Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
[ Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise ]

·Ni Ti Ooni, Alaafin Ati Aare Ona Kakanfo
·Sugbon Ta La Ri Ba Wi, Bi Ko Je Baba To Fi Omo Re Foko L'oru
·Ni 1978, Emo N Lo, Afe N Lo, Azikiwe Nikan Ni Ko Ti i Mo Ibi To Fee Gba Lo
·Leyin Odun Mokanla, Bose Fee Ko Oko Re Sile l'Abeokuta: Nitori Orekunrin Re
·Aafaa Abdulraham Ma N Shere Ni Bebe Ewon, Omo Ile-keu Re Fipa Ba Lo Po L'Ed
·Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
·Iyaale Ile To Fi Kokeeni Soyun Ti n Ka Boroboro
·Lati Ekiti Ni Wasiu Atawon Ore Re Ti Waa Fi Owo Ayederu Raja n'Ilorin
·Onisowo Ibadan Bo Lowo Awon Ajinigbe Leyin Ojo Marun-un Ninu Ahamo Won

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Owo Te Biodun, Ogbologboo Adigunjale N’Ibadan, Oko Olowo Nla Lawon Maa N Ja Gba
 
 
Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Owo Te Biodun, Ogbologboo Adigunjale N’Ibadan, Oko Olowo Nla Lawon Maa N Ja Gba


Nigba ti owo awon SARS to n gbogun ti idigunjale nileese olopaa ipinle Oyo te oga iko awon ogbologboo adigunjale Ibadan kan, Biodun Adelabu, o soro lati mo awon eeyan to ti kagbako iko re pelu bi gbogbo awon to gbo iroyin ohun se n fo fere fayo. Idi ni pe bo tile je pe gbogbo won naa ko ni won mo okunrin yii, ojo pe ti won ti n gbo iroyin bi ajanaku oun atawon emewa e se n migbo kijikiji.

Biodun, eni odun metadinlogbon pelu merin ninu awon omo eyin e ni won da okan ninu awon asofin ipinle Oyo, Onarebu Bamidele Ojo, lona ti won si yinbon fun okunrin jeje naa ninu osu kejo, odun yii, sugbon ti Eledaa ko o yo. Nise ni won fibon tu ifun baba naa, ise abe ni won si se fun un.Oke aimoye eeyan bee ni Eledaa won ko ti won leyin lowo Biodun atawon emewa e ti won si ti se bee padanu owo, oko ayokele atawon dukia iyebiye mi-in. Sugbon ko si ibi ti ariwo ayo ti mi igboro titi to adugbo Oke-Apon, nIbadan nitori nibe lokunrin igaara ole naa n gbe.

Bi won ba n soro nipa iko adigunjale to gbona bii ajere, ti ogbon ati ete ise naa si wa lowo won n«Ibadan ati agbegbe e, oga ni iko naa lojokojo. Ohun to maa n je isoro awon ti won yan oko olowo nla laayo lati maa ji gbe ni eto aabo tawon eeyan maa n se si i lara, sugbon eyi ki i se isoro fun awon Biodun nitori won ni enikan ninu won to mo nipa bi won se n ba eto aabo moto je daadaa, iyen lo n je Victor Okafor.

Bee naa ni won se lojo kesan-an, osu kejila, odun to koja, nigba ti won fibon gba oko ayokele olowo nla kan to je ti okan ninu awon olootu ileese itewe nla ti won n pe ni Macmillan, laduugbo Ring Road, nIbadan.

Bi won se gba oko naa ni Okafor sise owo e kiakia, sugbon gbogbo ogbon alabahun, eyin ni yoo maa to igbin lojokojo. Asiri won tu nitori awon olopaa da Okafor duro niluu Ikire, nipinle Osun, nigba to n gbe oko naa sa lo si Abuja. Leyin naa ni won mu baba isale won ti won n pe ni Alaaji Ibrahim Animasahun ati Biola Ayoola. Eyi lo mu ki Biodun ko lo si Eko nigba naa fun igba die.

Geogeo bIwe Iroyin Yoruba soe gboo, ookada lookunrin to pera eo loomoo bibi ilu Iloorin yii fi n soe eoseo rin, o si joo pe soe lo ji i. Oreo eo kan ninu ile to n gbe laduugbo Oke-Apoon lo gun un jade ni nnkan bii osou meota seoyin tawoon ooloopaa tesoan Yemeotu si da a duro. Woon beere iwe alupupu naa, o ni oowoo ooreo oun to ni in lo ni lati wa, sougboon Bioodun funra eo o ri iwe ookada ko sileo, o ni eoni to ta a foun ko ti i fun oun niwee eo nitori oun ko ti i san owo pe. Agboo pe ookada oohun soi wa ni tesoan ooloopaa Yemeotu nibeo titi ta a fi pari akojoo iroyin yii, beoeo ni ko ju osou kan loo sigba naa ti Bioodun fi ra ookoo goooofu tokunboo kan wale lati Eko to ti loooo soe atipo.

Ta a ba ni i paroo, oojoo peo ti ikoo yii ti n pa awoon eeyan leokun, beoeo lo peo tawoon agbofinro ti n doodeo woon. Sougboon goongoo soo loojoo ti woon foju kan ooga awoon adigunjale ti woon n pe ni Bioodun yii ninu ookoo eo laduugbo Beoyeorunka, nIbadan, to n jaye kiri. Ko pe oun ko pa woon nitori bo soe ri awoon agbofinro lo dana iboon ya woon, sougboon awoon eesin-o-kooku naa jeowoo fun un pe lakoo lawoon wa bii iboon.

Iwe Iroyin Yoruba gboo pe o gba woon ni asiko dieo ki woon too ri ogbologboo yii mu. O soe ookan ninu woon lesoe ganan, nigba ti woon si too yinboon fun un leoseo ni eegun reo too roo ti woon fi ri i mu.

Nigba to n fi Bioodun han awoon oniroyin lorukoo CP Mohammed Indabawa, Alukoro ooloopaa ipinleo naa, DSP O・labisi Okuwobi-Ilobanafor, fidi eo muleo looseo to kooja pe o peo tawoon ti n doodeo reo kawoon too koolu u nibi tawoon ti mu un.

Bioodun ko fi ookan pe meji nigba to n soalaye itu to ti pa nidii isoeo idigunjale. O ni, ƒNi nnkan bii oodun meota seoyin ni mo beoreo idigunjale. Eonikan ti a n pe ni Alaaji Animasoahun lo mu mi woo isoeo yii, oun ni mo maa n ta awoon foonu ti mo ba ji fun. Beoeoreo, n≪Ibadan, ni sooooobu eo wa, oun naa lo mu mi moo eoni ti a n pe ni Bigi. Bigi yeon, Abuja lo n gbe, oun la maa n ta awoon mooto ta a ba ji fun.

Mo ti niyawo, mo si bimoo kan. Mo moo nipa isoeo asooo tita, sougboon mi o da sooooobu tara mi ni, isoeo yeon niyawo mi ro pe mo n soe. Ti mo ba ti loo si Eko nigba mi-in, ma a yaa ra jinsi dieo boo.

Sougboon lati igba tawoon ooloopaa ti fi Bioodun han awoon oniroyin lolu ileesoeo woon to wa ni Eoleoyele loojoo Isoeogun to kooja ni okiki ti kan de adugbo woon, lati igba naa si ni itiju ti ba iyawo eo. Ni nnkan bii aago mookanla aaroo oojoo Eoti, Fraide, to kooja lobinrin naa ko gbogbo eoru eo jade, sougboon o soe nnkan ti awoon araale woon ko fi ni i gbagbe eo booroo. Nisoe lo tun gbe eoroo amunawa ooreo ookoo eo peolu isoaasun oobeo ookunrin naa loo.

Bioodun tun soalaye pe, Ta a ba ti ri mooto ti woon gbe sileo, a maa loooo koolu u lati eoyin. Ti eoni to ni in ba ti boo sileo la maa gba a.

Awoon asoofin meji la ti koolu ri. Ileepo la ti loooo ba eoni ta a kookoo da loona laduugbo Ashi, a si gba mooto eo, sougboon a ko yinboon fun un. Adugbo Olodo la ti gbe asoofin keji, a fi mooto wa koolu u, bo soe sookale la gbe e sinu mooto wa. Nigba to n soe agidi ni ookan ninu wa to n jeo Suraju yinboon fun un, a waa ju u si eogbeo igbo kan loona Eogbeoda.≈ ƒLoojoo keosan-an, osou kejila, oodun to kooja la gba ookoo ayookeoleo Toyota Avensis alawoo dudu kan loowoo obinrin kan laduugbo Ade-O・yoo ni Ring Road, a si gbe e fun Victor lati yoo eroja idaabobo ara eo.≈ Bioodun ni ori yoo oun ti awoon ooloopaa ko ri oun loojoo ti woon mu eyi ti woon n pe ni Bioola nigba to n boo lati ibi inawo ti Alaaji Animasoahun soe laduugbo Alekusoo, Beoeoreo lo loun wa toun ti n wo bi woon soe n mu un loo. O ni iyeon lo jeo koun sa loo Eko. Loojoo kan ni Bigi pe oun pe kawoon tete maa mura fun idigunjale mi-in, o ni soe oun moo pe bi woon soe mu Bioola, owo lawoon maa na lati beeli eo peolu awoon mi-in ti woon ti mu.≈ O fi kun un pe Alaaji Animasoahun lawoon maa n jaboo fun ni gbogbo igba, ati pe awoon ko paayan ri lati igba tawoon ti beoreo isoeo naa. O darukoo awoon to ku bii Yusuf, Suraju ati Dayoo.

Iwadii Iwe Iroyin Yoruba fi han pe ile meji ni Bioodun reonti to si n gbe nitori iyawo meji lo ni. Iyaale ti bimoo kan fun un, nigba ti iyawo kekere ko ti i bi, beoeo oodoo reo lo maa n gbe ni Oke-Apoon.

Nibi ka maa rin irin oru ati ka ma moo isoeo ti ara ile eoni n soe lo mu kawoon eeyan beoreo si i fura si i, paapaa peolu bo soe jeo pe ni gbogbo asiko tawoon adigunjale ba wa si adugbo naa ni ki i si nile.

Geogeo bi ookan ninu awoon alabaagbe Abey se soo fakooroyin wa, ƒNi bii inu osou keota si osou keorin oodun yii lawoon ole yoo wa leonu gan-an laduugbo yii. Nigba yeon lawoon lanloooodu pe awoon ayalegbe woon si ipade. Soe eo moo pe oowoo to ba dileo lesou n beo nisoeo, nitori eo ni woon se beere isoeo ti awoon teonanti n soe. Onisoowo asooo ni Bioodun pera eo nigba naa, latigba naa lawoon ara adugbo si ti n fi oju eeyan gidi wo o laimoo pe ogbologbo adigunjale ni.

Soa, DSP Ilobanafor ti soo pe ileesoeo ooloopaa yoo gbe afurasi-adigunjale naa loo sile-eojoo leoyin ti awoon ooloopaa ba pari iwadii woon.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, March 30 @ 04:45:17 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue:
O Ga O! Awon Olopaa Ati Adigunjale Fibon Para Won Loju Ija Niluu Ibadan: Awon Ol


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


"Owo Te Biodun, Ogbologboo Adigunjale N’Ibadan, Oko Olowo Nla Lawon Maa N Ja Gba" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: