo pe mi lo sodo e l’Ekoo to salaye iru ise to n se fun mi. O ko mi bi emi naa se le maa fi ayederu owo dola lu awon eeyan ni jibiti, o si ko die ninu awon owo yen fun mi.

“Bi emi naa se pada s’Ibadan ni mo wa ofiisi kan si adugbo Ojoo, ti emi naa si bere si i sise yen. Fatai naa lo ba mi wa awon ti won n ba mi dogbon fa awon eeyan wa. Adesina lo maa n jokoo si ofiisi gege bii oga ofiisi, oun lawon onibaara maa n loo ba. Ba a se maa wole si won lara niyen.

“Ti ki i baa se pe won gba emi naa tele, mi o ba ti se e. Fatai ko lo ko mi ni jibiti lilu, o kan fi awon ilana kan ti won n lo han mi ni. Eni ta a lo gbaju-e fun yen, owo ta a gba lowo e ko ju egberun lona aadota naira lo.

Egberun meeedogbon naira ni won pin kan mi ninu owo ohun.’’ Sugbon eni keta awon afurasi yii, Sikiru Adedeji Jagunmade, so pe oun ki i se ara awon afurasi odaran naa ni toun. O ni wonle wonle loun, ori ile kan ti oun si ti fee sise lojo naa loun n lo ti oun fi tibe di ero ahamo awon agbofinro.

Gege bo se so, “Emi ko ba won lu eeyan ni jibiti o. Okunrin kan lo pade mi loju ona to so fun mi nipa owo ororo, iyen ni mo se tele e lo si ofiisi yen, ibe naa la si wa ti obinrin kan fi n pariwo, ti awon Operation Burst fi de ti won fi waa mu wa.’’ Sa, alakooso agba fun iko alaabo Operation Burst nipinle Oyo, Ogagun Laz Ilo, ti fidi e mule pe awon afurasi odaran naa ti wa ni akata awon olopaa nibi ti won ti n sewadii oran won siwaju.

Igbakeji okunrin soja naa, CSP Elijah Bawa, to soju ogagun naa so fawon oniroyin pe awijare afurasi keta (Jagunmade) ko moyan lori to, ati pe iwadii awon olopaa ni yoo tu asiri ohun gbogbo ti awon onijibiti ti gbe se fun gbogbo aye ri

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, January 25 @ 02:35:14 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise:
Orin Ewi ni Yoruba - Yoruba Poems: Awon Owe Yoruba Proverbs Alo Oro


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise

"‘Ise Jibiti Yii Ko Wu Mi Mo, Ori Mi Gan-an Ko Ro Mo On Rara’" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: