Yoruba
- Ojule    - Koko Mẹwa    - Ẹka Abule    - Ifirohin-Ransẹ    - Iwadi    - Oju-Agbo Yoruba    - Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba    - Agbeyẹwo    - Ifiranṣẹ Ara-ẹni    - Ifimufilẹ    - Iwe Akọọlẹ    - Apoti Akọsilẹ    - Akoonu    - Isopọ Ọpọnlujara    - Ẹgba Ayelujara    - Ibeere Ti Ọwọpọ    - Ipolongo Wa    - Ẹkun Imọ Ọfẹ   

 

 
Omo Ibo La Nnkan Mo Ore E Lori Nile Oti N'Ijesa-tedo, Lo Ba Pa A Patapata
 
 
Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
Lati Owo Olayinka Adedayo

Omo Ibo La Nnkan Mo Ore E Lori Nile Oti N'Ijesa-tedo, Lo Ba Pa A Patapata

Nitori esun pe o pa Sunday to je ore e, ni aago mesan-an aabo ale ojo kokandinlogun, osu keje, lagbegbe Pako, n'Ijesa-tedo, l'Ekoo, ti ile-ejo Majisreeti to wa l’Ebute-Meta fi kan Ukpai Ama-Ukpai, eni odun merinlelogun, adajo ti pase pe ki okunrin naa si wa latimole olopaa to wa n'Ikoyi.

Gege b'Iwe Iroyin Yoruba se gbo, isele naa waye lasiko ti Ama-Ukpai atawon meji kan ti owo awon olopaa ko ti i te bayii lo sile-afe kan lati loo muti, ko si pe rara ti ede-aiyede waye laarin won, eyi lo fa ibinu fun Ukpai to fi la nnkan mo ore re lori, teje si bere si i da lori omokunrin naa.Sugbon bi won se n gbiyanju lati gbe e lo sileewosan ni Sunday ku lojiji.
Lesekese ti won ri i pe okunrin naa ti ku ni won fi i sile ninu agbara eje re, ti won si sa lo, sugbon arakunrin Nefi kan, Dabup Kenneth, to ri gbogbo bi isele naa se sele lo sare pe awon olopaa ti won si wa, ko si pe pupo towo won fi te afurasi odaran ohun. Agbejoro ijoba, Silas Cyriakus, so fun ile-ejo pe esun igbimo-po lati sise ibi ati ipaniyan ni won fi kan an, eyi to tako ofin iwa odaran ipinle Eko, to si tun ni ijiya to lagbara labe ofin orile-ede yii. O so siwaju si i pe oun ti fi eda iwe esun naa sowo si eka to n ri soro idajo nipinle Eko fun imoran to peye.

Lasiko to n gbe ipinnu re kale, Adajo Abileko M.O. Tanimola pase pe ki won fi olujejo ohun pamo sogba ewon to wa n'Ikoyi titi tile-ejo yoo fi gbo imoran lati ofiisi eka to n ri si eto idajo nipinle Eko.

O waa sun igbejo sojo kefa, osu kokanla, odun yii.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, June 08 @ 19:50:25 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu:
Nitori Oro Ti Ko To Nnkan - Lamidi Fogo Mo Ore E Lori, Lo Ba Ku Patapta: Won Ti


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

"Omo Ibo La Nnkan Mo Ore E Lori Nile Oti N'Ijesa-tedo, Lo Ba Pa A Patapata" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: