Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
[ Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo ]

·E Waa Wo Simia To Pa Oree Re L'Osogbo o
·Nitori Foonu, Baale Ile Meji Jabo Sinu Konga, Loju Ese Ni Won Ku
·Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
·Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
·O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
·Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
·Grace Atale Re Pa Oko e N'Iyana-Ipaja
·Oro o, Iku Gbigbona Leleyi o! Nibi Ti Johnson Ti n Taja Loju Titi L'Akure N
·O Ma Se O! Dauda To n Tun Redio Se Gan Mona L'Osogbo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Kayeefi nla! Ebenezer Kun Iyawo E Bii Eran l’Akure, Gbogbo Eya Ara E Lo Yo
 
 
Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo Lati Owo Solomon Adewoye, Akure
Kayeefi Nla! Ebenezer Kun Iyawo E Bii Eran l’Akure, Gbogbo Eya Ara E Lo Yo

Ninu aye ta a wa yii ni baba ti n fomo re soogun owo, tiyawo si n so oko di dindinrin, bee loko mi-in n fiyawo e seso, gbogbo e, nitori faaji aye yii naa ni. Sugbon ki lo le mu ki okunrin to lowo lowo, to kole, to si niyawo gidi to n ran an lowo ni gbogbo igba sadeede mu iyawo re lojo kan, to si kun un bii eni kun ewure lati fi soogun owo, kayeefi nla gbaa ni o jare! Ohun to sele lose to koja si idile okunrin kan ti won n pe ni Ebenezer Eleso, omo bibi ilu Akure niyen. Eni ogoji odun ni okunrin yii, ise riwaya lo n se, o si tun n se ise awako taksi pelu. Adugbo Similoluwa Estate loun ati iyawo e, Adesola Eleso n gbe ni ile kan ti won n pe ni Fine Boy House.

Gege bi Iwe Irohin Yoruba se gbo, ko sija laarin awon mejeeji, koda obinrin naa, eni odun marundinlogbon ti bimo meji fun un, okunrin lawon mejeeji< okan n je Oluwole, omo odun mewaa, ekeji si n je Emmanuel, omo odun merin. Adesola ti loyun iketa sinu kisele laabi yii too de ba a.Awon toro naa soju won so fakoroyin wa pe nise ni Ebenezer ran awon ore e ki won loo pa iyawo re lati fi soogun owo ni nnkan bii aago mejila osan ojo Aje, Monde to koja lohun-un. Ki i se pe won pa Adesola nikan o, won tun yo eyinju re mejeeji, won la ikun re, won si gbe omo tuntun ti ko i bi to wa ninu e jade, koda nise ni won tun fa irun abe re ti won si ge oyan re mejeeji lo. Awon araadugbo naa ni pabanbari re ni pe leyin tawon ore Ebenezer se eyi tan ni won sese waa da epo kerosinni si i lara, ti won si dana si i lara ati inu ile ti won pa a si.

Iwadii akoroyin wa fi han pe se lawon eniyan naa tete se ise ohun paapaapaa, bi won sise ibi naa tan ni won da oju re dele ki awon eeyan araadugbo ma baa mo ohun to n sele. Kete ti won dana sinu ile naa tan lawon ara adugbo ri eefin, iyen lo mu ki won tete lo sinu yara ohun lati pana to n jo, sugbon won ko mo pe awon asebi naa ti se awon ise ibi kan sara Adesola, iyawo Ebenezer. Ohun ti Ebenezer si n tenumo fawon araadugbo ni pe ina lo pa iyawo oun, o si lojo naa loun yoo sinku e.

Awon molebi Adesola salaye fun akoroyin wa pe nise ni Ebenezer fi omo awon soogun owo nitori gbogbo molebi lo fee fi oju ri oku omo naa sugbon o ko jale lati je ki awon molebi ri oku omo won. Irole ojo naa lo sinku iyawo re sinu ile to n ko lowo, posi olowo iyebiye lo si ra to fi sinku e. Odaran oko Adesola yii atawon ore e pelu egbon re kan ti won n pe ni pasito, Ogbeni Bunmi Eleso ni won jo loo sinku Adesola lai je kawon molebi iyawo foju ri oku omo won.

Kayeefi to wa ninu oro yii ni pe bi won ti ko oro naa de odo awon olopaa, nise ni iya iyawo atawon molebi to ti n leri tele so pe awon ko sejo mo ati pe ina lo jo omo awon, ki i se pe won fi setutu, bee niya iyawo si tun san egberun mokanla lati gba beeli oko omo e lojo keji isele naa. Bo tile je pe eyi ko dun mo awon idile baba iyawo ninu, won dide soro naa, okan ninu awon idile baba oloogbe yii to je olopaa kogbereegbe (Mopol) niluu Abuja sugbon to waa lo isinmi e l’Akure lo gbo soro naa to si tun loo fi olopaa mu Ebenezer lojo keta isele buruku yii.

Ohun ti a gbo ni pe olopaa Abuja yii ti won pe ni Rotimi kan an nipa pe awon fee fi oju ri oku Adesola, eyi lo mu ki won lo sibi ti won sin oku naa si lojo Satide pelu dokita kan atawon asoju lati idile mejeeji. Nibe gan-an lasiiri ti tu. Bi won ti hu oku Adesola sita, won ba obi abata alawe meta loju re mejeeji, won ri aso pupa ti won fi we oju oyan re mejeeji ti won ti ge kuro, won tun ri ikun re ti won la ti won si ti ko gbogbo ifun re jade pelu omo inu re.

Poroporo lomi bere si i bo loju awon to foju kan oku obinrin naa, ohun kan soso to si n ti enu Ebenezer, oko iyawo jade leti iboji ni pe ki gbogbo eeyan saa maa ba oun gbadura pe ki asiiri awon to sise naa tu sita lai pe lai jinna, nitori oun ko mo nnkan nipa oro naa. Bo ti n soro naa jade lenu lawon to wa nibe n bi i pe bi ko ba tile mo nipa e, ki lo de to fi n kanju to si sare sinku iyawo re lai je ki enikeni mo ju awon ore e, kin nidii ti ko fi pariwo sita fawon eeyan lati waa wo ohun toju e ri. N lawon eeyan naa ba kuku so o pe dajudaju, Ebenezer yii mo nipa iku iyawo re, o kan n dibon ni.

Bakan naa lawon olugbe agbegbe naa atawon to n gbe ile ti iya iyawo ko si agbegbe Ayedun, niluu Akure soro. Ohun ti gbogbo won so ni pe iwa Ebenezer fihan pe o le se ise naa nitori amugbo eeyan ni, bee lo tun je toogi, won ni ki i se iru iyawo e ni isele naa to si nitori awon ohun meremere ti iya iyawo re ti gbe se laye re. Won salaye pe iya iyawo re to pa lo ra moto to n lo fun un, oun lo ra ile to si ko ile fun un, koda won ni osu yii ni iya naa fee kan ile naa fun won. Ohun lo n gba owo ile ti iya naa ko si Ayedun. Gbogbo aye ni iya naa ti gbe le e lowo to fi mo awon ohun-ini e.

Ninu oro agbenuso awon olopaa nipinle Ondo, Adeniran Aremu, o so pe loooto nisele naa sele ati pe okunrin naa ko ni pee foju ba ile-ejo fun esun ipaniyan.

Lowolowo yii, Ebenezer ati baba e to fi mo awon ore e bii merin si wa latimole awon olopaa.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Wednesday, June 25 @ 23:46:23 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo:
Agbonrin abami ran pasito lo sorun apapandodo l'Okeigbo


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo

"Kayeefi nla! Ebenezer Kun Iyawo E Bii Eran l’Akure, Gbogbo Eya Ara E Lo Yo" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: