Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo
[ Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo ]

·Ilu Kan, Oba Marun-Un: Oba Ni Egba Ake, Egba Owu, Egba Agura, Oke Ona Ati Ibara
·Eyi Ni Bi Owo Se Te Alao To Fi Khadija Omo Igbakeji Mimiko Soogun Owo L'Aku
·Itan Bi Ladoke Akintola Se Di Aare-Ona-Kakanfo Ile Yoruba
·Eni Ba Fibi Soloore, Iya Ni Yoo Je Ku
·Akanni She Ayederu Iwe INEC, O Lashofin Loun, Lo Ba Fi Gba Awon Eeyan Repete
·L'Oshogbo, Awon Omo Egbe Okunkun Ti Won Fesun Ipaniyan Kan Foju Bale-ejo
·O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
·Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
·Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


E Gba Wa O, Awon Olokada Ogbomoso N Ja Wa Lole Awon Ara Ilu
 
 
Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
Lati Owo Abayomi Akanni, Ogbomoso

E Gba Wa O, Awon Olokada Ogbomoso N Ja Wa Lole Awon Ara Ilu

Lati bii ojo die seyin nisele a-n-ja-baagi gba lowo ero ti awon olokada kan ti so dise ti gba igboro ilu Ogbomoso, koda oro yii gan-an tun kan awon to n ti ibi iso-oru bo, bibeli, owo, to fi mo foonu won ni won n gba lo. Beeyan ba n rin legbee titi ti ko fura, kia ni won a ti ja baagi to gbe kopa gba lati ori okada, ti won a si sa lo. Ogooro awon iyaloja to n ji lo si irinajo loo raja lo si ti ha sowo awon elegiri ohun, ti opolopo won si ti pada si ese aaro.

Ninu oro Abileko Victoria Alabi to je onisowo elubo ti awon olokada ja baagi re gba, to si se bee padanu owo to to egberun lona ogoje o le marun-un naira (145,000) o n so pe ko ti i ju osu meji lo ti awon ole ko soobu oun ti awon eleyinju aanu fi kowo foun lati tun ra oja.Nnkan bii aago mefa aaro ojo Alamisi (Tosde) ose to koja lo loun gbona oja. O ni oun koko da olokada naa duro, sugbon o ni oun ko lo, afigba toun ri i to yiju pada waa ba oun, lo ba bere si i lo baagi mo oun lorun, loun ba kigbe ole sugbon kawon eeyan too de, o ti fi ese da batani soun lara, loun ba daku lo gborangandan. Bo se gba owo lowo oun niyen. Mama yii

loun ti fisele naa to awon olopaa leti.

waa ro gbogbo awon onisowo egbe e pe ki won pada si ese aaro, ki won maa toju owo won sinu igbanu.

Nigba to tun di ojo Aje, ojo kerindinlogun, osu ta a wa yii, won tun ja poosi to je ti Arabinrin Nafisat Jimoh to n ta oili lagbegbe Ora-gada gba, won si gbe owo ti ko din legberun lona aadorin naira (70,000) lo. Obinrin yii ni oili ogbon naira ni awon olokada naa ra lowo oun, ti won si fun oun ni aadota naira, senji muri kan loun n wa lowo ti won fi ji poosi oun nibi toun fi si toun ko si fura, ni won ba ni koun ma wule daamu ara oun mo, ni won ba lo. Nibi toun ti ni koun fowo sinu poosi loun ti wa a ti.

Nigba ti akoroyin Iwe Iroyin Yoruba kan si awon iyaloja ati babaloja oja Aaraadaa, Alagba John Adewole ti awon eeyan tun mo si Abanise ati Oloye Alice Ojewumi so pe loooto ni ko si ifokanbale mo, iberu-bojo lo ku tawon fi n gun okada nitori se ni awon olokada kan n pale gbogbo baagi, to fi mo poosi owo awon eeyan mo, ti won yoo si sa lo. Awon eeyan yii ni oge aseju lo n koba awon oloja nitori pe igbanu ni won n lo laye atijo, yoo si nira keeyan too le towo bonu aso eni lati tu u lo bo se rorun lati ji poosi.

L'Ojoru, ojo kejidinlogun, osu kesan-an, odun yii ni akoroyin Iwe Iroyin Yoruba kan sile egbe olokada to wa lagbegbe Arinkinkin, awon to je oga won so pe awon eeyan awon ki i se ole, awon ti Gomina Fasola ti ipinle Eko le danu lo n pitu owo won.

Nigba to n soro, aare egbe National to je ti olokada nijoba ibile Guusu Ogbomoso, Alagba Olamoyegun Oluwole, so pe awon olokada ti ko si ninu egbe kankan lo n seru ise ibi bee laarin igboro, ati pe bi won ba mu iru won, won ko le ba kaadi idanimo olokada lowo won.

Orisiirisii igbese lo lawon ti gbe lati le dekun iru iwa bee.

Ninu oro oga agba fawon olokada nijoba ibile maraarun ekun Ogbomoso, Alagba Adeyemi James Omowale, oni iwa a-n-ja-baagi gba ki i waye tele, afi nigba ti Gomina Fasola ti ipinle Eko le awon olokada kuro, ti opolopo won si bale siluu Ogbomoso ni ise ibi naa ti bere laarin ilu. O fi kun oro re pe opolopo won ko darapo mo egbe kankan, ati pe orisii ilu lawon eeyan ti n waa gun okada niluu naa. O fi kun un pe ohun tawon eeyan ilu gan-an n da sile ninu oro yii ko kere, idi ni pe bi owo awon ajawee ba te okan lara awon olokada yii, nise ni won a maa da soro ti ko kan won rara.

Okunri yii ni laipe yii ni igbese tawon yoo fi wagbo dekun iru iwa odaju, ole ati jibiti bee yoo waye.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, March 30 @ 04:23:37 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue:
O Ga O! Awon Olopaa Ati Adigunjale Fibon Para Won Loju Ija Niluu Ibadan: Awon Ol


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue

"E Gba Wa O, Awon Olokada Ogbomoso N Ja Wa Lole Awon Ara Ilu" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: