Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
[ Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo ]

·E Waa Wo Simia To Pa Oree Re L'Osogbo o
·Nitori Foonu, Baale Ile Meji Jabo Sinu Konga, Loju Ese Ni Won Ku
·Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
·Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
·O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
·Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
·Grace Atale Re Pa Oko e N'Iyana-Ipaja
·Oro o, Iku Gbigbona Leleyi o! Nibi Ti Johnson Ti n Taja Loju Titi L'Akure N
·O Ma Se O! Dauda To n Tun Redio Se Gan Mona L'Osogbo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Tirela To Ko Opolopo Miliiki Ni Won Da Lona L'Ekoo, Nibi Tawon Ajayi Ti N J
 
 
Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Tirela To Ko Opolopo Miliiki Ni Won Da Lona L'Ekoo, Nibi Tawon Ajayi Ti N Ja A Sile N'Ibadan Lowo Ti Te Won

Leyin ti won ti fipa gba oko tirela kan to kun fun miliiki iyefun lagbegbe Berger, l'Ekoo, owo awon agbofinro ijoba ipinle Oyo ti won n pe ni Operation Burst ti te Yemi Ajayi, okan ninu awon adigunjale ohun ti won maa n fipa ja awon oko tirela gba kiri.

Oko eru nla to ni nomba KRD 343 KD to je tileese akeru KK Global Nigeria Limited lo n ko miliiki kurugbe to to egberun meta o le metalelogosan-an lati Eko lo si Ibadan, ti awon obayeje eeyan naa si gba eru towo e to milionu lona ogun naira ohun. Ati eru, ati tirela to gbe e lawon eruuku fibon gba ni nnkan bii aago mesan-an ale Ojobo, Tosde, ojo kokanlelogun, osu kesan-an, odun yii.

Gege b'Iwe Iroyin Yoruba se gbo, mefa lawon adigunjale naa. Aso soja ati aso olopaa ni won wo ti won si duro si oju titi ona Eko s'Ibadan lati le fi tan awon awako ti irin-ajo won je mo ona naa. Bi awako eru yii se de odo won ni won wo o ju sile ti won si gbe oko re sa lo.Sugbon idunnu won ko lo titi nitori ko ju wakati mefa towo awon agbofinro Operation Burst te won n'Ibadan nibi ti awon afurasi ole naa ti n ko awon oja ti won ji pamo sinu ile ikerusi kan laduugbo Oke-Ado. Nigba naa ni won ni asiri obitibiti eru eleru mi-in ti awon jagunlabi ti ji pamo sibe tu sawon agbofinro lowo.

Nigba to n royin isele ohun ati ohun toju e ri lowo awon eeyan naa fakoroyin wa, awako tirela yii, Ogbeni James Amanokhai salaye pe, "Ileese to n je WAPCO ni mo ti ko eru yen ni nnkan bii aago mesan-an ti mo si bere irin-ajo leyin ti mo gba epo disu ti mo maa da sinu oko. Bi mo se koja abe biriiji Berger (l'Ekoo) ti mo n sunmo ibi ina to n dari oko ni mo ri awon okunrin meji kan ti won wo aso olopaa ti won duro si aarin meji oju titi.

"Nibi ti mo ti n duro kawon oko koja ni oko Hilux kan ti nomba e je XD 922 AGL to ni iru ina oko awon panapana lori sare dabuu ona, bee ni mi o ri awon olopaa ti mo n wo lookan mo. Lojiji lawon mefa kan be jade si mi pelu ibon AK 47. Awon merin wo aso soja, awon meji yooku wo aso olopaa. Won n hale mo mi, won ni mo ta omi si moto awon lara.

"Mo be won gan-an, won ko gbo, bi won se wo mi bo sile niyen pelu ekeji mi, ti won gbe wa sinu moto tiwon. Okan ninu awon to woso soja yen ko sinu moto wa, o n wa a, olopaa kan naa jokoo ti i. Awon yooku n wa oko tiwon ti won gbe awa sinu e, won dojuko ona Oworonsoki. Ba a se de iyana Oworo, won pada sona Ibadan. Won ko gbogbo owo apo mi ati foonu ti mo n lo nibi ise. Eyi ti mo n lo funra mi wa ni apo ibadi sokoto ti mo wo, mo waa jokoo le iyen ki won ma baa ri i.

"Nigba ta a de ori biriiji Oworo, won wo wa ju sile latinu moto. Ekeji mi tie n be won pe ki won fun wa ni foonu wa, sugbon won ni abi kawon gbe wa ju sinu odo ni. A ba tun n be won pe ki won maa ko foonu lo, ki won saa ma ju wa sinu odo.

"Leyin ti won lo tan la bere si i fese rin lo sona Obalende, a si debe ni nnkan bii aago kan oru. Nibe ni mo ti pe oga mi, loju-ese ni won ti pe ileese to ta moto fun wa ti awon yen si ti mo ibi ti moto yen de nipase idaabobo to maa n wa lara moto." Nigba to n fidii isele yii mule fawon oniroyin ni olu ileese Operation Burst to wa l'Agodi, Ogagun Laz Ilo ti i se oludari agba iko naa so pe iko ayara-bii-asa ti oga agba ileese ologun orile-ede yii gbe kale ti won n pe ni QRG ni won koko fi isele ohun to leti. Awon yen lo pe awon tawon fi bere ise lori isele naa.


"Bi iroyin se te wa lowo nipa adugbo ti moto yen de lawon eeyan mi ti sare lo sibe ti won si ba won nibi ti won ti n ja eru ti won n ko o wo inu ile lo, iyen je nnkan bii aago meta aabo oru. Nigba tawon eeyan mi wo ibe ni won tun ba awon apo iresi ti won ti ji ko pamo tele. Iresi atawon miliiki pelu moto yen la ti gba, a si mu Ajayi." Ajayi so fawon oniroyin pe oun ko si ninu awon to loo fibon gba eru l'Ekoo, oun kan n ba won seto bi won se maa ko eru eleru naa pamo lasan ni, ati pe obinrin kan ti won n pe ni Alaaja Falilat lo ni in.

Gege bo se so, "Ni nnkan bii aago mefa ale ojo Tosde ( ojo kokanlelogun, osu kesan-an) ni Alaaja Falilat pe mi pe awon ni awon eru kan lati ibi ise, awon n wa ibi ti awon maa ja a si. Mo so fun won pe mo ni ibi kan ti won le renti, won si maa nilo awon ohun irinse keekeekee lati ko awon eru yen kuro lati inu kontena si yara nitori kontena ko le ri ona debe.

"Mo pe ore mi kan to n je Femi pe ko gbe mi loo pade Alaaja ni Too Geeti. Oko to gbe eru yen wa de ni nnkan bii aago mejila oru. Mo so fun Alaaja pe ki won je ka ni suuru di ojo keji ka too ja a, won ni rara, awon fe ka tete ja a kiakia nitori awon ko fe ki won tun maa gbowo lori eru yen.

"Mo loo wa awon to maa n ko eru l'Ogunpa ati awon oko keekeekee ti won n ba wa ko eru lati inu oko lo siwaju ile yen. Nibi ta a ti n ko o lowo ni Alaaja ti pe mi ni nnkan bii aago meta aabo oru pe awon soja atawon olopaa ti wa nibi ti oko eru yen wa. Mo ni ki won saa ma ba won so nnkan kan, ki won je ki n de nitori awon le ma mo nnkan ti won maa so fun won." Okunrin to pera e leni odun marunlelogbon yii fi kun un pe, "Nigba ti mo debe, awon soja bi mi leere pe ta lo ni eru, mo ni Alaaja ni, sugbon mi o ba Alaaja nibe. Mo mu won lo si ibi ti a n ko awon eru si, bi awon soja se mu mi niyen. Mi o mo ile Alaaja, ore mi kan lo mu mi mo won, onisowo ate ni mo si mo won si." Ogagun Ilo gba awon to ba ni moto nimoran lati maa fi idaabobo si ara e ko le ran awon agbofinro lowo nigbakuugba to ba sonu, bee lo seleri lati fa okunrin afurasi-adigunjale naa le awon agbofinro ti yoo sewadii oran naa siwaju lowo.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, June 08 @ 19:57:52 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue:
O Ga O! Awon Olopaa Ati Adigunjale Fibon Para Won Loju Ija Niluu Ibadan: Awon Ol


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue

"Tirela To Ko Opolopo Miliiki Ni Won Da Lona L'Ekoo, Nibi Tawon Ajayi Ti N J" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: