Gbagede Yoruba
 



Lasiko Ayeye Kanifa, Bashiru Sa Jamiu To N Lo Jeje E Ladaa Pa L'Ofa
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
Lati Owo Seyi Adeshina, Ilorin

Lasiko Ayeye Kanifa, Bashiru Sa Jamiu To N Lo Jeje E Ladaa Pa L'Ofa

Inu ogba ewon n'Ilorin ni okunrin birikila kan, Ogbeni Bashiru Abdukareem, eni to sa Ogbeni Olasunkanmi Jamiu ladaa pa lakooko ayeye awon odo kan niluu Ofa wa bayii.

Gege bi a se gbo, lakooko tawon odo ohun n se ayeye olodoodun ti won n pe ni Carnival ni won bere si i fada hale ti won si n pa igo lati je kawon araalu mo pe awon lagbara. Asiko ohun ni Jamiu n koja lo jeje e ti won si sa a ladaa pa.

Awon esun ti won fi kan Bashiru ni kootu ohun ni ipaniyan, dida alaafia ilu laamu, kiko sawon eeyan ninu lati da ilu ru ati dida egbo si eeyan lara.



A gbo pe Ogbeni Ibrahim Raji lo loo foro naa to awon olopaa agbegbe Ofa leti nipa iwa buruku ti Bashiru hu, ati pe se ni olujejo gbimo-po pelu awon kan, iyen Yello, Lukman Saroti atawon mi-in lati sise ibi ohun. Awon yooku ti sa lo, Bashiru nikan lo n kawo ponyin rojo ni kootu.

Bashiru ti won lo n gbe adugbo Alagbede, l'Ofa, ko ju omo odun metalelogun lo. A gbo pe ohun tawon odo toogi ohun n tori e ja ni ta ni alagbara tabi olori laarin idile Alubata ati Ile Nla niluu Ofa, eyi ni won fi seku ojiji pa eni eleni.

Olopaa to n soju ijoba, Arabinrin Mojisola Olamokun, so ni kootu pe ejo naa si n te siwaju, fun idi eyi, ki won ri i daju pe won fi olujejo sogba ewon di asiko igbejo mi-in.

Adajo-binrin M. Q. Salahu gba imoran olopaa yii, o si pase ki won ju Bashiru satimole ogba ewon to wa lagbegbe Oke Kura, n'Ilorin, titi ti iwadii esun naa yoo fi pari. O sun igbejo si ojo keji, osu kewaa, odun yii.


 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, March 30 @ 04:45:10 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam



Comments 💬 التعليقات
 

For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا

Awọn ọna asopọ ti o jọmọ

· Die sii Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Iroyin Nipasẹ MediaYorubaTeam


Ọpọlọpọ Itan Ka Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwọn Abala

Apapọ Dimegilio: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

Jọ̀wọ́ Gba Ẹ̀ẹ̀kejI ki o sI dIbo fun Abala YIi:

O tayọ
O dara pupọ
O dara
Deede
Buburu


Aṣayan


 Ọrẹ-itẹwe Ọrẹ-itẹwe





Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu



"Lasiko Ayeye Kanifa, Bashiru Sa Jamiu To N Lo Jeje E Ladaa Pa L'Ofa" | Buwolu wọle/Ṣẹda Eto Akọsilẹ | 0 Awon Alaiye


Awọn asọye jẹ Ohun ini nipasẹ Iwe ifiweranṣẹ. A Ko Lodidi Fun Akoonu wọn. Nibayi, A Pe Awọn oluka lati jabo Eyikeyi Abusive, Unsuitable And/tabi Islamophobic Content



Ko si awọn ọrọIwoye Ti o gba laaye Fun Aisinisi, Jọwọ Forukọsilẹ
 

Gbagede Yoruba
Akọọlẹ Tirẹ
Ojule Akọkọ  | Awọn Itan Yoruba  | Gbagede Yoruba  | Ifiranṣẹ Ara-ẹni  | Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba  | Koko Mẹwa  | Ẹka Abule  | Ifirohin-Ransẹ  | Iwadi  | Agbeyẹwo  | Ifimufilẹ  | Iwe Akọọlẹ  | Apoti Akọsilẹ  | Isopọ Ọpọnlujara  | Ẹgba Ayelujara  | Ipolongo Wa


Ẹsin Islam الدين الإسلامي Religion of Islam Addinin Musulunci Agama Islam Religión del Islam 伊斯兰教 Dini ya Kiislamu Религия Ислам Religião do Islã イスラム教 Esin Islam 이슬람의 종교 Portal African Muslim Website - Arabic English African Islamic Website For World News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Articles, Radio, Audio, Video, Quran, Hadith, TV Channels, Fatwas, Muslim News, Newspapers, Magazines Headlines, Forums, College, Schools, Universities, Mosques, Quranic, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Ramadan, Vidoes, Books, Fasting, PDFs On EsinIslam.Com And IslamAfrica.Com