Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara
[ Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara ]

·Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
·Arungun Loko Mi, Gbogbo Irinse Mi Lo Ti Baje, Mi O Fe e Mo Abigail
·Oko Mi Fi Pata Mi Soogun Owo Philomina
·Emi Atoko Mi Ko Ja, Nitori Omo Lawon Ebi Re Se Fee Le Mi Jade - Rafia
·Latodun Merin Seyin Loko Mi Ko Ti Ba Mi Lasepo, Mi o Se Mo - Folasade
·Odo Ni Wolii Moses Ti Ni Ki David Loo We Iwe Isegun, Lo Ba Fogbon Ji Moto Re Gbe
·Oro Buruku Toun Terin: Awon Omo Poli Ojere Mefa Daku Lakooko Ti Won Fee Sedanwo
·O Sele L'Egba! Seun Bimo Kan Fokunrin Meji L'Abeokuta
·Babalawo Fewon Jura Lori Esun Aini Salanga L'Ondo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Ija PDP N Buru Si I - Baba Iyabo, Atiku, Jonathan - Ajatu-Akata, O Doju E
 
 
Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
Lati Owo Olawale Adejare

Ija PDP N Buru Si I - Baba Iyabo, Atiku, Jonathan - Ajatu-Akata, O Doju E


Kinni kan sele l’Abuja lojo Aiku, Sannde, to koja yii, kinni naa fi bi agbara ijoba ti tobi to, ati bi oro ija naa to n lo ninu egbe PDP ti di egbinrin ote, to je ba a ti n pa okan bayii ni okan n ruwe, to si je kaka ki ewe agbon de ni, nise ni kinni ohun tun n le koko si i. Okunrin kan ti won yan gege bii akapo egbe PDP tuntun, iyen PDP tawon Abubakar Atiku, ti Kawu Baraje n se olori won, Mallam Tanko, lo ha sowo awon omo Aare Goodluck Jonathan niluu Abuja lojo naa, oun ni akapo ti won ko jinnijinni bo, ko si le gbagbe ohun to sele si i. Lojiji ni won ranse si i lati ile ijoba, won si so pe ko maa bo ko waa ri won kia nibe. Ohun to se rorun lati ranse pe akapo egbe PDP tuntun yii ni pe okunrin naa ti gba ise agbase lowo ijoba apapo, o n ba won se titi nitosi Ogbomoso, iyen gan-an ni won tori e pe e ti won ni ko waa salaye nnkan kan fawon. Sugbon nigba to debe, oto ni ohun to ba.

Bo ti debe ni won so fun un pe titi to n se yen, awon fee gba ise naa lowo re ki awon si gbe e fun elomi-in, yoo si da owo to ti gba pada fawon nitori ko ti i se ise naa debi kan. Sugbon to ba fee maa sise naa lo, ohun ti yoo koko se ni lati kowe fipo re sile, iyen ipo akapo to je ninu egbe PDP tuntun. Won ni bo ba fipo naa sile nikan lawon le fi oju aanu wo o, ti awon yoo si je ko maa ba ise re lo. Jinnijinni da bo Mallam Tanko Isiaku, ko si mo bi yoo se fi egbe to sese wa ninu re sile ti yoo waa kede pe oun ko si ninu egbe PDP tuntun mo. O ni ki awon omoose aare yii je ki oun loo so fawon eeyan oun, oun yoo si fun won lesi ki ile too suSugbon awon eeyan naa taku, won ni ko le lo sibi kan, bo ba mo pe oun fee se ko se, bi ko ba si setan lati fi egbe re sile ko maa lo, ko si gbagbe ise ti won gbe fun un. Nigba naa ni ko sibi ti okunrin naa yoo sa gba mo, o si so fawon eeyan naa pe oun ti gbo, o si kowe lati so pe oun ko se egbe PDP tuntun mo.

Nise ni oun ro pe oro naa ti tan sibe, o si fee tete maa lo sile. Afi bi won tun se da a duro ti won ni ko le lo sibi kan, ko gbodo sa lo bee ni ko gbodo fi won sile. Won ni awon ti seto fun un nibi ti yoo ti ba gbogbo awon oniwee iroyin ati akoroyin telifisan gbogbo soro, won ni bo ba ti soro tan, yoo waa maa lo. Bee ni gbogbo awon oniroyin to wa ni Aso Rock jade si okunrin naa lojiji, ko si ri alaye mi-in se ju pe oun ti kowe fipo oun sile, oun ko si se egbe PDP tuntun mo, oun ti pada sinu egbe PDP atijo, nibi ti ohun gbogbo yoo ti maa lo deede foun. Oro naa ko tete ye awon elegbe re to ku, afi nigba to jade to n salaye ohun ti Jonathan atawon omo re foju oun ri, to si so bi won se fi tipatipa da oun pada sinu egbe PDP atijo.

Nnkan ko rogbo ko si jo pe kinni naa yoo yanju ninu PDP, nitori lojoojumo ni kinni naa n le si i, awon omo egbe PDP tuntun fee gba egbe naa lowo awon asaaju egbe PDP atijo, sugbon ko seni to fee gba fenikan.

Eyi to si tile le nibe ni pe olopaa lo ku bayii ti won fi n le ara won kiri, oro naa ko si yo Gomina sile paapaa, nitori lose to koja yii ni won fi awon olopaa deruba Gomina ipinle Rivers, Rotimi Amaechi. Awon olori ile igbimo asofin ti won ti je tele kaakiri Naijiria ni won pade, se won sese da egbe naa sile ni, ilu Pota ni won si ti sepade won. Bi won ti de sibi ipade naa ti ese gbogbo won si ti pe, won le logorun-un meji daadaa, won pinnu laarin ara won pe ajoji ki i wolu ki omo onile ma mo, won ni ba a ba de ile kan olori ile naa laa koko ki. Won ni awon gbodo wa Gomina ipinle ni kinni naa n le si i, awon omo egbe PDP tuntun fee gba egbe naa lowo awon asaaju egbe PDP atijo, sugbon ko seni to fee gba fenikan.

Eyi to si tile le nibe ni pe olopaa lo ku bayii ti won fi n le ara won kiri, oro naa ko si yo Gomina sile paapaa, nitori lose to koja yii ni won fi awon olopaa deruba Gomina ipinle Rivers, Rotimi Amaechi. Awon olori ile igbimo asofin ti won ti je tele kaakiri Naijiria ni won pade, se won sese da egbe naa sile ni, ilu Pota ni won si ti sepade won. Bi won ti de sibi ipade naa ti ese gbogbo won si ti pe, won le logorun-un meji daadaa, won pinnu laarin ara won pe ajoji ki i wolu ki omo onile ma mo, won ni ba a ba de ile kan olori ile naa laa koko ki. Won ni awon gbodo wa Gomina ipinle gba de ile re pa, ti won si ni ko le koja laarin awon, nitori ase lati oke lawon n tele. Gomina yii bo sile, o si salaye, sugbon won so fun un pe ko ri bee, won ni ibi to wa yen naa ni yoo wa, afi bo ba loo gba ona mi-in wole. Ohun tawon olopaa naa so pe awon se ti oju ona naa pa ni pe ona yii naa ni ile egbe PDP tuntun ti won sese gba wa, ase to si wa lowo awon ni pe awon ko gbodo je ki enikeni de ile egbe tuntun naa, ko seni to gbodo koja si apa ona naa rara. Se ki i se ile egbe naa to wa ni Pota yii ni won yoo koko ti, won ti ti ti Abuja, won ti tawon ti won fee se iru re ni Kano, gbogbo ibi ti won ba si ti n fee ni sekiteeria tuntun ni egbe PDP n gbe ti, nise ni ijoba apapo n yegi fun won. N lo ba di ohun ti awon asaaju egbe PDP tuntun yii n sa fawon olopaa, won ko fe ko di ohun ti won yoo maa gbe won ju si atimole.

Oro naa ko duro bee paapaa, awon kan ti gba ile-ejo lo ninu won, iyen awon asofin bii ogorin, won ni kile-ejo pase pe Jonathan tabi Bamanga Tukur ko lase lati yo awon nipo awon. Ohun to je ki won se eyi ni pe Tukur ti hale mo won pe bi won ko ba pada sinu egbe PDP atijo ti won ba so pe awon n se egbe PDP tuntun, awon yoo yo won ni, won yoo si fipo ti won wa nile igbimo asofin sile kia, won yoo maa duro de ojo ibo mi-in. Ohun to je ki won lo sile-ejo niyen o, won ni ki won ba awon deruba Tukur. Tukur naa wa nile-ejo, oun ni ki won kilo fun Baraje ko yee pera re ni olori egbe PDP, won si ni ki won fi olopaa mu oun ati Oyinlola ki won gbe won ju sewon, nitori won n pariwo pe awon ni PDP tuntun.

Bo tile je pe awon agbaagba inu egbe naa bii Olusegun Obasanjo, Ibrahim Babangida, Abdul Salami Abubakar ti sepade pelu Jonathan nidaakonko, won ko ri oro naa yanju, nitori ohun ti okunrin naa n so ni pe oun ko le faramo ibeere ti awon PDP tuntun naa n beere, oun ko si le se ohun ti won ni ki oun se rara. O ni akoko ni pe won ko le pase fun oun pe ki oun ma du ipo aare lodun 2015, bee ni won ko le so pe dandan ni ki oun yo Bamanga Tukur. Nibi ti oro naa ti daru ti ko si lojutuu niyen. Koda, fun bii wakati marun-un ni awon Gomina ti won n saaju egbe PDP tuntun yii ati Jonathan pelu igbakeji re fi sepade ni Aso Rock lojo Aiku, Sannde, ijeta yii, sugbon gbogbo bi won ti se pe ni ipade naa to, won o ri oro yii fi ti sibi kan, Jonathan ni oun ko gba, awon Gomina naa si ni awon naa ko fe, won ni ki onikaluku pada sile, nigba to ba ya oro yoo yanju ara re. Awon Gomina meje ti won ba Jonathan fa oro yii ni Muritala Nyako lati Adamawa; Babangida Aliyu ti Niger; Rotimi Amaechi ti Rivers; AbdulFatah Ahmed ti Kwara; Alaiyu Wamako ti Sokoto; Sule Lamido ti Jigawa ati Rabiu Kwankwaso lati Kano. Awon wonyi ni won saaju awon egbe won to ku, ti won si n fa won sinu egbe PDP tuntun. Leyin ti won si sepade ti won ko ribi fi ori oro naa ti si, won ni awon yoo tun pade lojo keje, osu kewaa, to n bo yii, ibi ti awon ba si ba a de nigba naa, gbogbo aye yoo foju ri i. Sugbon Jonathan ati awon ti won jo n sejoba ti so pe awon ko le gba, awon ko fe ki won da ijoba PDP si meji, bee ni ojo n lo gidi gan-an. Awon Kawu Baraje ti inu egbe PDP tuntun ni ko si eyi to kan awon nibe, bi Jonathan ba ti gba ohun ti awon wi, kia lawon yoo pari ija, ti kaluku yoo si maa ba ise re lo. Won ni awon naa ko feran ija, Jonathan ati Tukur lo pe ogun, iyen naa lawon si se gbe ogun tiwon, enikan ni yoo si reyin enikan.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Saturday, January 25 @ 04:53:47 PST Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· EsinIslam Media Yoruba
· Ekunrere Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere:
Oye Okere Tilu Saki, Ile-ejo Ni Mogaji Ko Gbodo Gbe Igbese Kankan Bayii


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere

"Ija PDP N Buru Si I - Baba Iyabo, Atiku, Jonathan - Ajatu-Akata, O Doju E" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: