Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose
[ Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose ]

·Won Ni Akeem Pa Sajenti Opeyemi Iyawo Re, O Ti N Se Faaji Lewon Bayi
·Eyi Ni Bi Pasito Se Gbe Majele Je Ni Ipinle-Ogun
·Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
·Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
·Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
·Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
·Orekunrin Bukola Fee Fi i Soogun Owo N'Ibadan
·Nitori Wahala Ojoojumo, Igbeyawo Odun Mefa Tuka L'Osogbo
·Won Ti Ran Oga Ileewe To Fipa Ba Akekoo Re Lo Po Lewon Odun Mewaa L'Ekiti

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Bi Sanusi Lamido Sanusi Ti Papa Di Oba Ilu Kano Lehin Awuyewuye Ati Ijaagboro
 
 
Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
Lati Owo Ademola Adejare

Bi Sanusi Lamido Sanusi Ti Papa Di Oba Ilu Kano Lehin Awuyewuye Ati Ijaagboro

Bi ko ba je pe awon olopaa tete ni, ti won si ti mura sile sepesepe, ohun ti yoo baje niluu Kano ko ni i se e fenuso, nitori oba tuntun ti won je nibe. Lesekese ti won kede oruko Alaaji Sanusi Lamido Sanusi gege bii oba tuntun ti yoo je niluu naa ni nnkan ti sele, ti awon odo si gbegi, ti awon kan si bere si i ba dukia ati ohun-ini je, ti awon kan paapaa n dana soju titi kaakiri. Titi di osan ana ni awon olopaa ati soja si n yi gbogbo ilu naa po, ti won n le awon omo to n parojo ti won n fee maa ba ijaagboro naa lo danu, ti won si n kilo fun olomo pe ko toju omo won.

Se lojo Eti, ojo Jimo, ojo kefa, osu kejo odun 2014 yii ni Alaaji Ado Bayero, Oba ilu Kano tele waja, eni odun metalelogorin ni ki iku too mu un lo, nitori ni ojo keeedogbon, osu keje, odun 1930 ni won bi i. Ninu odun to lo laye yii, odun mokanlelaaadota nibe lo fi joba, osu kewaa, odun 1963 ni won ti we lawani oye fun un, omo Fulani ponbele si ni. Omo Abdullahi Bayero ni, baba re si ti joba fun odun metadinlogbon ko too ku. Bi baba re ti ku ni won mu egbon re to n je Sanusi, iyen akobi baba won, pe ko joba, odun mewaaa loun si lo ti won fi le e loye. Igba naa ni won fi Ado Bayero si i, leyin to ti se ise olopaa, to si se asoju Naijiria ni Senegal. Bayero naa lo ku yii o.Ohun to waa fa ija igboro ni pe oto ni eni ti awon ti ro pe yoo di oba ilu naa, Alaaji Aminu Sanusi Ado Bayero ni won ti ro pe awon afobaje mu, awon kan si ti gbe iroyin naa jade pe oun ni won mu, nitori oun ni akobi Oba to waja, iyen Alaaji Ado Bayero, ati pe gege bii asa won lohun-un, akobi omo to ba je okunrin bee ni yoo joba leyin baba won. Eyi ni ko se ya won lenu nigba ti won gbo ikede naa, ti awon eeyan si ti n jo ni aafin ati ayika re. Sugbon nigba ti won waa gbo pe ki i se okunrin naa ni won pada mu mo, ti won si kede oruko oga agba ile ifowopamo Naijiria tele yii, oro naa di ijaagboro lesekese ni. Lati itosi aafin ni won ti bere, won si ja ija naa titi de adugbo Fagge, won de Soron Diki, won de Kuramawa, Gwale, Kofar Nassarawa ati Chrianchi. Bi won ti n dana kiri adugbo, bee ni won n korin, "Baa ma so, Baa ma so", iyen ni pe awon ko gba, awon ko fe, awon ko gba Sanusi Lamido Sanusi ni oba won. Sugbon awon olopaa tete da si oro, bee ni ijoba naa si n salaye pe ko si ohun meji to je ki awon yan Lamido Sanusi ju pe oun ni awon afobaje fa kale lo, bee ohun ti awon afobaje yii si ro papo ni pe ninu awon ti won n du ipo naa, Sanusi lo kun oju osuwon ju, oun lo kawe ju lo, to ni iriri to po ju, to si gbajumo kari aye.

Sugbon awon ti oro soju re ko gba bee, won ni awon asaaju egbe APC ti won wa siluu naa, ti won si duro ti gomina ibe, Rabiu Kwankwaso lorun lati igba ti Ado Bayero ti ku, titi di igba ti won kede oba tuntun naa, lo wa nidii oro naa, awon ni won ko si gomina naa lemi-in, ti won ko si je ko se ohun ti awon ara Kano fe, nigba to se pe omo egbe won loun naa n se.

Asaaju Bola Ahmed Tinubu lo saaju awon olori egbe APC lo sodo gomina yii, won ni awon waa ba a kedun iku Ado Bayero, sugbon bi won se debe ni won ko lo mo, Kano ni won sun, won ko si kuro ni odo gomina ohun titi ti won fi kede pe Sanusi loba Kano. Awon ti won tun tele Tinubu lo ni Nuhu Ribadu, Nasir El-Rufai, awon asofin agba meji, Danjuma Goje ati Bukola Saraki, awon gomina meta, Rotimi Amaechi lati Rivers, Aliyu Wamakko lati Sokoto ati Ahmed AbduFatah lati Kwara. Bi awon wonyi ti de Kano ni won loo ki Gomina Kwankwaso, won si sare jade lati loo ba Sanusi se ipade repete. Leyin naa ni won pada waa ba gomina, ibe ni won si so eru kale si, won si wa nibe titi ti won fi kede pe Sanusi Lamido Sanusi loba. Iyen lawon PDP se binu, won ni APC gbe oselu wo inu eto oba jije ni Kano, sugbon El-Rufai so pe awon omo Jonathan lo n binu yen, won si le binu ko somi.

Bee bi a ba ti yowo asa ilu Kano to so pe akobi omo oba won ni won n fi joba kuro, Sanusi Lamido Sanusi to joba yii ki i se eeyan yepere laaye ara tire naa. Oun naa kawe o gboye, o si tun kawe nipa esin Islamu daadaa. Orile-ede Sudan lo si ti lo si yunifasiti, ko too tun lo si Ahmadu Bello ni Zaria. Ojo ketalelogbon, osu keje, odun 1961 ni won bi i, sugbon lati 1985 lo ti n sise ni banki, o si sise naa titi to fi di oga pata ni banki apapo ile wa. Ipo naa lo wa ki ija too de laarin oun ati Aare Goodluck Jonathan, ti won si yo o kuro nipo naa ni bii osu meta seyin. Ohun ti awon kan fi n so pe bi a ba ti yowo oro asa kuro, Sanusi ni ipo oba naa to si niyen.

Ki i se pe Sanusi sese n mura fun oye naa paapaa, o ti n mura tipe, afi bi igba to mo pe Ado Bayero ko ni i pee ku mo. Ni gbogbo igba to fi wa ni ileefowopamo Central Bank ile wa, ko si igba ti ki i fi owo nla ranse si Kano, bo ba si ti gbo pe awon Boko Haram, tabi kinni kan sele ni Kano yii tabi agbegbe re, yoo seto bi won yoo se ko owo banki naa fun won lati fi ran won lowo, igba kan wa to si fun won ni ogorun-un milionu leekan. Ati pe oun ati Kwankwaso to n se gomina bayii ni ija tele, sugbon lasiko naa lo pari ija pelu re, awon eeyan bii El-Rufai ati Tinubu ni won si se e ti won fi tun dore ara won. Oro ti akowe ijoba ipinle Kano so ko po. Nigba ti awon afobaje mereerin to wa ni Kano yi i ka, okunrin naa jako kehe, o si kede bayii pe, "Inu mi dun lati so fun yin pe ninu awon meta ti won n du ipo Oba ilu Kano, Sanusi Lamido Sanusi lawon afobaje mu o, ijoba si ti fowo si i." Oro naa si di iroyin kari aye lese kan naa, gbogbo aye n pariwo pe Sanusi Lamido Sanusi loba Kano tuntun.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, June 26 @ 00:34:59 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· EsinIslam Media Yoruba
· Ekunrere Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere:
Oye Okere Tilu Saki, Ile-ejo Ni Mogaji Ko Gbodo Gbe Igbese Kankan Bayii


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere

"Bi Sanusi Lamido Sanusi Ti Papa Di Oba Ilu Kano Lehin Awuyewuye Ati Ijaagboro" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: