Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
[ Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin ]

·Gbogbo Musulumi Jakejado Orileede Naijiriya Ni Babayemi Gba Niyanju Lati Se Awok
·Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Ikolu Awon South Africa Si Naijiria - Ekunrere
·Xenophobia (Ikorira-Ajeji) Attack: Awon Omo Naijiria Ti Yari Pe Awon Naa Yo Gbes
·Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
·Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
·Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
·Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
·Eru n Bawon Ara Mushin Nitori Oriyomi Ti Won Dajo Iku Fun
·Aafaa Wo Gau N'Ijare, Orebinrin Re Lo Seyun Fun, Niyen Ba Gbabe Ku

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Azeez Yii Ma Buru O: O Pa Iya Ati Omo Leyin To Ta Ile Re Ni Milionu Lona Irinwo
 
 
Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
Lati Owo Soyemi Oluyinka ati Adeola Alabi-Oloye

Azeez Yii Ma Buru O: O Pa Iya Ati Omo Leyin To Ta Ile Re Ni Milionu Lona Irinwo Naira

Iroyin kan lo gba ilu Eko kan lojo Abameta, Satide, to koja yii pe won tun ti ri ajaale lagbegbe Ajuwon, won si ti n ri orisiirisii oku nibe, eyi to fa ipaya fawon eeyan. Eyi lo mu Iwe Iroyin Yoruba gba adugbo ohun lo, nibe si lasiiri ohun to sele gan-an ti tu si wa lowo. Awon olopaa to n gbogun ti iwa idigunjale (SARS) n’Ikeja, niluu Eko, lo sawari oku arabinrin eni odun merinlelogota to je oga asobode (Custom) nigba kan, Angela Uzo Kery, ati omo re to je omo odun mewaa, Obiagulum, ti aafaa kan pa laipe yii nibe nitori to ta awon nnkan ini re.

Gege bi iroyin to te Iwe Iroyin Yoruba lowo se fi han, okunrin afurasi onijibiti kan, Alaaji Olatunji Azeez, lo pa obinrin oga asobode ohun atomo e leyin to ta awon ile re ni iye to le daadaa ni milionu lona oodunrun naira. Ile ti okunrin naa sese ra lojule keje, lagbegbe Wadoye, Pipeline, l’Ajuwon, lo sin awon eeyan naa si, bee ni awon olopaa ti ti i pa, ti won si ko ‘Ile adigunjale ati apaayan’ sara re lati fi le awon eeyan sa nibe, bee ni won ko fi adugbo naa sile rara.Owo awon olopaa tesan to wa ni Oko Oba, ni Area G Division, l’Ekoo, te Azeez atawon isomogbe re meji leyin ti iwadii fi han pe o lowo ninu iku oloogbe ohun. Bo tile je pe afurasi yii seleri lati fun awon agbofinro ohun ni milionu mesan-an naira lati mu ki won doju iwadii won bole, sibe awon eeyan naa ko o.

Nigba ti won n foro wa a lenu wo, Azeez jewo pe nise loun tan obinrin naa pe ariran loun, ati pe awon molebi fee gba awon ohun ini re lowo re. Oni ki oloogbe ohun ko awon iwe ile re wa koun le gbadura si i, bee niyen si se. Adugbo tawon ile yii wa ni Omole, Oko Oba ati Ajah, bakan naa lo ta won ni milionu lona marundinlogorin naira, milionu lona ogofa ati milionu lona aadofa naira, eyi ti apapo re je milionu lona irinwo din meeedogbon naira.

Lasiko tawon olopaa beere ibi to toju awon eeyan naa si lo seleri owo fun won, sugbon awon yen ni ko ma seyonu, bo ba ti le jewo, awon yoo fowosowopo pelu re. Nigba naa lo jewo nipa awon ise ibi to se ohun, ati pe nnkan to je koun pa omo obinrin naa ni pe o mo nipa asiri oro ohun.

Ohun to tile je ki awon olopaa bere iwadii yii ni pe aburo oloogbe loo so nibe pe awon ko ri egbon awon, oun lo si so asiko to ti jade, ibi to lo, iyen Sanngo, nipinle Ogun, lati loo gbadura, ati oko Toyota Camry ti nomba re je LND 554 A2 to gbe jade. Ohun aabo to maa n wa ninu moto (tracking device) lo satona won debi toko naa wa, iyen ile akoku kan ni Alakuko, ibe lowo si ti te Ahmed Sholotan ati Waliu Akiniyi ti won je alabaasisepo Alaaji Azeez.

Akiniyi lo so fun won pe Sholotan lo gbe oko naa foun lati toju re titi tawon yoo fi ri onibaara fun un, oun lo si se atona bowo se te Azeez to gbe oko fun un, ko too di pe asiri iku obinrin yii atomo e tu.

Nigba ti oniroyin wa pe agbenuso ileese olopaa, DSP Ngozi Braide, o ni loooto nisele naa sele, ati pe awon ti taari re sodo awon olopaa to n ri soro idigunjale nipinle Eko (SARS) fun iwadii siwaju si i.

Aaro ojo Abameta, Satide, to koja yii niroyin naa gba igboro pe won ti ri ajaale niluu Eko, nigba tawon oniroyin wa si debe la ri i pe ile kan ti afurasi yii ra si adugbo ohun, lo tan awon oloogbe lo, to pa won, to si sin won sinu ile ohun. Awon oku naa lawon olopaa loo hu lojo Eti, Fraide, to koja, ti won si yi gbogbo ile naa po.

Olopaa kan to ba wa soro to ni ka ma daruko oun ni oun ko le silekun ile naa fun wa, o ni lati SARS Ikeja lawon ti waa ti i, bee loun ko le so ju bee.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, June 26 @ 00:02:24 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise:
Orin Ewi ni Yoruba - Yoruba Poems: Awon Owe Yoruba Proverbs Alo Oro


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise

"Azeez Yii Ma Buru O: O Pa Iya Ati Omo Leyin To Ta Ile Re Ni Milionu Lona Irinwo " | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: