Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
[ Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo ]

·E Waa Wo Simia To Pa Oree Re L'Osogbo o
·Nitori Foonu, Baale Ile Meji Jabo Sinu Konga, Loju Ese Ni Won Ku
·Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
·Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
·O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
·Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
·Grace Atale Re Pa Oko e N'Iyana-Ipaja
·Oro o, Iku Gbigbona Leleyi o! Nibi Ti Johnson Ti n Taja Loju Titi L'Akure N
·O Ma Se O! Dauda To n Tun Redio Se Gan Mona L'Osogbo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Iyaloja Ikorodu, Alaaja Allison So Pe: Emi O Le So Telomi-in O, Sugbon Iyaloja T
 
 
Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
Lati Owo Olowoake Latifa

Iyaloja Ikorodu, Alaaja Allison So Pe: Emi O Le So Telomi-in O, Sugbon Iyaloja Temi Ki I Sawo

Ti a ba n daruko awon asaaju oloja nipinle Eko, o daju pe won ko ni i rin jinna rara ti won yoo fi daruko Alaaja Taofikat Abeni Abiodun Allison, obinrin yii ni olori gbogbo oloja ilu Ikorodu ati agbegbe re pata.

Kinni kan to je kayeefi ninu oro e ni pe ojo keta ti won bi i saye niya e atawon ti won sun mo on ti n pe e ni Iyalode, oruko yii gan-an ni pupo ninu awon ore mama e n pe e ko too di pe won jade laye. Yoruba bo, won lori ti yoo ba joba inu agogo ide lo ti n waye, nitori e ni ko se je iyalenu fawon eeyan nigba t’Oba ilu Ikorodu pe obinrin yii pe ko waa joye iyaloja oja Ayangbunren.Sulaiman Oke Osekalu ti inagije re n je Baba Olopaa, toun naa je omo ilu Ibese ni baba mi.

Mo lo sileewe alakoobere Methodist to wa n’Ita-Elewa lodun 1947. Leyin ti mo setan nibe ni mo lo sileewe girama kan toruko re n je United Modern School, ko too waa di pe mo gba ileewe olukoni (Teacher Training School) lo.

Igba ewe mi daa pupo nitori pe olorun omo ni mi lodo mama mi; emi nikan lomo tiyaa mi n wo loju, mi o ni niwaju, bee ni mi o ni leyin lodo won ju odo baba mi lo. Nitori e ni won se n ke mi, ti won n ge mi, sugbon won o waa tori eyi fayo ba aye mi je nitori won gbagbo pe omo kike ko lo se koko bi ko se pe keeyan ko omo lekoo ti yoo fi wulo funra re ati fawon eeyan ti won ba sunmo on lo se pataki julo.

Iyawo mefa ni baba mi fe, ipo keta ni iya mi wa ninu awon iyawo mefeefa ohun. Baba si

bimo pupo, a fee to mokanla, emi ni won si bi sikefa.

Owotawon obimifimu miatibimose bere ise Ise aso tita ni iya mi yan laayo. Won maa n loo ko adire lati Abeokuta, nipinle Ogun wa si Jankara, l’Ekoo, nibi waa ta ni. Sugbon nigba ti mo bere si i sabiyamo ni won kuro ni Jankara waa gba soobu siluu Ikorodu lati le maa ba mi mojuto awon omo. Sugbon ise olopaa ni baba mi n se ni tiwon.

Bo tile je pe iya mi wa ninu awon iyawo ti baba feran, sibe, won o fayo fo o, bee ni won laforiti pelu gbogbo ohun toju won ri lori oro omo bibi. Ni ti keeyan ke omo, baba mi nawo ife si mi gidi nitori to je pe emi nikan lomo to wa lowo iya mi, nitori pe abiku da mama mi laamu gan-an. Sugbon mama mi o fi bee nifee si eyi, won si maa n so fun baba mi pe, “Ma ba mi ba a je, nitori olomo kan soso bii eni ti ko ti i bimo rara ni, je ki n ko nnkan mi daadaa,

aimoye omo lo wa lowo e.” Koda, yato si emi, o tun lawon omo molebi iya mi meji kan ti won n gbe lodo wa nigba naa, bi iya mi ba gbese ile fun wa, won maa so fawon omo ohun pe bi mi o ba ti sise temi, awon naa o gbodo sise todo tiwon, nitori ibi o ju ibi lo, bi a ti beru bee naa la bi omo, okan o si ju okan lo lodo Olorun. Won maa n te e mo mi leti nigba aye won pe ninu epe tabi adura, ma a fokan ranse sawon leyinwa ola. Sugbon ni bayii, adura ni mo fi n ranse si won pe k’Olorun Oba ba mi forun ke won, nitori eyin ti won fi sile daa gidigidi.

Lodun 1960 ni mo bere ise oluko, nitori mo lo sile-eko awon olukoni niwonba die. Mo se ise yii fun odidi odun mejidinlogbon ko too waa di pe mo fi i sile loo gbajumo oja aso tita ti mo koko ti mu mose tisa tele.

Poun mefa ti a n gba lowo-osu wa lara nnkan to je ki n fise naa sile. Ti mo ba si fee loo pade awon onibaara mi ti won n na Aba ni Gbobi mo Fadeyi, ma a ti ji kuro nile ni nnkan bii aago merin idaji ki n le baa tete yanju oja ati gbese owo ti mo je won tele ko too di pe ma a waa pada sileewe ti mo ti n ko omo. Ki n si too debe lawon eni yii a ti koja mi kale, ki n kan sanwo oja ti mo ti gba tele, ki n si ko oja mi-in ni. Nigba mi-in si ree, o le je aso oju windo to ba daa ni mo maa ko waa ta. Bayii ni mo se titi ti mo fi di okan lara awon ontaja oja Ayangbunren ti mo pada waa je iyaloja ibe.

Awon ileewe ti mo ti sise ni Jamatul School to wa n’Ikorodu, Salvation Army School, Bethel Primary School to wa n’Ikorodu, Ota-Ona pelu Methodist Primary School, nibi ti mo ti sise olukoni gbeyin ko too di pe mo duro ise.

Igba timowole oko Odun 1960 ti mo wose tisa naa ni mo wole oko, oruko baale mi ni Alaaji Fatai Allison, eni to ti doloogbe bayii. Omo mefa l’Olorun fi ke mi obinrin meji, okunrin merin. Oruko akobi mi ni Olalekan Allison, Oba ilu Ibese to wa lori ipo bayii. Nitori eni yii lopo awon eeyan to sunmo mi se n pe mi ni Yeye Oba ilu Ibese.

Odun 1960 ti mo wose tisa naa ni mo wole oko, oruko baale mi ni Alaaji Fatai Allison, eni to ti doloogbe bayii. Omo mefa l’Olorun fi ke mi obinrin meji, okunrin merin. Oruko akobi mi ni Olalekan Allison, Oba ilu Ibese to wa lori ipo bayii. Nitori eni yii lopo awon eeyan to sunmo mi se n pe mi ni Yeye Oba ilu Ibese.
Koda ninu awon obinrin mejeeji ti mo bi, okan wa to n sise ka ra, ka ta, bee lo ni ifokanbale nidii e.

Bimose bere oja tita nipereu Odun 1963 ni mo bere oja tita ni pereu. Aso ti mo n ta legbee oja kan l’Ota-Ona ni gbogbo ojo Satide ati Sannde ti mi o ba ti lo sileewe nigba naa lo so mi deni to n segbe pelu awon ti won n ta ankara. Emi lawon alaso ibe si fi se akowe egbe ohun fun odidi ogun odun ko too di pe won tun fi mi se olusiro owo (Auditor) nitori ti won ri akitiyan mi ninu egbe naa.

Awon ton sowoninu obakan mi Mo lawon obakan mi to n taja daadaa, awon mi-in tie n na ilu oyinbo ninu won. A reni to n ta bia, a si tun reni to n ta aso ninu won, ti won de rise daadaa nidii owo ti won n se.

Bimose diIyaloja oja Ayangbunren atiIyaloja Jenera n’Ikorodu Nigba to di odun 1982 temi naa deni to n ni iso sinu oja Ayangbunren, nigba ti mo maa fi lo odun meloo kan ni awuyewuye kan waye laarin awon alaamojuto oja igba naa lori eni ti won fee yan sipo iyaloja ibe.

Gbogbo asiko yii, ki n taja, ki n si gba ile mi lo ni temi, bee ni mo tun ni ero ti mo fi n yo bulooku nibe. Mo saa n fokan kun okan ki gbogbo e le jora, ki n si le rowo fi to awon omo ki won baa le je eeyan gidi lawujo.

Nigba to di akoko ti won fee je iyaloja mi-in loja yii lawon komiiti ba ni emi lawon fe ki n dipo ohun mu, sugbon mo ko jale pe mi o fe. Omokunrin kan wa ti won n pe ni Baba Iyabo topo mo s’Obe, eni yii saa lo

taku pe oun ko ni i gba ki won fi mi je iyaloja.

Ai waa tete gba sawon eni yii lenu lo je ki won gba aafin Oba ilu Ikorodu, Oyefusi Oguntade Keji, to wa nibe bayii lo pe ki won pa a lase fun mi lati je oye naa, nitori emi lawon nifee si. Nigba to si se pe irorun araalu naa l’Oba n wa, lawon naa ba ranse si mi pe ki n foju kan awon laafin, sugbon ori eleeketa ti mo ri

onise won ni mo too loo je won. Nigba ti mo debe, Oba atawon oloye won fi aidunnu won han si mi lori bi mi o se koko je won ati bi mo se ko jale pe mi o le di ipo ohun mu. Won ni se emi o mo pe ile oye ni won ti bi mi ni? Ase t’Oba pa lojo naa lo je ki n pinnu lati je oye oja yii.

Odun 2000 ni mo bo sipo yii, sugbon nigba to di odun 2004 ti won wuye naa fun mi ni baba wa, Oyefusi Oguntade Keji atawon oloye so pe emi ni Iyaloja Jenera gbogbo oja difisan mefeefa to wa niluu Ikorodu.

Awon oja naa ni Ikorodu West, Ikorodu North, Agbowa-Mota, Ijede, Bayeku ati Ayangbunren yii.

Awon ipenija timoni Ni gbogbo igba ti mo n taja laarin oja, ko si nnkan to n je aawo laarin emi atawon oloja egbe mi to ku, nitori mo je Awonipenijatimoni Ni gbogbo igba ti mo n taja laarin oja, ko si nnkan to n je aawo laarin emi atawon oloja egbe mi to ku, nitori mo je enikan to nitiju, bee ni mo mowon ara mi pupo, ati pe nnkan to le mu ija waye laarin emi ateeyan, mo maa n gbiyanju lati sa fun un. Sugbon ipenija ti mo ri naa ni tawon ti won ko jale pe awon o fe mi lori ipo ti mo wa yii, awon eni ohun gbogun gidi ti mi, sugbon nigba to ya ti won ri i pe eni tawon n koju ija si ko tie se bii eni to ri awon, ati pe won ri i pe ida mesan-an ninu ida mewaa awon omo oja ni won wa leyin mi ni won se jawo ninu a n fojoojumo wa isubu eni. Nisinyii, ko siyato kankan laarin wa mo.

Ajosepoemiatawonolojapelu aseyoritimotise Mo maa n dupe lowo Olorun ni lori awon ohun to ti koju mi ati bi Eledua se mu mi bori. Loooto lo je pe Olorun nikan l’Oba a-fi-ni mona, gbolohun yii lo si n to emi iyaloja atawon ara oja sona ti a fi laseyori to po.

Suuru temi atawon olopaa oja fi n seto oja; ti a o lera mo won, a o gba alubosa, a o gbata, a o si gbowo faini lowo won pe bi won ko ba san iye owo bayii, won o le rojo niwaju wa n mu ilosiwaju nla ba wa. Ayafi eni to ba koja aaye re nikan la maa n ba ja, koda onitohun yoo ri nnkan ti a n ba oun ja le lori. Bee la n samulo ofin oja ti a la kale pe a ko gbodo nira wa lara. Bi a ba si ri oloja meji ti won kejo wa siwaju wa pe won ja, a a ri i pe a pari e fun won, awon naa a si ri i daju pe eyi to je otito oro la ba won so ko too di pe won yoo pada si iso won. Mo waa dari idupe mi lo sodo Kabiyesi, awon oloye ati ijoba ipinle Eko, Babatunde Raji Fasola,

fun akitiyan won lori oja yii, eyi to n mu ko gberu si i lojoojumo.

Bimosensamojutoojayii Onikaluku ni won legbe tiwon; egbe alata wa, ti alaso wa ati bee bee lo. Awon egbe yii ni ko si je ko fi bee nira fun wa lati dari awon ara oja. Gbogbo awon Iyalode egbe ni won maa n bawon omo egbe won sepade, awa naa a tun ba awon olori sepade, koda, a si se iru ipade bayii lanaa, ibe naa la si ti maa n soro lori nnkan ti a ba n fe. Bakan naa la tun maa n lu aago kaakiri aarin oja leekan losu bi a ba fee pe ipade gbogbo ara oja pe eni kankan ko gbodo pate laarin aago meje saago mejo aabo ko too di pe onikaluku yoo tun pada senu oro aje e.

Ni gbogbo Ojoru, Wesde, ni gbogbo difisan mefeefa yii maa n peju sodo mi lati sepade olosoose. Awon iyalode oja kookan atawon oloye won ni won maa n wa.

Loripeawoniyalojamaansawo Emi o ri idahun siyen, nitori tinu emi lemi le so o, ko de si nnkan to jo bee lodo mi.

Ihatiokomikosorooyeyii Eru koko ba won nigba yen pe se ki i se pe awon eni yii yoo pa mi fawon, koda awon omo mi ti won wa loke-okun gan-an ki baba won nilo pe ko gbodo faaye gba mi lati je oye ohun, nitori awon ko ti i setan lati foju sunkun mi. Sugbon akoole eda ti duro ni toro oye yii, ati pe itan ti mo gbo lenu awon obi mi ni pe nigba ti abiku omo da iya mi laamu gidi gan-an, ti won bimo dori eleekarun-un ko too di pe emi duro lo je ki won gba ile-ye-mi-wo lo nigba ti won bi mi, lati mo idi tomo se n ku lowo won. Asiko naa ni babalawo to gbe opele sanle je ko di mimo fun won pe ki won maa pe mi ni Iyalode. Ojo keta ojo ti won bi mi ni won si ti n pe mi bee. Oruko yii naa ni gbogbo awon eeyan tawon ati iya mi jo n segbe n pe mi ki won too ku. Oro Oba to pada yi wo o lo fa a toko mi gan-an fi juwo sile pe ki n joye naa.

Oko mi ki i jowu, bee ni ko si ninu oro re pe nigba wo lo wole, nigba wo lo jade, ka too waa so pe yoo se ilara mi. Ati pe o mo pe mi ki i se onirinkurin. Bakan naa, ki i seni to laapon, tie ni pe koun rowo to awon omo t’Oloun fun wa. Emi nikan lo si fe titi aye re.

AJOSEPO TO WA LAARIN EMI ATAWON ARA OJA ATIJOBA EKO Ajosepo gidi lo wa laarin wa, koda okan ninu won lo gbe aso ankara ti e n wo nibe yen wa pe oun fee fi sinku iya oun, a de ni lati ba a lo. Bii tegbon-taburo la n se, a o si ko won laya je debi ti won yoo maa paya lati soro. A o fi owo sisan ni won lara, sugbon nnkan kan to le mu ki emi ati won ja naa loro owo akole ati olode, nitori a ni lati sanwo won. Oro owo yii lo je ki a tilekun eeyan kan laaaro yii nitori ti ko sanwo olode ati ti akole, o de ti waa be wa, a si ti si i fun un.

Ni tijoba, ajosepo to danmoran lo wa laarin wa. Koda, nigba ti baba Gomina papoda laipe yii, gbogbo wa pata la lo sibe lati fi ijokoo ye e si. Ni tawa o, gbogbo ofin to n gbe kale lo ba wa lara mu, ayafi eni ti ko ba daa funra re, ti ko si le kontro ara e tele lawon ofin ohun yoo ni lara.

Awon nnkan ti a fe latowo ijoba Nnkan ti a fe latowo ijoba ni ti titi oja ti a n ba won ja si pe ki won tunse, sugbon ti won ti waa da okuta si bayii, ti won tun seleri lati waa da omi-in sibe ko too di pe awon yoo da oda si i. A tun waa n be won pe ki won pese geeti fun wa. Loooto lo je pe awon ni won se eyi to wa nibe fun wa, sugbon a n be won pe ki won lo ida mewaa ninu owo ti won n pa fun idagbasoke oja ilu Ikorodu fun wa, a o si ni i ki won ko o le wa lowo.

Nnkan ti a fe latowo ijoba ni ti titi oja ti a n ba won ja si pe ki won tunse, sugbon ti won ti waa da okuta si bayii, ti won tun seleri lati waa da omi-in sibe ko too di pe awon yoo da oda si i. A tun waa n be won pe ki won pese geeti fun wa. Loooto lo je pe awon ni won se eyi to wa nibe fun wa, sugbon a n be won pe ki won lo ida mewaa ninu owo ti won n pa fun idagbasoke oja ilu Ikorodu fun wa, a o si ni i ki won ko o le wa lowo.
Iye odun teeyan n lo nipo Gege bawon ti won ti je saaju mi, ko soro pe won gbodo wa nibe fun iye odun kan, titi teeyan yen yoo fi jade laye ni, afi bi onitohun ba siwahu nikan lo le mu kawon eeyan kowe ehonu nipa e sawon to ye ki won gbo si i. Nidii eyi, eni to wa lori akaba, ko ranti pe oun nikan ko loun ni in, gbogbo eeyan ni.

Idi ti won fi maa n BERU iyaloja Ki i se pe isese wa leyi, sugbon nnkan kan temi ri nibe ni pe aije ijekuje lo mu iberu wa. Bi mo ba lu aago laarin iseju kan pe mo fee ri gbogbo ara oja yii, ma a ri won. Ki i se pe mo se iberu sara lo je ki won maa paya mi, bi ko se pe awon naa mo pe mi o ni won lara, bee la fi won lokan bale. Mo maa n se e laduura pe owo ti mo ba yo seeyan ni k’Olorun yo sawon omo mi, mo si dupe pe Oloun yo o si won, eyi to si n mu inu mi dun bayii. Awon ara oja ta a n soro won yii, eeyan lawon naa, baale ile ati iyaale ile ara won ni won, awa naa o gbodo waa tori pe won n bowo fun wa ki a waa se won nisekuse.

Bi won se lawon oloselu nlo awon iyaloja Ooto loro yii, ko si tun ri bee. Akoko ni pe oloja paapaa ko ni pati, a si ni lati dibo, bee la ri ondibo, onwobo, onkabo ninu wa, sugbon a ni lati wole daadaa ki a too dibo fenikeni ninu awon ondupo. Loooto lo je pe gbogbo awon egbe oselu ni won maa n waa ba wa pe ka sadura fun won, ati pe ibi t’Olorun ba ni eda yoo de ni yoo de. Adura tiwa ni pe eni to maa depo ohun, tohun gbogbo yoo derun fun wa ni k’Olorun ba wa yan sibe.

Oro babaloja Loooto ni babaloja wa, sugbon iyaloja lo n dari eto oja, ati pe lai sobinrin ko sokunrin, lai si sokunrin naa ko sobinrin, nitori Olorun jo fi wa kera wa ni.

Iyanju mi fawon OBINRIN Asa oko kan ko kun koboodu to gbode kan lo ba oro je, eyi ko si dara rara. Nnkan ti won si fi feran mi nile oko ni pe won ko ri mi pelu okunrin mi-in latigba ti mo ti wole oko. Mo waa ro gbogbo awon odobinrin ti won sese fee wole oko atawon adelebo pata pe ki won yera fun irinkurin ati sise iranu kiri adugbo. Aimoye awon okunrin mi-in ti won feyawo meji lo je pe ko wu won, sugbon latari iwa idojuti, aibowo foko eni ati aifi okunrin lokan bale lo maa n sun iru okunrin bee sita lati wa obinrin ti yoo gbo tie. Paapaa julo, iwa awa obinrin sokunrin lo le mule ro. Mo be awon obinrin pe ki won joo, ki won tori t’Olorun, ki won ma se mo to; mo to;, ki won ma si yose sibi meji, eyi lo le je ki adura won gba daadaa. Bi won ba si n fa a, yoo tete tora.

Bee mo fe ki won gba pe beeyan ko ba gbadun oko, yoo gbadun omo to ba bi leyinwa ola.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, January 25 @ 04:04:52 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin:
Buhari Omo Musa Sa Kuro Nibi Ayeye Igbeyawo Saidi Osupa: Lehin Ti Alfa Muri Fun


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin

"Iyaloja Ikorodu, Alaaja Allison So Pe: Emi O Le So Telomi-in O, Sugbon Iyaloja T" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: