Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
[ Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga ]

·Eyi Ni Bi Enu Se Ko Ba Bobrisky, Okunrin To N Se Bii Obirin: Won Ni Awon Olopa D
·O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
·Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
·Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
·Owo Te Wahab Nibi To n Ti n Se'Kinni' Fomo Odun Mewaa Legbee Ogiri
·Mumini Lu Magun Lara Iyawo Oloye Ilu n'Iyana-Offa
·Imeh Ha Sowo Olopaa L'Ekoo, Aburo Iyawo e Lo Se Kinni un Fun
·Aliyu Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po n'Ilorin, Lo Ba Doyun
·Adebowale Atawon Egbe e Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


O Ma Se O, Ibrahim Ku Somi L'Eko-ende, Nibi Ti Won Ti N Dije Odo Wiwe
 
 
Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
Lati Owo Florence Babasola, Osogbo

O Ma Se O, Ibrahim Ku Somi L'Eko-ende, Nibi Ti Won Ti N Dije Odo Wiwe

Oro di bo o lo o ya lona lojo Eti, Fraide, ojo ketadinlogbon, osu yii nibi eto idije kan ti ileese to n ri si oro asa ati ibudo igbafe (Ministry of Home Affairs, Culture and Tourism) l'Osun sagbekale lati fi sayeye Osun World Tourism Day Celebration, niluu Eko-ende, nijoba ibile Ifelodun, nipinle Osun, nigba ti okunrin kan, Ibrahim, ri sinu odo.

Gege bi a se gbo, aago mesan-an aaro di aago mewaa ale ni won fi eto naa to waye ni Ekoende Highland Lake si, sugbon oro ko ri i bee mo nitori pe ni kete ti wahala ti sele lonikaluku ti fese fe e. Oniruuru idije ni won salakale fun ojo naa bii iwe wiwe, ayo tita, eja pipa ati bee bee lo. lonikaluku ti fese fe e.Ni nnkan bii aago meji osan, opolopo awon eeyan ilu naa atawon lookolooko nileese eto asa l'Osun ti pese sitosi odo kan ti won n pe ni Odo-Otin, nigba ti idije ohun sun kan awon ti won mo-on we, awon meji ti won dangajia julo, Ogbeni Ibrahim ti gbogbo eeyan mo si Baba Musa ati Ojo ni won jo sedije naa.

Leyin iseju mewaa tawon mejeeji ti we lo sisale odo, Ojo to je omo bibi ilu kan nipinle Edo yo jade loke lohun-un, sugbon won ko gburoo Ibrahim toun je Agatu. Bo se maa n se lawon eeyan koko pe oro naa nitori aridaju iroyin fidi e mule pe ko si bi odo se jin to lagbegbe naa ti Ibrahim to je apeja to si n gbe niluu Oore, nijoba ibile Ifelodun kan naa ko le

de isale re.

Leyin bii wakati kan lara bere si i fu awon eeyan pe o da bii eni pe iku omi ti pa omuwe yii. Bayii lawon Agatu egbe e pelu awon iko panapana ti won wa nibi eto naa bere si i wa inu odo, o si gba won ni opolopo wahala ki won too ri oku Ibrahim yo. Won fi ambulansi ijoba ipinle Osun gbe oku Ibrahim kuro nibe, kia si ni gbogbo awon eeyan ti bese won soro to fi mo awon ti won n ta orisiirisii nnkan nibi eto naa.

Ki lo waa le fa iku gbigbona yii fun eni ti ki i se igba akoko ti yoo we lodo niyi? Iwe Iroyin Yoruba foro wa awon eeyan die lenu wo niluu Eko-ende, ohun ti pupo ninu won si tenumo naa ni pe aitele ilana yiyan Oba ko too di pe ijoba ipinle Osun kede oruko Oba to wa nibe bayii lo n fa iku akufa niluu naa.

Gege bi ohun ti a gbo, ko ti i ju ojo meta ti won jawe oye le Oba yii lori ti enikan ti won n pe ni Currency loo fo moto lodo ohun, leyin to fee ti moto naa sise ni iyen gbera fura re, to si seku pa Currency sibe.

Laipe yii la tun gbo pe Oba Olaniyan fowo si yiyan Bamgbade Aaje gege bii Oluwo ilu naa lati ropo Tijani Akinwoye, eni ti gbogbo eeyan mo gege bii Oluwo ilu Eko-ende to si je pe lodo re ni nnkan ti won n pe ni 'Edan, Iya Ajibola' ti won maa n lo fun enikeni to ba joba wa.

Sugbon nitori pe Akinwoye ko lowo si yiyan Oba Olaniyan la gbo pe o fa wahala laarin won, ti Kabiyesi fi faaye gba awon kan lati yan elomi-in dipo re ko tun too di pe Baba Musa tun ku somi yii.

Sugbon Oba Olaniyan ni iro patapata ni oro pe oun fi enikan je Oluwo. Kabiyesi ni, ''Aafa ni mi, awon onibaje ni won n so oniruuru nnkan nipa mi, ko si see se ka ma ri iru awon eeyan bayii ninu ilu. Ko si nnkan to kan mi nipa yiyan Oluwo, n ko ti i yan enikeni sipo latigba ti mo ti dori aleefa. Awon perete ni won n so bee kaakiri.'' Baba Musa la gbo pe o ti to eni odun mejidinlogoji, o niyawo meji, Olorun si fi opo omo jinki re.

Iwe Iroyin Yoruba ba Komisanna oro asa nipinle Osun, Onarebu Sikiru Ayedun, soro lori isele yii,

sugbon o ni oun ko le so nnkan kan nitori oun ko si lorile-ede Naijiria lowolowo.

Oba ilu naa, Alaaji Rauf A. Olaniyan so fun Iwe Iroyin Yoruba lori foonu pe ko si nnkan to jo bee rara, ati pe ko seni to ku nibe. Ohun ti Kabiyesi so ni pe, "Lati bii aago meji ku die la ti pari gbogbo eto lojo naa, emi atawon alejo si gba ibe loo kirun Jimo. Gbogbo wa la wa nibe pelu awon oludije, ko si nnkan to jo pe enikeni ku rara." Sugbon awon araalu naa so pe Kabiyesi ko so ooto fun wa, won ni loooto ni okan ninu awon omuwe ilu naa ti won n pe ni Baba Musa ku somi

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, March 30 @ 04:51:37 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo:
Agbonrin abami ran pasito lo sorun apapandodo l'Okeigbo


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo

"O Ma Se O, Ibrahim Ku Somi L'Eko-ende, Nibi Ti Won Ti N Dije Odo Wiwe" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: