Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
[ Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga ]

·Eyi Ni Bi Enu Se Ko Ba Bobrisky, Okunrin To N Se Bii Obirin: Won Ni Awon Olopa D
·O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
·Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
·Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
·Owo Te Wahab Nibi To n Ti n Se'Kinni' Fomo Odun Mewaa Legbee Ogiri
·Mumini Lu Magun Lara Iyawo Oloye Ilu n'Iyana-Offa
·Imeh Ha Sowo Olopaa L'Ekoo, Aburo Iyawo e Lo Se Kinni un Fun
·Aliyu Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po n'Ilorin, Lo Ba Doyun
·Adebowale Atawon Egbe e Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Awon Adigunjale Ya Bo Banki Moniya
 
 
Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Awon Adigunjale Ya Bo Banki Moniya

Eeyan meji lo padanu emi won moju ojo Aiku, Sannde, ijeta nigba tawon digbolugi adigunjale bii metadinlogun ya bo ileefowopamo FCMB to wa nitosi Kara, ni Moniya, Ibadan.

Ago olopaa to wa legbee ileefowopamo ohun, iyen tesan Kara to wa labe akoso ago olopaa Moniya lawon eeyan naa koko kolu ti won si yinbon pa oga won, ASP Taiwo Adekusile, ni nnkan bii aago kan aabo oru ojo naa. Bee lawon ogbologboo adigunjale naa ko ibon olopaa merin lo pelu aso atawon ohun eelo agbofinro gbogbo ti owo won to.

Bo tile je pe afojusun awon adigunjale ohun ni lati fo banki yii ki won si ko gbogbo owo to wa nibe lo, awon agbofinro ni won koko dojuko, won fee koko gbogun ti awon to le di won lowo nibi ise buruku won ohun.Gege b'Iwe Iroyin Yoruba se gbo, meji ninu won ni won koko ti siwaju lati loo wo bi oju ile se ri na. Bi awon wonyi se debe, nise ni won dibon bii araalu ti alaafia je logun, won ni awon kan n di alaafia adugbo awon lowo, awon si fe ki awon olopaa naa yan eni ti yoo ba awon mu arufin ohun ti mole lodo won nibe.

Oro yii ni won n so lowo ti okan ninu awon obayeje eeyan yii fi pariwo ke sawon akegbe won lohun rara nibi ti kaluku won ti farapamo si. Leekan naa ni gbogbo won jade ti won si ya bo tesan olopaa naa bii igba tawon ijalo ba bo oku eran.

Pelu bo se je pe oru ni gbogbo eyi n sele, awon olopaa to wa ninu tesan naa ko ju merin lo.

Ko gba awon eni ibi ohun lasiko rara lati gba agbara lowo awon meta ti won wa nibe ki won too wole to oga won lo.

Sugbon sa, ASP Adekusile fi ye won pe akoni agbofinro ni oun i se. Oun ti gburoo awon jagunlabi latinu yara e to wa, lesekese lo si ti mura ija. O yara ke ibon e lati koju ogun naa, sugbon amuni-kolu-ni, alangba ori esu nibon ti oga awon olopaa naa ke. Bi awon eruuku se gburoo pe enikan ke ibon nibi kan ni won ti pariwo pe ta lo ke ibon nibe yen. Nigba naa lawon bii mefa ninu won loo sigun ba a tibinu-tibinu. Saaju lawon odaran naa ti fi lilu han awon olopaa ti won koko ba pade leemo. Won fi idi ibon da ogbe nla sagbari okan ninu won, won si fi okun de awon meji yooku mole ki won too wole to oga won lo.

Gege b'Iwe Iroyin Yoruba se gbo, ASP Adekusile fere ma ti i je ki won wole tan to ti yinbon fun okan ninu won to si tun ba won fija peeta. Sugbon awon odaju adigunjale yii po ju lori oun nikan, nigba ti won yoo si fi ja ija ohun fun iseju meloo kan, won paapaa reyin e leyin ojo oke aimoye ibon ti won ro le e lori.

Bi isele ohun ko tile soju eeyan, eni to ba debe to ri i bi ota ibon awon eruuku ohun se dabira si gbogbo ara ogiri ofiisi oga naa fotofoto, yoo mo ohun to ni lati sele si okunrin naa nigbeyin-gbeyin.

Bi awon to n jagun ibon ninu ile se n se tiwon lowo ni die ninu awon to duro sita tijatija taju kan-an ri ile kekere kan to wa legbee tesan naa, won si woye pe enikan wa ninu ile oniyara kan ohun. N lawon alailaaanu eeyan yii ba tun loo gbe ogun ka eni eleni mole laimo pe okunrin naa ki i se olopaa gege ba a se gba pe won ro lokan ara won.

Lati ita ni won ti bere si i yinbon fokunrin naa lai je pe oun funra e silekun fun won, leyin eyi ni won fipa ja ilekun le e lori, ti won si wo o jade sita. Iwaju ita ile ohun lokunrin Hausa naa paapaa dake si.

Awon ero to koja legbee e ni afemoju ojo naa ti won ri i nibi to ti n japoro iku nibe ko gbiyanju ati se aajo e nitori won ko riran ri eje to bo o lara latoke dele, won ro pe oti amupara lo so o di eleya bee. Leyin naa lawon apani-sola ole yii dojuko ileefowopamo ti won mo-on-mo waa ja lole gan-an.

Akiyesi akoroyin wa fi han pe die ninu awon arufin yii ko fi ara ire jade ninu tesan naa pelu ipa eje eeyan to kan sile tolotolo kaakiri se n toka si gbogbo ibi tawon odaran naa gba koja lo sileefowopamo naa.

Bo tile je pe won ba awon ilekun kan je ninu banki ohun, won ko lanfaani lati de yara agbara won debi ti won yoo ri owo kankan gbe. Eyi lo mu ki won loo kanra mo ileepo nla kan to wa lodikeji ileefopamo naa.

Iwe Iroyin Yoruba gbo pe ni nnkan bii aago merin idaji ku iseju mejila lawon loogun ba won lalejo nileepo nla naa.

Ero amunawa to n sise lowo ni won koko loo pa. Leyin ti gbogbo agbegbe naa ti wa lookun ni won koja sidii ero ayaworan to maa n tu asiri ise ibi gbogbo to ba sele ni ayika ileepo ohun,won si ba a je.

Leyin e ni won de awon osise ileepo naa lokun mole, sugbon won da okan si ninu won, okunrin yii ni won ti siwaju pe ko maa mu awon lo si gbogbo ibi ti won n keru si ni ileetaja igbalode nla to wa ninu ogba ileepo naa.

Ipa la gbo pe won fi ja awon ilekun wole sawon yara gbogbo ti won keru si nibe, ti won si kowo ati oke aimoye eru lo.

Alaaji to nileese naa to ni ka foruko boun lasiiri so pe owo ati dukia tawon eni ibi naa ko lo lodo oun ko niye nitori aje bugba je fun oun latojo Abameta moju ojo naa daadaa.

Akoroyin wa ri oogun abenu-gongo kan tawon igaara olosa ohun ri mole niwaju tesan awon agbofinro naa.

'A¯ba¾' loruko ti won pe e, won ni kinni buruku ohun ni ki i je keesin ta firi nibikibi tawon adigunjale ba ri i mo titi ti won yoo fi pari ise ibi won.

Gbogbo igbiyanju awon agbofinro lati jo kinni dudu ohun nina lo ja si pabo pelu bi ina ko se ran an titi ti akoroyin wa fi kuro nibe.

Nigba to n fidi isele yii mule, alukoro ileese olopaa ipinle Oyo, DSP Olabisi Okuwobi-Ilobanafor, so pe loooto nisele ohun waye ati pe bi won se po lori oga olopaa tesan naa lo sokunfa iku e, nitori okunrin naa pitu meje tode n pa nigbo ko too pada je Olorun nipe.

Obinrin agbenuso awon agbofinro naa so pe o se ni laaanu pe isele yii mu emi okan ninu awon olopaa lo, sugbon iwa akikanju tokunrin naa hu pelu bo se ba won ja to si se die ninu won lese ni ko fun won lanfaani lati fokan bale pitu owo won nileefowopamo ti won mo-on-mo fee ja lole.

DSP Ilobanafor, eni to so pe awon olopaa ti bere iwadii lori isele naa tun ro awon araalu lati maa wa ni ikiyesara nigba gbogbo ki won si fi to awon agbofinro leti ti won ba ri awon eeyan to ni apa ibon lara, tabi ti won ba ri ibon ati ohun eelo olopaa lowo eni ti won fura si pe ki i se agbofinro.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, March 30 @ 04:35:28 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue:
O Ga O! Awon Olopaa Ati Adigunjale Fibon Para Won Loju Ija Niluu Ibadan: Awon Ol


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue

"Awon Adigunjale Ya Bo Banki Moniya" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: