Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
E Gba Ni E Laja, Baale Ile Sa Iyawo Re Ladaa N’Ile-Ife
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
Lati Owo Florence Babasola, Osogbo

E Gba Ni E Laja, Baale Ile Sa Iyawo Re Ladaa N’Ile-Ife

Inu bibi ti ko mo pe olowo oun ko lese nile lo sun omokunrin eni odun mejidinlogbon kan, Chijioke Onyedim, dele-ejo Majisreeti ilu Ileefe laipe yii.

Agbo pe nise ni okunrin naa n fi ada le iyawo re, Felicia, kaakiri lojo ketadinlogbon, osu kejo, odun yii. Koda, gbogbo awon ti won n da a lekun ni won fara kaasa ibinu re lojo yii.I go kill you today ni won lokunrin yii n pariwo nigba to n le iyawo re nibugbe awon osise Yunifasiti Obafemi Awolowo, iyen (Senior Staff Quarters of OAU Ile-Ife). Yato si tiyawo re, agbejoro fun ileese olopaa, Sunday Osantunyi, salaye fun ile-ejo pe okunrin yii fi ada owo re sa okunrin olulaja kan, Salifu Adewole, ni apa osi. Bakan naa lo tun fo aga onike merin to je ti Ogbeni Adebayo ti owo re je egberun lona mefa naira lojo yii.

Osantunyi ni gbogbo awon esun ti won ka si Chijioke lese yii ni won ni ijiya labe ofin iwa odaran tipinle Osun.

Okunrin olujejo yii ni oun ko jebi awon esun ti won fi kan oun.

Agbejoro re, Arabinrin Modupe Olufemi ro ile-ejo lati fun oun lanfaani ki oun gba beeli re.

Ninu idajo re, Adajo Arabinrin Risikat Olayemi fun olujejo ni beeli pelu egberun lona mewaa naira ati oniduuro kan niye owo kan naa.

Olayemi ni oniduuro naa gbodo ni risiiti iwe owo-ori olodun meta pelu foto pelebe meji, leyin naa lo sun igbejo siwaju

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, January 25 @ 03:05:50 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"E Gba Ni E Laja, Baale Ile Sa Iyawo Re Ladaa N’Ile-Ife" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: