Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
[ Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga ]

·Eyi Ni Bi Enu Se Ko Ba Bobrisky, Okunrin To N Se Bii Obirin: Won Ni Awon Olopa D
·O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
·Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
·Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
·Owo Te Wahab Nibi To n Ti n Se'Kinni' Fomo Odun Mewaa Legbee Ogiri
·Mumini Lu Magun Lara Iyawo Oloye Ilu n'Iyana-Offa
·Imeh Ha Sowo Olopaa L'Ekoo, Aburo Iyawo e Lo Se Kinni un Fun
·Aliyu Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po n'Ilorin, Lo Ba Doyun
·Adebowale Atawon Egbe e Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Oro Ooni Ati Alaafin (Ta Ni Yoruba Gan-an?)
 
 
Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Oro Ooni Ati Alaafin (Ta Ni Yoruba Gan-an?)


Ninu awon iwe ti mo gba lose to koja yii, okan wa nibe to kan mi kuu. Ohun to wa nibe niyi: “Baba, ajinde ara ko maa je. E jowo, awa merin kan wa ti a maa n jokoo po ka oro yin ninu Iwe Iroyin Yoruba losoose. Enikan ninu wa yoo ka oro naa, a oo si bere si i se atupale le e lori. Awa mereerin yii, oluko agba ni wa ni yunifasiti, awon meji ni purofeso ninu wa, awa meji to ku si powo le won. Oro Ooni ati Alaafin ti e bere yii, oro nla ni o, o see se ko je ohun ti yoo yanju wahala ile Yoruba gan-an le gbenu le yii. Sugbon e ma bere nibi ti e ti fee bere yen, ki i se ohun to fa ija Ooni ati Alaafin ni ki e fi bere. E jowo, Baba, e so fun wa, ta ni Yoruba gan-an? Nibo ni won ti wa? Ta lomo oko, ta lomo ale? Leyin eyi ni ki e too soro ija.

Bi bee ko, e o kan gbe oro naa lori ni, ko si ni i mu iyanju kankan wa. E seun sa. E jowo, e ma daruko mi ati nomba mi, nitori oro ki i ye awon eeyan wa boro, eyi ti mo ko ranse si yin lojosi ko wahala gidi ba mi.” Mo mi kanle nigba ti mo gba leta yii, nitori nigba tawon ojogbon bayii ba soro, afi keeyan tele e. Sugbon ohun ti won n beere lowo mi yii, bii igba teeyan fee so itan gbogbo Yoruba ni, ise nla si ni. Bee ni tododo, bi a ko ba tu oro naa de isale, ki kaluku mo ara re, a oo kan maa se e lasan ni. Eyi lo je ki n gba lati gbiyanju oro naa, ti mo si bere si i fi oro lo awon oniwadii, awon onkowe ati awon ore mi. Won ti da orisiirisii iwe jo fun mi, n ko si ro pe mo sise mi-in lati ojo Isegun to koja ju ise kika lo.Mo dupe lowo aburo wa, Iwe Iroyin Yoruba, pupo, n ko mo pe ogbon ati imo omokunrin naa to bee, loooto mo mo pe o logbon lori. O so awon kinni kan fun mi ti n ko gbo ri, nigba ti mo si ye awon oro naa wo, mo ri i pe ododo ni. Mo dupe lowo ore mi oga yunifasiti Ibadan nigba kan, ati gbogbo eyin ti e fi ise iwadii orisiirisii ranse si mi.
Oro itan naa le gba wa ni akoko die, sugbon e je ka fi i pamo, ko le wulo fawon omo wa paapaa lojo iwaju. A ko kuku mo eni ti yoo pari ija, ti yoo ko Yoruba de ile ileri, ohun ti a n se ni lati la ona ti yoo see to kale, ki eni ti Olorun ba yan ninu wa le ri ohun mu lo nigba ti ise naa ba ya. Se e ri ohun to sele si Yoruba, ko yato sohun to sele sawon Hausa o. Awon eeyan bii Yakubu Gowon, Ibrahim Babangida, T.Y Danjuma, Sani Abacha atawon bee ti won ti se olori ile wa lati ile Hausa ki i se omo Hausa, bee ni won ki i se Fulani, otooto eya ni won ti wa. Oto ni Hausa, oto ni Gambari, oto ni Nupe, oto ni Kanuri, oto ni Hukuhuku ati bee bee lo.

Sugbon nigba ti Uthman Dan Fodio de lo fi ogun gba gbogbo ijoba ile naa, o si fi awon omo re se olori won, awon ni won si n joba nibe titi doni. Bi ti Yoruba naa ti ri gan-an niyen, o kan po ju ti ile Hausa lo ni.

Ki Oduduwa too de sibi ti a n pe ni ile Yoruba loni-in ni Ife ti wa, Ekiti wa, Ondo wa, Ugbo wa, Ikale wa, Akoko wa, Oba wa, Okun wa, Ijesa wa, Egba wa, Ijebu wa, Awori wa, Edo wa, Tapa wa atawon Egun, Yewa. E oo ri i pe n ko daruko Owu, n ko daruko Oyo, n ko daruko Ibadan, n ko daruko Osogbo, Ede atawon ilu Origbo mejeeje, awon ilu wonyi ko si ki Oduduwa too de. Oro n bo nibe yen bo ba ya. Bawo ni mo se mo pe awon ilu wonyi ti wa tele? Eleyii ko le rara: ede won ni. Gbogbo awon ilu wonyi ni ede won yato si ara won, ajoji ni won si je si ara won pelu, nitori oruko otooto ni won n pe awon nnkan won, nigba ti Oduduwa (tabi Yoruba) ati awon eeyan re de, ti won fi ogun gba awon ile wonyi, ti won joba le won lori ni ede Yoruba di ohun ti gbogbo won n so.

Ki lo fa a ti ede won yato? Bi eeyan ba fee modi eyi, yoo lo sinu awon iwe itan aye to dara to si tun pe nni, iyen Bibeli ati Kuraani. Bibeli so pe igba kan wa ti awon omo eeyan gbiyanju lati ko ile giga lati ile de orun, Olorun so fawon angeli re pe awon eeyan fee mo ile kan orun, ati pe bi won ba ti wa ni isokan lori ohunkohun, won yoo se kinni naa. Awon angeli re si beere pe bawo ni won se le tu won ka, Olorun ni ki won da won lede ru ni, bee ni won da won lede ru, ti kaluku si n so ede otooto, ti awon ti won n so ede kan naa si jo n se po, ti won jo n lo. Nigba naa ni oro ti di pe a ko le fokan tan eni ti a ko ba gbo ede re, awon ti won n so ede kan naa ni won n pe ni eya kan naa. Olorun si so ninu Kuraani pe: Ijo kan naa ni gbogbo aye tele, awon (Olorun) lawon fon won ka; bee lo so nibomi-in pe: Bo ba se pe Olorun fe ni, ijo kan naa ni gbogbo aye iba je. Idi niyi ti ede Yoruba fi yato si ti Ibo ati Hausa, ti ede geesi yato si ti Jamani ati Faranse, ti ede Larubawa si yato si ti India ati Saina.

Ni ti ile Yourba, awon ede naa yato nitori pe lara awon ti Olorun da ni ibere aye naa ni Yoruba i se. Awon eya wonyi si ti n se aye won ko too di pe Oduduwa de: Oduduwa ati awon omo re si ni Yoruba, awon ni won ni ede ti a n so. Isoro wa ninu itan nibi ti won ti wa gan-an ni. Awon kan ni won n ro dirodiro bo lati ode orun ni, ori oke Ora, n’Ileefe ni won si so kale si. Eleyii le ma ri bee, nitori ilu kan ti wa nibe tele, ohun to see se ni ko je pe awon eeyan naa n rin bo lati ona jinjin, nigba ti won si gun ori-oke yii lati ibi ti won ti n bo, gbogbo won n wo ilu kan loookan ni, won si bere si i so kale lati ibe lo. Awon ti won so pe won rubo, won fi adie kan sile, won si ni ko tan ile ibe, lara asa Yoruba ni, ni gbogbo ibi ti Yoruba ba ti de ni won n setutu, niwon igba ti Orunmila si ti wa laarin awon ti won de naa, irubo ko se ajoji si won rara.

Sugbon kinni kan to fese mule daadaa ni pe awon Oduduwa ba awon eeyan ni Ileefe, ati pe nigba ti wo debe, Oduduwa atawon eeyan re ba awon ti won wa nibe jagun, won si bori won. Awon ti won so pe won ro wa lati orun fowo si eyi, won ni ija de laarin awon atawon eeyan Obatala, awon ti won so pe won n rin bo lati ibi kan naa so pe nigba ti won debe, awon ti won ba nibe gbogun ti won, gbogbo eyi si je ko daju pe nigba ti Oduduwa de ilu yii, ija lo ja to fi so ara re di oba won. Sugbon eleyii ki i se tuntun o, bi ile aye ti se ri nigba naa niyen, awon jagunjagun ni won n gba ilu kaakiri, eni to ba si lagbara ju ni yoo di olori, ti awon omo re yoo si maa joba lo. Ija naa ni awon Juu atawon Larubawa n ja lati ojo yii wa, ija naa lo wa nile ti ko tan to bi iru awon eeyan bii Osama Bin Laden atawon afemi-sofo bii Boko Haraamu, ija ati ojo yii wa ni, ija ka gbale onile ka si so ara wa di oba le won lori ni. Oro ojo iwaju niyen.

Sugbon nibo ni Oduduwa atawon omo re ti wa? Se Larubawa ni won ni abi ara Meka? Se Oranyan tele won de Ileefe ni abi ni Ileefe ni won ti bi i? Sebi ohun to n fa idi ija ile Yoruba loni-in niyen. N oo salaye abo iwadii temi ati ohun ti ogbon ori ati laakaye mi fi ye mi fun yin lose to n bo. O da mi loju gbangba pe bi a ba mo itan wa, ti a mo idi ti a se n ja, ti a si mo bi Yoruba ti je gan-an, lati ni asaaju ko ni i le, lati ni idagbasoke paapaa yoo rorun. E je ka maa ba alaye oro naa bo. E seun, mo dupe lowo yin o. A oo pade lose to n bo.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, June 08 @ 21:53:41 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· EsinIslam Media Yoruba
· Ekunrere Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere:
Oye Okere Tilu Saki, Ile-ejo Ni Mogaji Ko Gbodo Gbe Igbese Kankan Bayii


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere

"Oro Ooni Ati Alaafin (Ta Ni Yoruba Gan-an?)" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: