Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara
[ Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara ]

·Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
·Arungun Loko Mi, Gbogbo Irinse Mi Lo Ti Baje, Mi O Fe e Mo Abigail
·Oko Mi Fi Pata Mi Soogun Owo Philomina
·Emi Atoko Mi Ko Ja, Nitori Omo Lawon Ebi Re Se Fee Le Mi Jade - Rafia
·Latodun Merin Seyin Loko Mi Ko Ti Ba Mi Lasepo, Mi o Se Mo - Folasade
·Odo Ni Wolii Moses Ti Ni Ki David Loo We Iwe Isegun, Lo Ba Fogbon Ji Moto Re Gbe
·Oro Buruku Toun Terin: Awon Omo Poli Ojere Mefa Daku Lakooko Ti Won Fee Sedanwo
·O Sele L'Egba! Seun Bimo Kan Fokunrin Meji L'Abeokuta
·Babalawo Fewon Jura Lori Esun Aini Salanga L'Ondo

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Iku Ti O Pa Alaaji Azeez Arisekola Alao Aare Musulumi Ile Yoruba, Gbogbo Eniyan
 
 
Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
Lati Olawale Ajao, Ibadan

Iku Ti O Pa Alaaji Azeez Arisekola Alao Aare Musulumi Ile Yoruba, Gbogbo Eniyan Ni Yio Pa! Sun Re O, Alao!

Bi ko ba se ti eja nla to lo nibu yii, ani ti Aare Musulumi ile Yoruba, Alaaji Azeez Arisekola Alao ba si wa laye, yato si pe ojoojumo lo maa n fowo ran awon eeyan lowo, bii ki awon eeyan pe eni awon kan n saisan tabi pe iya owo ileewe n je awon, lati ose ta a wa yii gan-an ni ile okunrin naa iba bere si i gba yun-un fun ogooro awon musulumi ti yoo maa waa gba nnkan aawe lojoojumo, bo tile je pe ile e ki i wule fi ojumo kan sinmi igbalejo ero tele niwon igba to ba wa nile.

Bo ba waa di ojo odun Itunu Aawe, gbogbo awon to ti n jeun ofe lojoojumo yii ni won yoo tun ba a lalejo, Arisekola ko si ni i tori e roju koko, terin tawada ni yoo fi fun won lowo leyin ti won ba je ti won mu tan. Oro yii ko yo awon kristeni paapaa sile, koda to fi mo awon eeyan pataki pataki laarin ilu, eni gbogbo to ba ti lo sile okunrin yii ni yoo dunnu pada sile nitori owo to joju lagba onisowo naa yoo fi ta won lore. Oun si lenikan soso ta a mo nile yii ti odidi gomina ipinle n loo ba sodun nile, ti okunrin alowo-lodu yii yoo si tun di owo si odidi olori lapo bamubamu. Bee naa si ni lojo Ileya odun nla.

Ko jo pe awon ti won n gbara dale fun ekun nile Arisekola lojo ti okunrin naa ku yii tile ti i ranti awon asiko odun ti a n so yii, opo ninu won lo se pe oto ni ohun ti won ba lo sile e tele ki won too se konge ipapoda oloore won. Se o to bii ose meji kan to ti lo si idale, oun funra e lo si dagbere fun won pe oun yoo de l’Ojobo, (Tosde), ojo kejidinlogun, osu kefa, odun yii, ati pe lojo naa gan-an ni ki won waa pade oun nile waa gbowo.

Adehun ti Aare Musulumi ile Yoruba se fawon eeyan yii lelomi-in tori e lo sile e, won ro pe okunrin olowo ti-i-fowo-saanu naa ti de ki won ki i ki won tun le dogbon rowo mu lo sile ni, afi bi won se debe ti won ba gbogbo ara ile lori ekun sisun. Iroyin iku Arisekola dun abiyamo mi-in koja iku omo, o si dun olulufe mi-in wora koja ka pe aya e lo fo sanle to gborun lo. Awon wonyi gba pe ko si nnkan fawon nile aye mo nitori eni to je ki aye nitumo si awon lo ti dagbere faye nni.Ko si ya ni lenu bi omi-in ninu won se fo soke gbe ara won janle logede-n-gbe, won ni bi omo Alao ba lo sorun ti awon naa ba tele e lo ko se nnkan kan. Orisiirisii oro to safihan edun okan bii Ibadan ti lo.

Ogo Ibadan lo. Asiri mi tu. Yee, temi ba mi, ola ni won ni ki n waa gba nnkan ojoobi mi≈, ati bee bee lo n tenu awon abanikedun jade. Gbogbo arowa ti awon aafaa n pa nibe ko tile wo won leti, aye ko nitumo si won mo leyin iku Arisekola. Lati nnkan bii aago meji osan, iyen l’Ojoru (Wesde) to koja ni iroyin naa ti bere si i ta si awon kookan leti. Nigba ti yoo si fi di aago meta osan ojo naa, okiki ti n kan, nitori awon kan ti n gbe iroyin naa si ori ero ayelujara. Isele ohun kan Gomina ipinle Oyo, Seneto Isiaq Abiola Ajimobi, kuu.

Gbara ti iroyin ohun kan an lara loun funra e ti gbera lo sile Aare laiduro de enikeni. Ajimobi lo duro gege bii akobi Arisekola lojo naa nitori oun lo gbalejo gbogbo awon to loo ba ebi oloogbe kedun eni won to lo.

Ibe si ni gbogbo awon eeyan pataki pataki lawujo ti won lo sile yii lojo naa ba a. Lara won la ti ri Igbakeji Gomina ipinle Oyo, Oloye Moses Adeyemo< Aya Gomina ipinle naa, Oloye Abileko Florence Abiola Ajimobi; agba-oje oniwaasi nni, Alaaji Taofeek Akeugbagold; Azeem Gbolarumi ti i se Igbakeji Gomina Oyo nigba kan ri; Alaaja Monsurat Sumonu (abenugan ileegbimo asofin ipinle Oyo); minisita fun eto akanse ise fun ijoba apapo ile yii nigba kan ri, Alagba Wole Oyelese atawon eeyan nla mi-in repete. Ilu London ni Aare Musulumi ile Yoruba ku si, ohun ta a si gbo lenu awon to sunmo baba naa daadaa ni pe aisan jejere lo se e. Won ni itoju aisan yii lo tori e lo si London ko too ba olojo pade. Sugbon nibi ayeye isinku e to waye ni papa isere nla Adamasingba, n’Ibadan, ni alaga egbe awon musulumi lorile-ede yii, Alaaji Isiaq Kunle Sanni, ti so pe oro naa ko ri bee rara, o ni nise ni baba naa kan sun ti ko ji mo, ati pe ko too sun lo ti so fawon to wa laroowoto e pe oun fee reju die, ti oun ko ba si ji funra oun leyin wakati meji, ki won ji oun nigba naa. Jiji ohun ni won ji i nigba ti won ko ri i ko dide nile ti won si ri i pe akuko ti ko leyin omokunrin.

Bi okiki iku re ti n kan ni awon ero n ro girigiri lo sile re, awon mi-in ko si ti i le soro gidi tabi mo ohun ti won yoo so lori iku na rara. Awon oba nla bii Alaafin Oyo to je ore timotimo Arisekola ko le jade sita, bee ni ko gbalejo, nitori boya ni ojumo kan mo ti awon mejeeji ko ni i rira, tabi ki won soro fun igba pipe. Ko si ibi ti Alaafin n lo ti Arisekola ko mo, ko si ibi ti Arisekola n lo ti ko ni i wi fun Alaafin.

Awon kan tile so fun Iwe Iroyin Yoruba pe ilu London ni Sultan funra re wa nigba ti Arisekola ku yii, o si wa ninu awon ti won n seto lati tete gbe Aare pada wa sile fun sinsin. Ni bii aago merin owuro ojo Eti ni won gbe e de lati ilu oyinbo, bo si ti de ni awon moto to tele ara won lati papa-oko-ofurufu Ikeja, ile ko si ti i mo daadaa nigba ti won ti wo ilu Ibadan. Ni kutukutu owuro ojo naa ni awon ero ti n ro lo si Adamasingba, nibi ti won ti fee sadura ikeyin fun un ko too di pe won sin in. Opo awon ore re ati awon oloselu ti won wa ni won ko soro, awon mi-in kan n somi loju ninu won ni. Awon bii Oba Otudeko, Elejigbo Oba Omowonuola Oyesosin, awon gomina ile Yoruba pata, titi dori Asiwaju Tinubu ati awon olori egbe PDP pata, gbogbo won ni won wa nibe, bee lawon olorin esin igbagbo lati ori Bisoobu Ayo Ladigbolu ati awon bisoobu mi-in gbogbo. Elomiran ko si gba pe Arisekola ti ku, afi nigba ti won gbe okunrin naa wo inu iho ile lo.

Bi ero ti po ni Adamasingba, bee ni ero po ni Basorun, awon mi-in si n lakaka lati fowo kan posi re, bo tile je pe awon ti won sunmo on so pe oun fura re ti seto ibi ti won yoo sin oun si, o ti so pe ki won sin oun si egbe iya oun ni. Nibe naa ni won sin in si, ti awon iyawo ati awon omo re si wa nibe ti won n wo ikeyin baba won. Ki i se pe oro egan, aye ye okunrin musulumi ododo naa de orun ni, nitori awon ti won n sin oku re ko to awon ti won duro titi ti won n sunkun saa, bee ni awon ti won si n sunkun ko po bii awon ti won n fi gbogbo enu sadura, ti won n so pe afi ki Olorun dari ese gbogbo ji Alao Azeez, ki Olorun te Arisekola safefe rere.

Beeni, "Odo Olohun Ni A Ti Wa, Odo Re (Olohun) Naa Si Ni A O Pada Si," Eyi nii Olohun wi ninu Iwe Mimo Re Alukuriani Alaponle. Ki Olohun foriji baba rere yii. Ki Olohun si gba a sinu Ogba Idere Alujana Firidaosi - Amin

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, June 26 @ 00:50:35 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin:
Buhari Omo Musa Sa Kuro Nibi Ayeye Igbeyawo Saidi Osupa: Lehin Ti Alfa Muri Fun


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin

"Iku Ti O Pa Alaaji Azeez Arisekola Alao Aare Musulumi Ile Yoruba, Gbogbo Eniyan " | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: