Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
[ Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere ]

·Ijoba Ipinle Osun Ti Ki Oselu Bo Eto-eko O - Awon Eeyan Iwo-Oorun Osun Ke Gbajar
·Awon Aare Agbaye N Se Idaro Iku Robert Mugabe, E Gbo Nnkan Ti Obasanjo So
·Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
·Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
·O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
·Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
·Nitori Bi Won Ko Se Rowo Osu Gba, Awon Osise Di Onibaara Nipinle Oyo
·Nitori Owo Osu, , Edet Be Ori Omo Oga e N'Ijebu Ife
·Ipo Adele Oba Saki: Awon Afobaje Atawon Odo Yari Mo Ijoba Lowo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Nje Ija Ooni Ati Alaafin Le Pari Laye Yii Bi?
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
Lati Owo Adewale Adejare

Nje Ija Ooni Ati Alaafin Le Pari Laye Yii Bi?


Ibeere ti mo beere yii nidii o. O nidii gan-an ni. Opolopo awon eeyan ti won ti n da soro yii, ti won maa n te atejise ranse si mi latigba ti a ti bere oro asaaju Yoruba yii, awon kan wa ti won maa n tenumo on pe bi ija Ooni ati Alaafin ko ba pari, ko sohun kan ti a le se ti Yoruba yoo fi ni ilosiwaju laye yii. Awon mi-in ko ni i so bee yen, won yoo kan so pe ija aarin awon oba Yoruba ni ka koko yanju na, bi a ba ti yanju iyen nile Yoruba yoo toro.

Awon ka n tile la oro naa mole ni tiwon, ohun ti won wi ni pe awon oba merin lo n da ile Yoruba ru, won si daruko awon oba naa: Ooni, Alaafin, Awujale ati Oba Eko. Won nibi ti awon oba yii ba ile Yoruba je de lo wa nitori ija to wa laarin won, bi awon mereerin ko ba si pari ija naa, ko si asaaju kan ti yoo jade fun Yoruba wa yii.

Mo gba oro naa gbo debi kan, n ko gba a gbo tan. Mo gba pe ija wa laarin Ooni ati Alaafin, mo si gba pe ija yii n di ilosiwaju ile Yoruba lowo gidigidi. N ko mo boya awon oba mejeeji yii mo aburu ati oriburuku ti ija won n ko ba ile Yoruba, nitori bo ba se pe won mo pe awon lawon n fi ija yii ko ifaseyin ba wa ni, boya won iba ti mo ohun ti won yoo se si i, afi to ba se pe won ko fe ki Yoruba ni ilosiwaju rara, won kan fe ka maa seru awon eya to ku ni Naijiria ni. Sugbon ninu pe boya Awujale tabi oba Eko n ba Alaafin ja yen, ko soro ninu iyen. Idi ni pe Awujale ko le ba Ooni ja, bee ni ki i se Awujale lo n ba Ooni ja, Sikiru Adetona lo n ba Okunade Sijuwade ja to ni o n gberaga soun, ija yii naa ni won si fi n di ilosiwaju Yoruba lowo, nitori ohun to fa a ti Awujale fi so nigba kan pe awon ki i se Yoruba niyen.Bi ibi ko ba te, ti ibi ko ba wo, eni ti a ba niwaju to baba fun ni. Bo ba se pe lori oro ti Yoruba yii ni, ibikibi ti Awujale ba wa lo ti gbodo fori bale fun Ooni. Bi won si ti se n se e bo lojo to pe niyen o, afi nigba ti Oba Adetona je. Oba Adetona ko si ba Ooni kankan ja, afigba ti Sijuwade joba. Awon Obafemi Awolowo ni won fi dandan le e pe eni to mowe lawon fe ko je Awujale ni 1959 leyin ti Awujale Gbelegbuwa ku, awon yii naa ni won si ran S.O Sonibare lati loo mu un wa lati ilu oyinbo to wa, ti won si toju re pamo si ile Sonibare yii ni Maryland, Eko, titi ti won fi gbe e lo si Ijebu-Ode lati joba. Ko si tabi-sugbon kankan nibe, niwon igba to ti je owo Awolowo ni gbogbo agbara ijoba Yoruba wa nigba naa, bo ba se pe o koriira Sikiru Adetona tabi ti ko feran re, ko si bi okunrin ara ilu oyinbo naa iba se joba nigba naa.

Sugbon nigba ti ija oselu de, nigba ti ija de repete laarin Awolowo pelu Akintola, nitori pe Adetona je ore omo Akintola, isoro wa fun un lati wa leyin awon Awolowo, oro naa lo si da ija sile laarin won. Ija naa le debii pe nigba ti awon ti won je omoleyin Awolowo pada gbajoba, gbogbo ona ni Bisi Onabanjo gba lati yo Awujale kuro loye re. Nibi ti ija naa ti kan Okunade Sijuwade to sese joba nigba naa niyen. Awujale binu pe ni gbogbo igba ti laasigbo wa fun oun yii, ti won le oun jade kuro laafin oun, ti awon omoleyin Awolowo si n se iwe oun lo, Ooni ko ba oun da si i, koda ko sun mo oun rara, ko si kilo fawon eeyan re pe ki won ma foju Awujale gbole, nigba to si se pe ore lawon lati kekere. Bee ooto ni, ki Omooba Sijuwade too joba, ore nla loun ati Oba Sikiru Adetona, won jo maa n se faaji, won si jo maa n jade ariya gbogbo.

Ki enikeni too maa so ohun ti ko mo, oro ti mo so yii see wadii nibi gbogbo, o wa ninu awon iwe itan, awon mi-in ti won si dagba paapaa le so nipa re. Ooni ti soro yii loju mi ri pe ko sija kan laarin awon ju bee lo, Awujale ti soro naa loju mi ri, Obasanjo ti so o loju mi ri, bee ni Ayo Adebanjo. Ohun ti mo se so pe ko sija gidi kan laarin Ooni ati Awujale niyen, ija to wa nibe see pari daadaa, awon eeyan si ti gbiyanju re. Igba kan wa ti awon Ayo Adebanjo, Olanihun Ajayi - awon meji pere yii naa ni - ti won mu Awujale de aafin Ooni, ni bii odun 2009, ti Ooni gba Oba naa lalejo, ti awon mejeeji si jo da soro laarin ara won. Sugbon ohun to tun maa n ru ija yii sile ni ore ti Awujale ba Alaafin se, bi kinni kan ba ti sele laarin Ooni ati Alaafin, Awujale ni Alaafin yoo pe, yoo fi oro naa to o leti, ija naa yoo si maa feju si i.

Eleyii fi han pe ki i se Ooni ni Awujale n ba ja, ija awon ore meji lasan ni. Tabi ka pe e ni ota ore mi, ota emi naa ni, ore ore mi, ore emi naa ni. Iyen ni pe bi Ooni ati Alaafin ba n ja, nigba to se pe ore Awujale ni Alaafin, Awujale le da sija naa, yoo si so pe Ooni n ba ore oun ja. Ohun to n sele laarin awon wonyi niyen, o si daju pe bi ko ba sija laarin Ooni ati Alaafin mo, ko sija kan bayii ti yoo wa laarin Awujale ati Ooni.

Sugbon awon ija yii ti maa n ba nnkan to dara je ju ni, nitori nigba ti ija naa le ni Awujale so o ni gbangba, ti awon iwe iroyin gbogbo si gbe e pe awon Ijebu ki i se Yoruba ni tawon o, to si daruko ilu naa pe Wadai lawon ti wa. Bi awon agbalagba ba mo pe ija lo de ti Oba Adetona fi so bee, awon omo kekere ti won yoo ka iwe itan lojo iwaju nko, tabi awon omo Ijebu ti won ka oro to ba jade lenu oba won si oro lati odo Olorun won.

Bi ija Awujale ti ri yii naa ni ija Oba Eko ati Ooni ri. Ninu asa ati isedale Yoruba, ko si kinni kan to le fa ija laarin won rara, lati ibo sibo! Sugbon nigba ti Alaaji Riliwan Akiolu yoo di Oba Eko, ede-aiyede sele, nitori Kunle Ojora naa fee du ipo naa, oun naa fee di oba Eko. Kunle Ojora yii, ore timo-timo Ooni Sijuwade ni.

Bi won ba fee ka awon ore to sunmo Oba yii ju, boya ni won yoo ka eni merin ko too kan Kunle. Lati ile ni won ti jo n bo, won ko si n se ohunkohun leyin ara won. Dajudaju, bi iru Kunle ba fee joba, eeyan ko le so pe ki Sijuwade ma ran an lowo nibi to ba ti see se. Iranlowo yii lo bi Akiolu ninu, pe bawo ni Sijuwade yoo se gbe seyin enikan ninu idije ipo oba awon. Bo si tile je pe leyin ti Akiolu di oba tan, ti Ooni loo ki i to si ko ero leyin, to si mu ebun lo fun un, oro naa ko tan ninu Oba tuntun naa. Nitori pe Ooni pe Oba naa ni okan ninu awon omo oun, nigba ti Akiolu yoo pada fesi oro yii ni gbangba, ohun to so ni pe awon ki i se Yoruba, Binni lawon ti wa. Bi eeyan ba fee maa tu tifun-tedo oro ti Oba yii so, oluware yoo kan tun maa da nnkan ru si i ni, nitori itan ti won yoo pa fun un, oun naa ko ni i le gbe e sara.

Oro to so yii le mu ki ijoba ti ko ba feran re gba agbara olori ipinle Eko kuro lowo re, nitori awon oba bii Olofin Iseri, Oloto, Osolo, ati awon oba ti won ti Ife wa ni won ni ile won, ile Yoruba si ni gbogbo ibe, ibi ti won ti n da oko won lo di Eko. Nitori pe awon eru ti Oba Ibinni ran nise si fi agbara mu awon ti won n sise ninu oko yii lati di olori won ko so pe Yoruba ko ni won, tabi pe ile Ibinni ni Eko. Lara ohun buruku ti itan adorikodo ti awon oba wa maa n pa nitori ija maa n mu wa niyen, idi si niyen ti Jakande se le fi Osolo Farombi se alaga awon oba Eko ni 1980.

Sugbon eyin naa yoo ri i pe ija Awujale ati Ooni, tabi ti Oba Eko pelu Ooni, ati oju ati imu ni, ko si eyi to too gbe sare nibe. Nibi ti ija wa gan-an ni ti Ooni ati Alaafin. Nibi ti ise ti mo ni a oo se ti fee bere niyen.

Sugbon a gbodo koko mo idi ija yii, ka too le mo ohun ti a oo se si i, nitori emi naa gbagbo pe bi Ooni ati Alaafin ko ba ja, ile Yoruba yoo dara.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, March 30 @ 05:35:16 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 5
Awon Ibo Ni Oniyi: 1


E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Nje Ija Ooni Ati Alaafin Le Pari Laye Yii Bi?" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: