Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
[ Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga ]

·Eyi Ni Bi Enu Se Ko Ba Bobrisky, Okunrin To N Se Bii Obirin: Won Ni Awon Olopa D
·O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
·Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
·Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
·Owo Te Wahab Nibi To n Ti n Se'Kinni' Fomo Odun Mewaa Legbee Ogiri
·Mumini Lu Magun Lara Iyawo Oloye Ilu n'Iyana-Offa
·Imeh Ha Sowo Olopaa L'Ekoo, Aburo Iyawo e Lo Se Kinni un Fun
·Aliyu Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po n'Ilorin, Lo Ba Doyun
·Adebowale Atawon Egbe e Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Se Awon Baba Yii Ko Ni I Loo Sinmi Ni
 
 
Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
Lati Owo Sherifat Okoya, Ibadan

Se Awon Baba Yii Ko Ni I Loo Sinmi Ni

Beeyan ba ri awon baba ti won n loo pari ija inu egbe PDP lori telifisan, yoo ri i pe arugbo po ninu won. Baba ti won n pe ni Bamanga Tukur yen, beeyan ba ri i lori telifisan, yoo ri i ti gbogbo orun ti wole tan, gbogbo oju ti ko wonu, ko le rin kanmokanmo, bii igba ti won n ro; o rin ni. Ninu beba lo ti jade lanaa pe Tukur n se ayeye ojoobi omo odun mejidinlogorin (78), bo tile je pe awon ti won mo on so pe ojo ori re ju bee lo.

Koda bi ojo ori re ko ju bayii naa lo, asiko to ye keeyan jokoo ko maa sinmi ise to ti fi aaro ojo ati osan aye re se ni, sugbon oun ko le duro, bee ni ko le fa kinni ohun le awon omo re lowo, afi ko maa fi arugbo ara se wahala kiri. Beeyan si wo Tony Anenih, ko digba ti won ba so fun enikan ti yoo fi mo pe arugbo pata ni, oun kuku tie ti di omo ogorin odun.

Nibi ti nnkan ba ti daa, ipo oludamoran ni awon eeyan wonyi yoo wa fun ilu, won ko ni i si nipo ki won tun maa sare kiri, ka maa ranju, ka maa ja, ka maa daluru ka ni a n tun ilu se. Ipo to ye ki awon eeyan wonyi wa, ipo ti ija ba de, ki a ko ejo loo ba won ni, ki i se awon lo ye ki won tun wa loju ija ka maa waa ro won mu kaakiri.Awon nnkan kan wa ti ko daa, awon nnkan kan si wa to ti ni loju ju ole jija paapaa lo. Bi won ba so pe ko si ifeyinti ninu oselu, ki i se iru iyen ni won n wi, ohun ti won n so ni pe beeyan ba de ipo kan ninu ojo ori, oluware yoo jokoo jee, awon eeyan yoo si maa waa ba won nile, nibi ti awon naa yoo ti maa ko won, ti won yoo si maa fi ona han won, ti won yoo si fi ara won sipo ti gbogbo aye yoo ti maa gboro si won lenu.
Sugbon o da bii pe awon baba yii gan-an ni ko fee jokoo jee, nitori gbogbo agbara ti won ba ni ni won yoo lo lati debi kan, ti won yoo si maa fa ipo mo awon omode ti won ko ju egbe omo won lo lowo. E e si ba awon eeyan yii soro, e ba won soro ki won sinmi iwa okanjuwa, anikanjopon ati imotara-eni-nikan ti won fi n ba ilu yii je. E so fawon baba yii ki won loo sinmi, abi o digba ti won ba n ku soju agbo oselu ni.

Eleyii ma ga o.Bi won si n ge won lowo, won yoo maa boruka Ohun ti Goodluck Jonathan fee gba nidii awon iwa mi-in ti oun ati awon omoleyin re n hu yii, oun nikan lo ye o. Sugbon bo ba je bo ti n se yii naa lo n se lo, isoro n be fun eesan to fee di eewaa, to si ni oun ko ni i ba ookan se. Abi e ko ri ohun ti awon olopaa da lara lose to koja ni Pota. Nise ni won ma loo dena de Gomina ibe, ti won si ko moto ati igi dina ti yoo gba de ile ijoba to n gbe, ti won si ni ko gbodo koja, ko le lo sibi kan. Oro naa le debii pe o fee dija nla laarin awon olopaa ti won n so Gomina naa atawon olopaa ti won gbegi dina yii, nitori awon tibi ni oga awon gbodo koja lo sile re nibi to fee sun, awon olopaa keji si ni Komisanna lo fi awon sibe awon ko si le ko oro si oga awon lenu. Eleyii lo fi han pe Komisanna gan-an ni oga Gomina nipinle Rivers, ohun to ba se asegbe si ni.

Bee ofin ko so bee, ofin ko faaye gba iru re rara, gomina lo ni ipinle re, oun ni olori gbogbo awon to ba wa nibe, boya araalu ni o, bi agbofinro si ni. Koda bi aare paapaa lo si ipinle kan, gomina ibe ni olori, nitori oun ni yoo gba a lalejo, alejo ko saa ni i mona bii onile laelae. Sugbon nitori pe Jonathan atawon eeyan re niluu Abuja n fun okunrin Komisanna olopaa ipinle Rivers ti won n pe ni Mbu yii lagbara, to si mo pe bi oro ba bureke eyin oun ni won yoo wa, to si mo pe bi oun ba se se ise naa to loun yoo fi gba okun, o n ri Gomina fin, o n kan Gomina labuku, o ni ki won gbegi di oju ona fun un ko ma raaye wole ijoba.

Ohun to n ba aye opolopo oloselu je niyen, asilo agbara. Bi agbara ba wa lowo won, won yoo maa lo o bii eni pe won ko ni i kuro nibe mo, won a si ti gbagbe pe awon n bo waa di korofo. Ati pe aaye buruku ni Jonathan n fi gba iru olopaa yii, bi Komisanna ba se e to ba se e gbe, oga won patapata, IG, naa n bo lojo kan ti yoo se e fun oun Jonathan nitori ohun ti a ba se sile ni abowaba. Bawo ni aare orile-ede kan yoo se maa ta Gomina re lopo nitori ija oselu, bi ija ba waa pari, se awon olopaa ti won ti rira won bii Olorun kekere bayii yoo tun maa waa gboran si Gomina naa lenu. Bi won ti n da ilu ru niyen, nitori ojo kan n bo ti oga olopaa pata yoo ri oun naa fin, arifin naa yoo si le debii pe ko sohun ti yoo le se fun un. E so fun Jonathan ko ma tori oselu ba ilu je, nitori bi ogun ba je lo, ogbon n je bo leyin o.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, January 25 @ 04:46:06 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise:
Orin Ewi ni Yoruba - Yoruba Poems: Awon Owe Yoruba Proverbs Alo Oro


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise

"Se Awon Baba Yii Ko Ni I Loo Sinmi Ni" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: