Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Imo Ofin-Olohun - Awon Ibeere Ati Idahun
[ Imo Ofin-Olohun - Awon Ibeere Ati Idahun ]

·Gbigba Kadara Gbo - Al-Imaan Bi-l-Qadar (Ayanma Tabi Akosile)
·Umaru Gbe Oogun Wo Kootu, Ladajo Ba Da Igbejo Duro Kia
·Fasasi Ko Iyawo e Sile N'Ibadan, O Ni Ko Ro Amala Fun Baba Oun
·Adajo Ni Ki Won Fi Emmanuel, Ayederu Looya, Sogba Ewon Kirikiri
·Alake To Fee Ko Oko Dero Ewon N'Ilorin
·Yekeen Fee Ko Munira n'Ilorin, O Ni Latigba Tawon Ti Fera Loun Ti n Ru, Tou
·Adajo Ni Kawon Ebi Oko Medinat Da Ogun Oko Re Pada Fun un
·Igbeyawo Ogun Odun Daru L'Osogbo
·Lori Oro Ti Ko To Nnkan, Awon Olopaa Fibon Fa Femi Lorun Ya, Ni Won Ba Sa Lo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Loooto Ni, Ko See Se Ki Yoruba Maa Da Nikan Se Tie Loto, Sugbon...
 
 
Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
Lati Owo Mujidat Okoya, Ibadan

Loooto Ni, Ko See Se Ki Yoruba Maa Da Nikan Se Tie Loto, Sugbon...

Awon kinni kan wa to maa n mu inu mi dun, iyen ni oro ti eyin eeyan mi maa n ko ranse si mi. Loooto awon kookan le soro si mi, sugbon a ko le fe iru e ku rara, agbalagba ti yoo ba ko omode jo ko gbodo so pe oun ko ni i ri egbin. Sugbon ohun ti opo eeyan maa n so ranse nigba mi-in, oro ogbon gbaa ni. Emi ti mo n ba yin soro yii, ki i se pe mo gbon tan tabi mo mo tan, o kan je pe mo ba awon agba rin, mo si riran die nipa oro oselu Naijiria yii, iyen ni mo se maa n so awon ohun ti mo n so, nitori mo gba pe afogbon-ologbon-sogbon ko ni i siwa-hu. Bi kinni kan ba wa ti ko ba ye wa, e je ka beere, nitori bi e ba bi mi bi emi naa ko ba mo on, n oo fi lo awon ti won tun ju mi lo tabi awon ti a jo je egbe ti won ti ni iru iriri bee ri, o si da mi loju pe esi yoowu ti won ba fi fun mi yoo wulo fun gbogbo wa. Ohun to le mu idagbasoke wa niyen, ohun to si le gbe awa Yoruba debi ti a fee lo niyen.

Ibeere kan ti awon eeyan maa n beere lowo mi ju ni pe kin ni asaaju Yoruba ti mo n wa kiri yoo se fun wa gan-an. Awon kan tile so pe nigba ti won ti fi Bola se asiwaju ti gbogbo eeyan si n pe e ni Asiwaju, ki la tun n wa asiwaju mi-in lo si. Lara ohun ti ko ye wa naa niyen.Asiwaju Eko ni won fi Bola je, bee ni awon eeyan mi-in wa ti won je Asiwaju Ofa, Asiwaju Ijebu, Asiwaju Egba ati bee bee lo. Sugbon oro kan ti enikan so lose to koja yii, to si tun beere lori e dun mo mi ninu. O ni nigba ti mo ni ki awon APC ma ba Hausa se, bawo ni Yoruba se fee nipa ninu iselu ijoba apapo, se Yoruba nikan le da wole ibo ki won si di aare Naijiria ti won ko ba fi ti awon eya to ku se ni. Ibeere yii dun mo mi ninu, nitori ohun meji lo ko papo fun mi. Akoko ni pe o fi han wa pe opo eeyan lo mo pe a ko le da kinni kan se ni Naijiria nidii oselu bi a ko ba mu awon eya mi-in mora, ekeji si ni pe bi a oo ba lo siwaju, afi ka ni enikan ti yoo saaju wa.

Akoko ni pe ka so ododo funra wa, ko si bi a oo se lo siwaju tabi ti a oo ri ipo pataki kan di mu ninu ijoba ati ninu oselu Naijiria bi a ko ba ba awon eya to ku se. Okan lara asise ti awa se lojosi niyen. Igba kan wa ti a koko taku pe a ko ni i ba Hausa se, tabi ti a ba fee ba won se, a ko ni i ba awon to loruko ti won si lagbara ni adugbo won se, awon omode ti won ko mo nnkan kan, ti won kan n pariwo lasan, tabi ti won n tako awon alagbara ilu won la oo maa ba se, bi o ba si di asiko ibo, a oo waa ri i pe awon eeyan naa kan n fo koko lasan ni, won ko je nnkan kan. Nigba ti mo dagba yii, mo ri i pe ki i se gbogbo ibi ti Baba wa Awolowo ko wole re naa lo je pe ojooro ni won se si i, awon kan wa to je pe awa naa ko leeyan to ni, nitori ko sibi ti won ki i ti i sojooro lasiko ibo, awa naa n se e daadaa, awon ti won si n pariwo pe awon lomo Awolowo loni-in, ojooro won paapaa ju tawon ti won n bu pe won ji ibo awon lo.

Se awa naa ko sojooro lasiko AG ni, tabi a ko se lasiko UPN, tabi awa ti a se SDP ko se tiwa ni, abi a ko se lasiko AD? Olojooro ni gbogbo oloselu, nitori bi ero egbe ba se po to ni won yoo fi so pe oun lo wole, eleyii lo si maa n ba awon oloselu leru ti won yoo fi maa sojooro lati je ki iye ibo won ju ti awon alatako won lo gboorogbooro. Sugbon kinni kan ni o, ibi ti egbe oselu kan ba ti lero pupo leyin, ibi ti won ba ti gbajumo ju, ibe naa ni won ti le sojooro.

Bi oloselu kan ba sojooro nibi ti won ko ti feran re, asiri won yoo tu, iyen si ni ariwo ti e maa n gbo pe ojooro ni won fi wole, won ji ibo ko ni, ati bee bee lo. Ki i se pe awon ti won n pariwo yii ko sojooro tiwon naa, sugbon nitori pe awon laye n fe laduugbo naa ni. Nitori pe ile Hausa po ju wa lo, ojooro ti won n se nibe po, won yoo si ti duro de awa nibi, won yoo ti gbo iye ibo ti awa ka, leyin naa ni won yoo maa waa ju awon nomba nla nla kale, ibo tiwa ko si ni i to tiwon lae.

Bo ti wa nigba naa niyen o, o si da mi loju pe bo se wa lasiko yii naa niyen. Oogun kan soso to si ran oro yii naa ni pe enikeni to ba nigbagbo lati sejoba apapo, a fi ko ba Hausa se. Bi Hausa naa ba si fee maa sejoba daadaa lo, ti won fee wa nipo titi, afi ki won ba awa Yoruba se. Nibi ti a ti maa waa pe ara wa niyen. Awa ta a n pe ara wa ni oloselu Purogiresiifu, nigba ti ijoba ko ba si lowo wa, a oo maa pariwo pe awon alatako wa n ba Hausa se, omo ale Yoruba ni won, won ko feran Yoruba, awon ni won ta Yoruba fun Hausa, won ti gbabodi, omo Akintola ni won, ati bee bee lo. Sugbon bo ba digba tiwa, awon Hausa ti awa yoo ba rin, awon ti yoo buru ju eyi ti awon ti a n bu tele n ba rin ni. Tabi eyin ko ri igba ti awon eeyan wa n se PDP, e ko mo eebu ti awon ACN n bu won, sugbon ni bayii, ACN funra re lo n wa awon Hausa kaakiri, awon Hausa to buru jai.

Ti a ba waa so kinni kan fun yin, nje ko ni i ya yin lenu. Iyen ni pe ko sohun to buru rara bi a ba n ba awon eeyan wonyi se nigba ti oro ba ti di oro oselu, niwon igba ti a ti mo pe a ko le da kinni kan se funra wa, afi ka ni awon eya to ku. Sugbon ajosepo yoowu ti a ba n se bayii ko ni i mu anfaani kan waa ba wa, afi ti awa funra wa ba ti to ile wa ka too jade lo. Bawo ni a oo se to ile tiwa? Nibi ti asaaju Yoruba ti wulo niyen.

Asaaju yii ati awon eeyan ti won ba jo wa ninu igbimo won ni yoo ti seto ohun ti Yoruba fe, ibi ti a fee de logun odun ati ona ti a oo gba debe, eleyii ni gbogbo omo Yoruba ti won ba n soselu yoo ko si okan won, bi won ba wo inu egbe PDP, ohun ti won yoo maa ja fun niyen, bi won ba si wa ninu egbe APC, tabi egbe miin ti yoo tun de leyin ola, ohun ti won yoo maa ja fun niyen. Ohun ti awon Hausa n se ti won fi n mu nnkan je lori gbogbo eya to ku ni Naijiria niyen. Hausa PDP yoo ba eyi to wa ni APC se, ti ANPP yoo ba eyi to wa ni CPC se, bi oro ba si ti di oro akoso ijoba, kia lohun won yoo sokan.

Sugbon tiwa ko ri bee nibi, bi a ba n bara wa ja ija oselu, afi bii igba ti a gba iyawo ara wa, tabi ti a pa omo ara wa. Awon miiran tie gba pe ki won pa awon lomo, tabi ki won gba awon niyawo ko buru to ki won di awon lowo kawon ma wole ibo, nitori won ti so kinni naa di ounje, ona ofun si ree, ona orun ni. Bi a ba wo awon ohun meji kan ti mo ri lose to koja yii, e oo ti mo pe ko si oloselu kankan nibi kan, bee ni ko si egbe oselu kan to da yato, ona ti kaluku yoo gba dele ijoba ni won n wa, bee ni won ko ni ero gidi kan fun ijoba ohun, pupo ninu awon oloselu lo gba pe awon kan lo sohun-un kawon le ri owo nla ko nibe ni. Iyen ni won se le ta ile won, ti won yoo ta ona won, ti won yoo je gbese nitori pe won fee se alaga ijoba ibile, bawo leeyan yoo se se iyen ti ko ni i ji owo ijoba to ba debe, ti yoo si tun ji owo repete ti yoo fi du ipo naa lojo iwaju. Pupo ninu awon ti won se oselu ile yii, oro oselu ati eto re ko ye won rara, awon kan ri i bii ise okoowo ati ona atije lasan ni.

E wo egbe PDP bo se fo pekepeke, e wo ija buruku ti won n bara won ja, ti awon gomina n sepade ti won n yo ese, ti awon agbaagba egbe n pade ti won n se ara won nigbo, bawo ni iru egbe bee yoo se mu daadaa benikan. Sugbon ke e too maa pariwo pe PDP nikan ni iru iyen ti le sele, e wo ohun to n sele si Segun ati omo re, Kunle, ni Abeokuta. Awon asofin omo PDP ti won ba Gbenga ja ni 2011, ti won ba ijoba re je, ti won sa lo sinu AC, ti won so pe won bura, awon naa ni won ti tun kuro ninu ACN yii, ti won ni awon ko le lo si APC, ti won si tun n loo ba Gbenga nibi ti won gbo pe o n lo. Se oselu niyen! Iyen ki i se oselu, ise oro aje lasan, ka maa kiri ibi ti a oo ti ri ounje ati owo to po ko ni. Tabi ki lo ti yipada lara Gbenga ti won fi tun loo ba a. Bi opolopo oloselu ti ri nu-un, asewo won buru ju ti awon obinrin ti won wa ninu oteeli lo.

Ohun to je pe bi Yoruba ba fee lo siwaju ni Naijiria yii, egbe oselu tabi asaaju oloselu kan ko ni yoo gbe wa debe, afi ka ni asaaju kan ti gbogbo wa fowo si ti a oo si maa gboro si lenu. Ona ti a oo gba yan asaaju yii le soro o, sugbon ohun ti gbogbo wa gbodo koko mo ni pe ibere oriire omo Yoruba ni lati ni asaaju tiwon funra won.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, January 25 @ 04:09:07 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise:
Orin Ewi ni Yoruba - Yoruba Poems: Awon Owe Yoruba Proverbs Alo Oro


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise

"Loooto Ni, Ko See Se Ki Yoruba Maa Da Nikan Se Tie Loto, Sugbon..." | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: