Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin
[ Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin ]

·E Gba Mi Lowo Iyawo Mi o, O Fee So Mi Di Dindinrin Rafiu
·Nibo Ni Isokan Yoruba Yoo Ti Wa?
·TITUBA KURO NIBI ESE (AT-TAWBAH MIN AL-MA'ASIY)
·Kike Alkur'an Ati Awon Eko Re: Alaye Ola (Esan) kike AlKur'an Alaponle
·Kamalat, Omo Odun Mefa To Laisan Okan Ma N Pariwo, O Ni Kawon Omo Naijiria Ran
·IGBEYAWO NINU ISLAM: Itumo Igbeyawo; Kinni Erogba Igbeyawo Ninu Islam?
·Awon ipile meta Esin Islam ati awon Eri won Lati owo Shaikh Muhammad Ibn sulaima
·AKASO ODODO (Al- WASEELAH) - Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi -- Atunyewo
·Alaye lori Aayah (23) ninu Suuratu Furkooni

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Iyawo Ile Ka Oko E Mo Inu Ile Pelu Ale, Lo Ba Binu Dana Sunle Onile L'Osogb
 
 
Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
Lati Owo Florence Babasola, Osogbo

Iyawo Ile Ka Oko E Mo Inu Ile Pelu Ale, Lo Ba Binu Dana Sunle Onile L'Osogbo

Bii omi lawon eeyan se n ya lo si ojule kerin, laduugbo Ajijola Anabi to wa lagbegbe Aderin, nitosi Powerline, niluu Osogbo, lojo kin-in-ni, osu yii, nigba ti won gbo pe obinrin kan dana sun ile olojule mewaa ti oko re renti nitori pe o ka ale mo inu ile pelu oko e.

Ojo ti pe ti oko omobinrin ti ko ti i ju eni odun meeedogbon lo yii ti won n pe ni Gaa Moria ti n ni ife ikoko pelu iyaale ile kan nitosi ile won, sugbon ti Moria ti n so ojo ti yoo gba awon mejeeji lorun owo mu. Lojo ti gbogbo eeyan n se ayeye odun ominira orile-ede Naijiria, esu lowo si oro awon toko-tiyawo ohun, Moria si fee fi ibinu so iya agbalagba to je lanledi ile petesi naa di alainilelori.

Goriola Adedamola to je oko Moria la gbo pe o je olopaa kogberegbe lagbegbe Powerline, o si ti niyawo kan tele ti iyen bimo meta fun un, sugbon nigba ti ede aiyede kan sele laarin won niyen ko awon omo meteeta lo fun Iya Goriola niluu Ibadan.Ni nnkan bii odun meji seyin la gbo pe ise gbe Goriola lo siluu Jos, nipinle Plateau, nibe lo ti salabaapade Moria, nigba ti oro ife si wo laarin awon mejeeji lo fe Moria wa siluu Osogbo, sugbon ko ti i si omo kankan laarin won.

Lojo buruku ti esu gbomi mu lowo Moria yii, se lo ba oko re pelu ale ninu ile. O koko fibinu kolu ale oko re yii, awon mejeeji si jo woyaaja; dipo ki oko-iyawo se bii eni to mo ofin, se lo tun ran ale lowo lati sina iya fun iyawo e.

Nigba tawon mejeeji na an te won lorun, won kuro ninu ile, akoko naa ni Moria ko awon aso to ni ninu ile, o di won sinu baagi kan, o si loo gbe e sodo okunrin kan to n se telo nidojuko yara won. O wonu ile, o ko awon aso oko re jo soju kan ninu palo, o da kerosinni le e lori, o si sana si i. Akoko yii ni oko wonu ile, sugbon kawon mejeeji too mo nnkan to n sele, ina ti ran mo awon nnkan ninu palo, bayii ni eefin so, ti ina si n ran ara won lowo titi ti gbogbo yara meweewa pelu awon ile iyagbe to wa loke petesi naa fi jona tan.

A gbo pe se ni Moria fee maa sa lo nigba to ri i pe ibinu ti ko oun si wahala, sugbon oko re naa lo mu un sile pe oju re gbodo ri nnkan to n wa, ibe naa lawon agbofinro si de ba a ti won si mu un lo sagoo won fun iwadii lori oun to ri lobe to fi waro owo. Gbogbo igbiyanju awon ara adugbo lati pa ina naa lo ja si pabo. Eemeji la gbo pe awon osise panapana gbe omi lo sibe ko too di pe won ri ina naa pa, eleyii ti ko je ko raaye jo de awon yara to wa nisale.

Iwadi fi han pe ohun ti Gaa Moria n tenumo lodo awon olopaa ni pe oko oun ki i toju oun, o n muti, bee ni ki i fi owo ounje sile foun, idi niyi tinu fi bi oun nigba to tun laya lati gbe obinrin mi-in, paapaa, eni to wa nile oko tawon tun jo wa laduugbo wa sinu ile.

Iwe Iroyin Yoruba ba iya agbalagba to je lanledi ile naa soro. Iya yii, Alaaja Safuratu Agboola, eni odun metadinlogorun-un salaye pe odun 2011 ni olopaa kogberegbe yii, iyen Goriola gba yara ati palo kan ninu ile toun ti ko lati nnkan bii ogbon odun seyin yii. Alaaja Safuratu ni, "Inu yara mi yii ni mo wa tawon araadugbo deede n pariwo pe ki n jade ninu ile pe ina ti n jo loke. Awon kan sare wole lati mu mi jade, nigba ti mo gboju soke wo petesi ile mi, se ni mo n pariwo pe kawon eeyan saanu mi.

''Gbogbo yara oke lo ti jona tan, masinni merin lo jona ni soobu telo to gba iwaju yen, gbogbo aso alaso ti won gbe fun un fun odun Ileya lo ti jona mole patapata.

''Mo ti di agbalagba, ko sibi ti mo ti fee ri owo tun ile yii se bayii, mo ro ijoba ipinle Osun labe Gomina Aregbesola lati dide iranlowo fun mi, bakan naa ni ki awon araalu ran mi lowo.


''Ojo nla kan ro leyin isele yii to je pe gbogbo awa ti a n gbe isale ni ko le sun lojo naa nitori pe se ni agbara ojo n ya sinu yaara wa lati oke. E wo gbogbo ara ogiri, o ti n di alapa, ko sibi ti mo fee lo, kijoba dakun ran mi lowo." Ni bayii, Moria ti wa ni ago awon olopaa to n wadii iwa odaran niluu Osogbo, bee la gbo pe awon ojulumo ati ore Goriola ti n wa ona lati yanju oro naa nitubi-inubi nitori ise ti okunrin naa n se.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, June 08 @ 21:43:56 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga:
O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: B


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

"Iyawo Ile Ka Oko E Mo Inu Ile Pelu Ale, Lo Ba Binu Dana Sunle Onile L'Osogb" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: