Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
O Tan! Won Lawon To Ja Oba Sihooho Ni Ado Odo Ti N Ku Nikookan
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
Lati Owo Johnson Akinpelu, Abeokuta

O Tan! Won Lawon To Ja Oba Sihooho Ni Ado Odo Ti N Ku Nikookan

Kayeefi loro to n sele niluu Ado-Odo n je fawon eeyan agbegbe yii nitori bi won se ni awon ti won lowo si bi won se ja Oba ilu naa, Oba Adeniran Akanni Abdul Lateef, sihooho ti won si lu u bii eni maa pa a ti n ku nikookan bayii.

Gege bi Iwe Iroyin Yoruba se gbo, o kere tan, awon meta ni won so pe won ti ku bayii, ti won ko si le so pato iru iku to pa won, eyi ti won lo je keru maa ba awon yooku, ti okan won ko si bale mo pe awon lowo nipa bi won se fiya je ori ade nita gbangba.Bo tile je pe Oba Adeniran ti won fiya je naa ti so lakooko tijoba gbe iwadii kan dide lori wahala naa pe oun dariji gbogbo awon to huwa naa, sugbon awon eeyan ni awon alale to te ilu naa do si n binu. Ohun ti won ni awon agba ilu ohun so ni pe nnkan aburu lawon odo naa se, ati pe ti iru nnkan to sele si won yii ko ba sele, a je pe awon oba ki i se eni owo. Won ni won ti gbagbe pe eni to ba fowo kan oba, o ti fowo kan oosa, o si ye ki won rija oosa.

Bakan naa la tun gbo pe se lawon araalu naa n binu si Gomina Ibikunle Amosun lori bi won ko se ti i so nnkan kan lori abajade igbimo ti won gbe kale lati sewadii lori wahala to sele ohun, eyi ti ko je ki Oba naa ti i pada sori aleefa e lati bii osu meloo kan seyin ti wahala ohun ti waye.

Titi di akoko yii ni won nijoba ko ti i so pe eeyan bayii ni owo ti te, won ni afi bii eni pe won fee maa gbe leyin enikan lawon ka oro naa si.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, January 25 @ 03:09:09 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"O Tan! Won Lawon To Ja Oba Sihooho Ni Ado Odo Ti N Ku Nikookan" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: