Tite Wole
  Create an account
Ojule Nyin
Tite Jade
 
 
 
Yoruba

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Ẹ Forukọsilẹ Bayi!.

Onka Ni Oju-Agbo

Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi

Iwadi Ni Yoruba
Tumo Yoruba Sede Miran

E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:


Irohin Nitele-N-Tele


Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo
[ Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo ]

·Ilu Kan, Oba Marun-Un: Oba Ni Egba Ake, Egba Owu, Egba Agura, Oke Ona Ati Ibara
·Eyi Ni Bi Owo Se Te Alao To Fi Khadija Omo Igbakeji Mimiko Soogun Owo L'Aku
·Itan Bi Ladoke Akintola Se Di Aare-Ona-Kakanfo Ile Yoruba
·Eni Ba Fibi Soloore, Iya Ni Yoo Je Ku
·Akanni She Ayederu Iwe INEC, O Lashofin Loun, Lo Ba Fi Gba Awon Eeyan Repete
·L'Oshogbo, Awon Omo Egbe Okunkun Ti Won Fesun Ipaniyan Kan Foju Bale-ejo
·O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
·Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
·Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Ipase Awon Eto L'owoyi

Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.

Ona Igba Wole Si Agbo

Oruko-Aroso

Oro-Asiri

Se E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi? Ko Buru, E Lee Fi Oruko Sile E Te Ibi Yii Lati Fi Oruko Sile. Lehin Iforukosile, Anfaani Pupo Wa Fun Nyin, Fun Apere E Le Se Atunto Oju Ewe, E Si Lee Tun Fi Ase Sile Nipa Bi Awon Alaiye Yio Ti Han, Ati Wipe E Le Se Ifiranse Awon Alaiye Ti Yio Han Gedegbe Pelu Oruko Nyin Ni Ti Faari.

Awon Atoka Ti Atehinwa

Thursday, September 12
· Won Le Awon Omo Nigeria Ni South Afrika Poo!
· O Ma Se O, Eyi Ni Abayomi Adigun, Osise Telifisan AIT Se Ku Sowo Awon Ajinigbe L
· Nitori Eedegbeta (500) Naira, Odaju Baba Sun Omo Re
· Amugbalegbe Igbakeji Gomina Ipinle Ogun Se Igbeyawo Alarinrin, Gbegbo Aye Lo N R
· Xenophobia (Ikorira-Ajeji): Irinwo Omo Naijiria Ni Won Ti Gbaradi Lati Fi Orile-
· O Ma Se O, Olajumoke Di Awati N'Ilorin
· Nitori Esun Gbajue, Purofeso Fasiti Foju Bale Ejo L'ekoo
· Won Ju Ayomide Sewon L'Abuja Nitori Esun Jibiti
Sunday, September 01
· Ija Ti Waye Ni Papa Oko - Ofuurufu Ti Abuja: Hammed Tewon De
· Arabinrin Ti Fi Iya Je Omo odo Re Nitori O Ke Pe Iranlowo
· Baba Ti Omo Re Pa Fun Ogun Odun Nitori Warapa
· Nibi Ti Pasito Ti N Waasu Lo Tun Ti Ji Foonu N'Ibadan: Oro Buruku Toun Teri
· Alashewo Lo Po Ju Ninu Tiata - Igbanladogi Ju Bombu Oro Sita
· Won Le Awon Omo Naijiria Metalelogun Kuro Ni Saudi Arabia: Iyaale Ile Omo Naijir
· Aye o! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji: O Ma
· Eyi Ni Ashiri Bi Won Se Tan Ismaila Pa L'ojo Odun Ileya
· Odaju Abiyamo Re o: Baba Lu Omo Re, Omodun Meta Nilukilu: Won Fun Iyaale Ile Lor
· Hausa Ati Yoruba Koju Ija Sira Won L'ekoo: O Ma She O, Awon Omo Egbe Okunku
· O Tan! South Africa Lawon Omo Naijia Ko Le Wo Iluwon L'ofe: Owo Te Awon Omo
· Arewa Omoge Ji Telifison Nla Ni Oteli: Won Ji Iyaale Ile Nibi To Ti N She Ere Id
· O Ma She o!, Komishana Padanu Iya Ati Omo Meji Lojo Kan Shosho: Igbakeji Ipinle
· O Ma She O! Awon Baba Arugbo Fipa Fa Idi Won Omodun Merin Ya Ninu Ile Akoku
· Lojo Odun Ileya, Awon Fijilante Banuje Nitori Okan Lara Nwon To D'Oloogbe
· Nitori Orekunrin Re Ko O Sile, Omodun Merinla Pokunso Ni Delta: Won Ti tu Yewand
· E wo Oju Awon Omo Yahoo Ti Won N Foruko Oshinbajo Ati Aisha Buhari Lu Jibiti
· Ileewe Alakobere Ni Mo Ti N Gbadun Ibalopo, Ko Jo Mi Loju Mo Rara - Oshere Tiata
· Ijoba Ko She E Da She Lai Si Iriri Awon Agbaagba nibe - Gomina Abiodun
· Ayeye Odun ileya: Egbe So Safe Corps Fee Wo Iya-Ija Pelu Awon Odaran
· Aye O! Won Fipa Ba Omoge Arewa Sun Niwaju Shoosshi, Lo Ba Soda Sorun Alakeji
· Aalo Onitan: Ijapa T'ohun Ti Ikarahun Re

Awon Atoka Ti O Ti Pe

Yor b

- Ojule
- Koko Mẹwa
- Ẹka Abule
- Ifirohin-Ransẹ
- Iwadi
- Oju-Agbo Yoruba
- Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba
- Agbeyẹwo
- Ifiranṣẹ Ara-ẹni
- Ifimufilẹ
- Iwe Akọọlẹ
- Apoti Akọsilẹ
- Akoonu
- Isopọ Ọpọnlujara
- Ẹgba Ayelujara
- Ibeere Ti Ọwọpọ
- Ipolongo Wa
- Ẹkun Imọ Ọfẹ


Ohun Tawon Oloselu Wa Se N Pa Ara Won Nitori Ipo Ree O
 
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
Lati Owo Adejare

Ohun Tawon Oloselu Wa Se N Pa Ara Won Nitori Ipo Ree O

Bi a ba n se bayii, aye ko ni i roju. Bi a ba n se bayii, aye ko ni i dara.

Bo ba je bayii la n se, Naijiria yii ko ni i toro fun gbogbo wa. Ni gbogbo igba ti mo ba n ka oro aburo wa yii, iyen Lai Muhammed, nise ni aanu awon mekunnu ile yii maa n se mi, aanu awon araalu a si se mi pe titi, nitori lojokojo, nigbakigba ti wahala ba de, awon eeyan bii Lai ati awon asaaju oloselu ko ni i farapa nibe, won yoo ti rin jinna, won yoo ti sa lo, awon mekunnu ilu ni won yoo je pupo ninu iya ibe, awon ni won yoo farapa. Awon mekunnu ni won ko lowo, won ko nile l’Amerika won ko si leeyan nibe, bi won si leeyan, won ko ni owo moto ti won yoo wo lo, bi won ba lowo paapaa, oyinbo ko ni i fun won ni fisa, won yoo so pe won n sa lo ni.

Sugbon bi mekunu ko ba ni i fi iya je ara won, ti won ko si fe ki iya je aromodomo won, ohun akoko ti won gbodo se ni lati jinna sawon oloselu, nitori awon oloselu ta a ni lasiko yii ni won n ba aye awon omo Naijiria gbogbo je, awon naa ni won n so Yoruba dero eyin.Nibi iro ati etan ni won fi n ba wa laye je, nibi ka huwa ibaje ni koro, ka si ti sare ja gbangba, ka maa pariwo foo pe awon kan lo n se bee, eeyan mimo, eeyan Oloun lawa. Lose to koja, nigba ti ariwo n lo kaakiri ibi gbogbo pe gomina ipinle Akwa Ibom, Godswill Akpabio, ba aye je, o fee dori aye kodo, o seto owo ifeyinti ti oba ilu oyinbo ko gba fun ara re, ironu nla ba mi, mo si n ronu iru ohun ti awon eeyan bii Lai yoo so. Omo egbe PDP ni Akpabio, bi eeyan ko ba si je oloriburuku laye ati lorun, ko ni i ko iru owo bee yen fun ara re pe oun yoo maa gba a leyin ti oun ba fi ise sile tan. Owo ti oun nikan fee maa gba lowo ijoba ipinle naa losoosu leyin to ba ti gbe ijoba sile le ni milionu lona ogorun-un Naira, ohun to fee fi iru owo bee se ko ye enikan. Bawo leeyan kuku se n daju to bee, bawo ni eeyan yoo se ba aye awon araalu je nitori ti ara re nikan tabi ti idile re, ohun ni mo se fee gbo ohun ti Lai yoo so.

Sugbon Lai ko soro, okan ninu awon omoose re lo so o, egbe APC si binu gidi, won ni nibi ti awon eeyan ko ti ri ounje je ni ipinle Akwa Ibom yii, ti iya n je won, ti osi si n ta won to bayii, nibe ni enikan ti dide, to ni oun yoo maa gba owo ifeyinti to to bayii, nitori pe o fi odun mejo pere sise fun ilu re. Egbe APC ni ko si ohun meji ti eeyan yoo pe iru iwa bayii, ole jija ni, eyi si fi han pe ole paraku lawon ti won n se egbe PDP, won ko ba ohun meji wa sile ijoba ju ki won waa ji owo araalu ati dukia won ko lo. Loooto loooto, bi kinni naa ti ri niyen, enikeni, egbe oselu yoowu, ijobakijoba to ba se ohun ti Akpabio se yii, ole, jaguda paali ni, bo ba si je ibi ti ofin won ti le koko ni, bi won koyin iru eni bee si agba, ko se kinni kan. Tabi bawo ni eniyan kan yoo se tori pe oun sise ilu fun odun mejo, ti yoo si so pe ki ilu maa san owo ounje, owo ile, owo alejo, owo aiyaara, owo itoju ile, owo itoju ebi, ara ati ore foun, ti won yoo si maa ra moto foun atiyawo oun lodun merin merin, ti won yoo si maa sanwo gbogbo osise to ba wa nile awon.

Ki waa ni ki awon ti won fi odun marundinlogoji sin ijoba, tabi awon ti won ti dagba di omo ogota odun ti won si fi bii ogbon odun sinjoba se. Bee awon wonyi wa niluu, owo ifeyinti to ye ki won gba, won ko reni san an, to se pe pupo ninu won lo n ku si ori-ila, nibi ti won to si, ti won n reti owo ti enikan ko ni i fun won.

Gbogbo wa la n pariwo pe awon soja Naijiria n binu, won n ja, won ni awon ko le loo koju Boko Haramu, sugbon soja wo ni yoo ri gbogbo eyi ti awon gomina wa n se yii ti yoo loo koju Boko Haramu, tabi osise ijoba wo ni yoo ri ohun tawon oloselu n fi aye awon mekunu se yii ti yoo wa nipo kan ti ko ni i jale, ti ko ni i jiwo ko, bawo ni awon oloselu funra won ko si se ni i maa puro, ti won ko ni i maa yinbon pa ara won nitori ki won le depo gomina, nigba to se pe titi aye ni won yoo maa gbowo lai se ise kan. Ilu yoo si tun maa sanwo fun won nitori pe won ba tiwon je. Ohun ti mo se faramo oro kobakungbe ti APC so si Akpabio, gomina PDP to fee ni awon araalu lara niyen.

Sugbon o, o ye eni gbogbo ko dinwo alagbafo, ko ye atoole, oro bayii ko dun lenu APC atawon asaaju won, nitori ole kan naa ni gbogbo won. Oloselu Naijiria kan ko yato lati Eko to fi wo Gombe, afi ti won ba n puro, ti won si n tan awa araalu je nikan lo ku o, egbe aninilara, ajowo-ilu-ko ni gbogbo won. Boya awon agbenuso ati alariwo inu egbe yii gbagbe ni pe gbogbo ohun ti awon gomina oloselu asiko yii n se yii, Bola, asaaju egbe won lo koko se e ni gbogbo Naijiria yii. Ko si oloselu kan, tabi gomina kan, tabi aare paapaa, to laya lati se iru nnkan bayii, afi igba ti Bola se e. Bi oloselu to wa nipo gomina ba fee se asise, ile igbimo asofin lo ye ko tete da a lowo ko, ki won so pe ohun ti won fee se ko dara. Sugbon lojo naa lohun-un, ile igbimo asofin Eko labe Kuforiji ko ri ohun to buru ninu ohun ti gomina naa fee se ni 2007, kaka bee, won gbe e pamo fun araalu, won ti fowo si i tan ki enikeni too gbo, aarin ojo meta pere ni won si fi yanju e.

Boya ni opo eeyan mo nile yii pe iye owo osu kan naa ti Fasola n gba gege bii gomina naa ni Bola n gba, yoo si gba owo naa titi ti yoo fi ku ni, nitori o ti wa ninu ofin ifeyinti to se nigba to n se gomina pe iye owo ti gomina to ba wa nipo ba gba loun naa gbodo maa gba. Bakan naa lo je pe ijoba Eko gbodo ko ile kan fun un si ibi yoowu to ba fe l’Ekoo, won si tun gbodo ko ile kan fun un ni ilu Abuja. Nile ba di meji. Moto mefa ni won gbodo fun un ni tuntun, won yoo si maa paaro moto naa lodun meta meta, iyen ni pe Bola ti gbodo gba moto mefa lowo ijoba ipinle Eko ni 2007, yoo tun gba mefa mi-in ni 2010, yoo si tun gba moto tuntun mefa mi-in ni 2013, nitori odun meta meta ni won gbodo maa paaro e. Osise marun-un ni Bola yoo ni bo ti se wa ninu ofin won, ijoba ni yoo si maa sanwo won. Leyin naa ni won yoo fun un ni olopaa mejo, SSS meta, ati won eso mi-in ti won yoo ma so oun nikan. Ijoba ni yoo maa sanwo ti won yoo fi tun moto re se, bee ni odun meji meji ni yoo maa paaro aga ati sia ile re, ilopo meta owo osu re ni yoo si maa fi se eyi.

O tun ku orisiirisii nnkan o, o tun ku awon owo ati alawansi loriisiirisii, owo tawon ara Eko n san fun Bola nitori pe o se gomina won lodun mejo niyen o. Leyin ti oun se tie ni awon gomina mi-in bere si i tun ofin ifeyinti won se, sugbon ko si teni naa ninu won to sunmo ti Bola yii. Eyi to sunmo on die ni ti Bukola Saraki, ni Kwara ti Lai ti wa, iyen a fere gba gbogbo owo ijoba ibe tan, afi ti pe oun ko ni ki won ko ile kan s’Ekoo, ki won ko okan si Abuja foun, ile bongalo lo ni ki won ko foun. Ofin ti yoo tun sunmo ti Bola yii ni ti Akpabio to se, ti gbogbo ilu si n pariwo, sugbon ni tododo, nibikibi ti a ba ti da a sile ti a tun un sa, ko si ofin ifeyinti fun gomina kan ati igbakeji re to to ti Bola ni gbogbo Naijiria, koda ko si iru re leyin odi.

Gbogbo ohun ti mo so pata yii lo wa ninu iwe, gbogbo e lo wa nile igbimo asofin Eko, eni ba wa a debe yoo ri i.

Ib ti oro naa waa buru si ni pe awon gomina yii yoo so awon ipinle won di olosi ati onigbese gbeyin ni, tabi nigba ti gomina Eko ba n lo si bii mewaa ti won ti feyinti, to si je pe awon ohun to to si Bola yii naa lo to si gbogbo won, nibo ni ijoba yoo ti maa ri iru owo bee san fun gbogbo won. Sugbon bi awa naa ba jokoo ti a ba ronu, ti a si ye oro naa wo, ti a si ko oro oselu ati aimokan-mokan kuro, a oo mo eni to n sise fun ilu, a oo mo ore araalu ati awon ti won kan n gba araalu loju, ti won n ko owo won je. Ni ipo ti Olorun to Bola ati awon gomina atijo wonyi si, se bi won ba fee gba olopaa ti yoo maa so won, won ko le gba a ni, se won ko le fowo ara won kole sibi ti won n gbe ni tabi won ko nile, se won ko le ra moto funra won ni abi iye osise ti won ba fe, won ko le gba won. Sugbon awon eeyan wonyi ki i na owo tara won, owo araalu lo maa n ya won lara lati na, won ko si se oore tabi ise ofe kan fun mekunnu, nitori won yoo gba ju owo ise ti won ba se lo.

Ipade apero ti so pe awon ko ni i je ki gomina kan seto owo ifeyinti nigba to ba wa nipo mo, won fee gbe e sinu ofin. Amoran temi ni pe ki won ma duro lori iyen, ki won pa gbogbo ofin ole, ofin ininilara ati idogbonjale tawon gomina atijo wonyi ti se re, ki won si se ofin ifeyinti awon gomina ti gbogbo Naijiria yoo maa lo, nitori bi eeyan ba gbe aye awa mekunnu ilu le awon ajenifeni wonyi lowo, won yoo kan ba aye gbogbo wa je patapata ni.

 
 
 Posted By Ifiranse Eleyi Je Thursday, June 26 @ 00:53:12 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Comments & Debates :-: التعليقات والمحاورات

 
 
For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا
 
 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 

Awon Itona Ti O Bayi Mu

· Ekunrere Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Irohin Lati Owo MediaYorubaTeam


Eyiti Ti O Je Kika Ju Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwon Didi Lori Atoka

Iyeju Enu Awon Ti O Ni Iwon: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

E Jowo E Fi Iseju Kan Pere Sile Lati Kopa Ninu Ibo Didi Fun Atoka Yii:

O Dara O Lekele Kan O Dara Pupo O Dara Ni Opolopo Igba Tabi Ni Gbogbo Igba Ko Dara

Awon Iyanbo


 Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun Eyi Wa Fun Lilo Printer Ni Irorun


Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

"Ohun Tawon Oloselu Wa Se N Pa Ara Won Nitori Ipo Ree O" | E Se Atewole/Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam | 0 Awon Alaiye
Gbogbo Awon alaiye Je Ti Eniti O Ba Fiwon Ranse. EsinIslam Ki Yio Gbe Ebi Kebi Ti O Ba Ti Ipase Awon Oro Ati Ohun Atoka Ti Kowa Ba Fi Sowo L'ori Alantakun Yii.

A Ko Fi Aaye Lati Se Alaiye Gba Eniti Ko I Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam, E Jowo E fi Oruko Sile Lati Lo Si EsinIslam Nibiyii
 

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Fatwa Rulings, Muslim News Newspapers Magazines Headlines Articles Forums Schools, Universities, Colleges, Mosques, Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

  :-: Go Home :-: Go Top :-: