Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Pius Atawon Ore E Pa Abdullahi, Won Tun Ge Eya Ara E Lo Ni Kwara
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
Lati Owo Idris Alooma, Ilorin

Pius Atawon Ore E Pa Abdullahi, Won Tun Ge Eya Ara E Lo Ni Kwara

Ko seeyan to ri bawon a-feeyan-sowo se pa okunrin kan, Ogbeni Abdullahi, ni Kwara laipe yii ti ko ni i bu sekun nitori se ni won ge ori ati kinni abe e, bee ni won tun fa irun to wa labe ati abiya e lo. Sugbon owo olopaa ti te awon onise ibi ohun, won si ti n kawo ponyin rojo niwaju Adajo bayii.

Gege bi ohun ti a gbo, sadeede lawon a-feeyan-setutu-owo ohun, Ogbeni Pius Adamu ati Sabi Saberin lo sodo Abdullahi niluu Gwanara, to wa nijoba ibile Kaiama, nipinle Kwara, won ka a moju oorun ninu ile to sun si, won si sa a ladaa pa, leyin naa ni won ge ori e lati fi setutu owo.A gbo pe ni kete tawon obayeje ohun huwa ibaje naa tan ni won sa lo. Bawon eeyan to wa lagbegbe yii se ri oku Abdullahi ni won lo si tesan olopaa to wa niluu Gwanara, kia lawon olopaa ibe si ti gba won mu. Leyin igba naa ni won jewo pe loooto lawon seku ojiji pa omokunrin ohun.

Iwadii awon olopaa fidi e mule pe nise lawon eeyan naa gbimo-po pelu awon meta kan, iyen Yusuf, Sanni ati Kabiru, ti won ti sa lo. A gbo pe leyin ti won ti ge awon eya ara Abdullahi tan ni won so oku e segbee igbo kan ti won ti n wa kusa lagbegbe naa.

Olopaa to n soju ijoba, Sajenti Sanni Abdullahi, so pe awon si n ba iwadii lo lori esun yii, fun idi eyi, ki ile-ejo so won sinu ogba ewon Oke Kura di ojo igbejo mi-in.

Adajo M.B Magaji faramo imoran olopaa to n soju ijoba, o pase pe ki won ju awon odaran naa sogba ewon Oke Kura, n'Ilorin, di Ojobo, Tosde, to n bo.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, January 25 @ 02:51:45 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"Pius Atawon Ore E Pa Abdullahi, Won Tun Ge Eya Ara E Lo Ni Kwara" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: