Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Adajo Ni Ki Won Fi Isa To Sa Usman Ladaa Pa, To Tun Dana Sun Ile E N'Ilorin
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
Lati Owo Idris Alooma, Ilorin

Adajo Ni Ki Won Fi Isa To Sa Usman Ladaa Pa, To Tun Dana Sun Ile E N'Ilorin, Pamo Sinu Tubu

Beeyan ba ri boju okunrin apaayan kan, Ogbeni Isa, se le koko nigba ti won gbe e wa si kootu laipe yii, yoo mo pe omo esu ponbele ni, abi nigba to sadeede sa Ogbeni Usman ladaa pa, to dana sunle e, bee lo tun seyawo atawon omo e lese, eyi lo mu kawon eeyan so pe o ye ki won ye opolo e wo ko ma se pe o ti daru.

Gege bi a se gbo, Ogbeni Isa to n gbe labule kan nitosi ilu Oro-Ago, to wa nijoba ibile Irepodun, ni Kwara, lo sadeede fada yo si Usman, to si sa a lorun ati ni gbogbo ara, leyin to ri i pe okunrin naa ti ku tan lo dana sunle e, to si se awon omo atiyawo e lese.A gbo pe olori awon Fulani agbegbe yii toruko re n je Adamu Bahago toro naa soju e lo loo fi to awon olopaa ilu Omu-Aran leti, to si salaye gbogbo ohun to sele fun won. Leyin e lawon agbofinro ohun bere iwadii won, ko si pe towo fi te Isa, bo tile je pe awon egbe e ti won jo gbimo-po sise ibi ohun ti sa lo. Sugbon akoole awon olopaa fidi e mule pe loooto ni Isa huwa ibi yii.

Olopaa to n soju ijoba, Arabinrin Mojisola Olamokun so pe loooto nisele naa waye. O waa ro adajo kootu Majisreeti n'Ilorin lati ma se faaye beeli e sile, nitori pe iwadii si n te siwaju lori esun ohun, ati pe o see se ki okunrin afurasi-odaran naa sa lo, eyi to si le sakoba fun igbejo ododo lori esun yii.Adajo M Q Salahu pase pe ki won ju Isa satimole ogba ewon Oke Kura di Ojobo, Tosde, to n bo tigbeejo mi-in yoo waye lori esun naa.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, January 25 @ 03:40:00 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"Adajo Ni Ki Won Fi Isa To Sa Usman Ladaa Pa, To Tun Dana Sun Ile E N'Ilorin" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: