Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
[ Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin ]

·Gbogbo Musulumi Jakejado Orileede Naijiriya Ni Babayemi Gba Niyanju Lati Se Awok
·Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Ikolu Awon South Africa Si Naijiria - Ekunrere
·Xenophobia (Ikorira-Ajeji) Attack: Awon Omo Naijiria Ti Yari Pe Awon Naa Yo Gbes
·Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
·Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
·Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
·Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
·Eru n Bawon Ara Mushin Nitori Oriyomi Ti Won Dajo Iku Fun
·Aafaa Wo Gau N'Ijare, Orebinrin Re Lo Seyun Fun, Niyen Ba Gbabe Ku

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Aini-asaaju Lo N Fiya Je Yoruba O Oga OPC Ni Kwara
 
 
Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
Lati Owo Idris Alooma, Ilorin

Aini-asaaju Lo N Fiya Je Yoruba O — Oga OPC Ni Kwara


Bii isana eleeta ni Alagba Moruf Salam to je alaga egbe OPC ni Kwara se gbajumo. Yato si pe o n ja fetoo iran Yoruba, opo awon nnkan to ro mo eto aabo ati ilosiwaju ipinle Kwara lo n kopa ninu e.

Laipe yii ni oniroyin wa ba okunrin naa soro. O so nipa ipo ti won to Yoruba si ninu isejoba Naijiria, bi ipo asaaju se n je iran Yoruba niya, ona abayo si isoro Yoruba atawon nnkan mi-in.

IPO TI IRAN YORUBA WA NI NAIJIRIA IPO TI IRAN YORUBA WA NI NAIJIRIA O se ni laaanu pe omo eleran iran Yoruba n jeegun ninu eto oselu ati isejoba Naijiria. Ni orile-ede yii loni-in, ipo kerinla lomo Yoruba wa. A ko si nipo Aare, a o si nipo igbakeji, a o si nipo awon olori ile igbimo asofin mejeeji, bee lo je pe omo Yoruba ko si nipo olori awon adajo. Nibi toro ohun buru de, omo Yoruba ko ni olori awon osise ijoba.Dipo ki a bara wa soro, ka wa ona abayo si bi ti iran Yoruba ko se ni i gbe, ti a ko si ni i dero eyin, nise la n se oselu etanu.

Ninu ipade ti a se niluu Ikene lopin odun to koja, a soro sijoba Jonathan lori bi ko se fi omo Yoruba sipo pataki, sibe, ko si ayipada lori e titi di akoko yii. Ohun to waa se ni laaanu ni pe awon asaaju wa, tara won ni won n ja fun.

Fun apeere, e wo Asiwaju Bola Tinubu, iyawo e lo sile igbimo asofin l'Abuja, omo e di Iyaloja, opo awon ipo nla nla lo si ko awon eeyan e da si. Oloye Obafemi Awolowo ko se bayii nigba to wa laye, ife ile Yoruba lo wa lokan e, o si ja fun eya Yoruba to fi ku ni, ko da bii awon asaaju ti a ni lasiko yii.Nigba ti omo Yoruba fee di olori ile igbimo asofin kekere, omo Hausa ni Tinubu satileyin fun, iyen lo gbe Tambuwal wole, bee oruko Awolowo ati Yoruba ni gbogbo won fi n depo.

ORO IPO BABA ISALE NINU ETO OSELU ORO IPO BABA ISALE NINU ETO OSELU Gbogbo awon to je Baba Isale awon oloselu ni won ko je ki ilosiwaju wa rara. Nitori pe awon Baba Isale yii lawon to wa nipo n sin, won ki i bikita fawon to dibo yan won mo. Fun apeere Tinubu l'Ekoo, Bukola Saraki ni Kwara, Adedibu nipinle Oyo nigba kan ati bee bee lo.

ASAAJU FUN IRAN YORUBA ASAAJU FUN IRAN YORUBA Iya asiwaju n je iran Yoruba, a nilo enikan ti yoo je asaaju wa ti yoo maa ja fun wa. O kan je pe ko si oloselu ti a le yan lakooko yii, nitori eni ti a o ba yan gbodo je itewogba fun gbogbo araalu. Bi a ba yan Tinubu, awon omo egbe oselu PDP yoo tako o, bee lo je pe ti a ba yan Obasanjo, awon omo egbe oselu APC ko ni i faramo on, a o si le yan Gbenga Daniel kawon eeyan ma soro. Loju temi, Otunba Gani Adams tun la le fowo si nitori ki i se oloselu, bee lo je eni ti ko mo tara e nikan to si n ja fun iran Yoruba.

Bi awon kan ba fee soro nipa ojo-ori e gege bii ibeere yin, omo odun meloo ni Gowon nigba to di Aare Naijiria, kin ni ojo-ori Dimeji Bankole to fi di oludari ile igbimo asofin kekere, kin ni ojo-ori Bukola Saraki nigba to fi di Gomina ipinle Kwara? Fun idi eyi, Otunba Gani Adams kaju e daadaa.

ORO WAHALA AWON GOMINA NAIJIRIA ORO WAHALA AWON GOMINA NAIJIRIA

Oro yii da bii owe Yoruba to so pe amukun-un eru e wo, o ni oke le n wo, e o wo isale. Tawon gomina merindinlogoji ba le ni alaga meji ti won o si ri i yanju, se e ri pe nnkan ti ko bojumu ni.

Awon asaaju wa o ni eto kankan fun awon araalu. E wo alaga meji to wa ninu egbe oselu PDP, bi Bamanga Tukur se n pase ni Kawu Baraje n dari apa kan egbe oselu ohun. Bi Obasanjo se n so pe Tukur ni isoro egbe oselu PDP, bee lawon eeyan Jonathan n bu Obasanjo.

Ki i se pe egbe APC naa fara ro o. Bawon kan se n so pe Tinubu lo n dari egbe naa, bee lawon mi-in n so pe ife tara e nikan lo ni. Bakan naa lo tun je pe egbe naa pin si meji ni Kwara, awon ti Dele Belgore ati ti Lai Mohammed, gbogbo eyi lo ye ko dopin.

ETO IDIBO IJOBA IBILE OFA ETO IDIBO IJOBA IBILE OFA Afi bii igba teeyan n wo fiimu agbelewo loro esi ibo Ofa ri. Bi ajo eleto idibo se kede esi ibo lawon egbe oselu APC so pe esi ayederu ni won gbe jade. Ohun tawon araalu n reti ni pe ki ajo eleto idibo jade lati fidi ododo oro ohun mule.

AKITIYAN WA NIPINLE KWARA AKITIYAN WA NIPINLE KWARA Egbe OPC n se opo akitiyan ni Kwara lori eto aabo, o kan dun wa pe ijoba ko se koriya fun wa. Egberun lona ogun olopaa pere lo wa ni Kwara, bee milionu meta lawon eeyan to n gbe nibe. Eyi to tumo si pe egberin eeyan si olopaa kan soso leto aabo Kwara da le lori. Bawo leto aabo yii se le lo deede? Eyi lawa se n ran awon araalu lowo lori eto aabo, sugbon o ye kijoba naa ran wa lowo ki won si se koriya fun wa. Nitori ise tawon olopaa o le se, awa OPC n se e daadaa.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, March 30 @ 05:22:25 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise:
Orin Ewi ni Yoruba - Yoruba Poems: Awon Owe Yoruba Proverbs Alo Oro


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise

"Aini-asaaju Lo N Fiya Je Yoruba O Oga OPC Ni Kwara" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: