Gbagede Yoruba
 



Grace Ati Onobong To Gunra Won Nitori Okunrin Ti Foju Bale-ejo
 
Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo
Lati Owo Olowoake Latifat

Grace Ati Onobong To Gunra Won Nitori Okunrin Ti Foju Bale-ejo

Awon obinrin meji ti won koju ija sira won nitori oro okunrin, ti ikan si gun ekeji re nigo ti foju bale-ejo bayii. Onobong Lucky, eni odun merinlelogbon ati Grace Akpan, eni odun mejidinlogbon nigba oran naa si mo lori, leyii to so awon mejeeji deni ti n jejo niwaju Adajo Tanimola to wa nile-ejo Majisreeti Yaba lose to koja. Esun ti won fi kan won ni pe won da omi alaafia adugbo Olorunfunmi, l'Oworoshonki, l'Ekoo, ru lasiko tawon mejeeji fija peeta nitori oro omokunrin ti won jo n fe.

Ninu oro agbenuso olopaa lori oro naa, Inspekito Rita Momoh, o ni Onobong ati Grace kolu ara won lojo keji, osu kewaa, odun to koja, ni bia palo kan to je ti Ogbeni Akpan, iyen lakooko tomokunrin to je oko afesona awon mejeeji wa nile oti yii pelu Grace ti won jo n je igbadun.



Afi bi Onobong se de sibe, ti ko si se meni meji to fi kolu alaba-pin-oko e yii pelu obe ti won lo fi gun un loju.
Sugbon ki oro Grace ma waa da bii eni tobinrin egbe e pa layo loju oko afesona won ohun ni won lo fa a toun naa fi fo nnkan mo Onobong lori, tija si di rannto laarin won ko too di pe awon eeyan la won. Leyin naa ni won fa won le awon olopaa to wa nitosi ibe lowo, latibe naa ni won ti taari won sile-ejo tigbeejo ti n waye lowo bayii.

Esun mereerin ti won fi kan awon olujejo yii ti won so pe awon ko jebi re rara ni Momoh so pe o tako abala ketalelogorin (83) ati igba o le mokandinlaaadota (249) tiwe ofin iwa odaran tilu Eko, todun 2011, bee lo nijiya ninu pelu.

Ninu idajo re, Adajo M.O. Tanimola faaye beeli egberun lona aadota naira sile fun won pelu oniduuro meji niye owo kan naa. Bee lo ni igbejo yoo maa tesiwaju lojo kerindinlogbon, osu kewaa, odun yii.


 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, June 25 @ 23:35:16 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam



Comments 💬 التعليقات
 

For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا

Awọn ọna asopọ ti o jọmọ

· Die sii Nipa Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo
· Iroyin Nipasẹ MediaYorubaTeam


Ọpọlọpọ Itan Ka Nipa Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo:
Yoruba Greetings, (Middle) Names In Yoruba Language With Titles Of Obas (Kings)


Iwọn Abala

Apapọ Dimegilio: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

Jọ̀wọ́ Gba Ẹ̀ẹ̀kejI ki o sI dIbo fun Abala YIi:

O tayọ
O dara pupọ
O dara
Deede
Buburu


Aṣayan


 Ọrẹ-itẹwe Ọrẹ-itẹwe





Akole Atoka Agbo-Oro

Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo



"Grace Ati Onobong To Gunra Won Nitori Okunrin Ti Foju Bale-ejo" | Buwolu wọle/Ṣẹda Eto Akọsilẹ | 0 Awon Alaiye


Awọn asọye jẹ Ohun ini nipasẹ Iwe ifiweranṣẹ. A Ko Lodidi Fun Akoonu wọn. Nibayi, A Pe Awọn oluka lati jabo Eyikeyi Abusive, Unsuitable And/tabi Islamophobic Content



Ko si awọn ọrọIwoye Ti o gba laaye Fun Aisinisi, Jọwọ Forukọsilẹ
 

Gbagede Yoruba
Akọọlẹ Tirẹ
Ojule Akọkọ  | Awọn Itan Yoruba  | Gbagede Yoruba  | Ifiranṣẹ Ara-ẹni  | Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba  | Koko Mẹwa  | Ẹka Abule  | Ifirohin-Ransẹ  | Iwadi  | Agbeyẹwo  | Ifimufilẹ  | Iwe Akọọlẹ  | Apoti Akọsilẹ  | Isopọ Ọpọnlujara  | Ẹgba Ayelujara  | Ipolongo Wa


Ẹsin Islam الدين الإسلامي Religion of Islam Addinin Musulunci Agama Islam Religión del Islam 伊斯兰教 Dini ya Kiislamu Религия Ислам Religião do Islã イスラム教 Esin Islam 이슬람의 종교 Portal African Muslim Website - Arabic English African Islamic Website For World News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Articles, Radio, Audio, Video, Quran, Hadith, TV Channels, Fatwas, Muslim News, Newspapers, Magazines Headlines, Forums, College, Schools, Universities, Mosques, Quranic, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Ramadan, Vidoes, Books, Fasting, PDFs On EsinIslam.Com And IslamAfrica.Com