Prev  

114. Surah An-Nâs سورة النّاس

  Next  




1st Ayah  1  الأية ١الأولي
بِسْم ِ اللهِ الرَّحْمَٰنِ الرَّحِيمِ
قُلْ أَعُوذُ بِرَبِّ النَّاسِ
Qul aAAoothu birabbi annas

Yoruba
 
Sọ pé: "Mo sá di Olúwa àwọn ènìyàn,

Ayah  114:2  الأية
مَلِكِ النَّاسِ
Maliki annas

Yoruba
 
Ọba àwọn ènìyàn,

Ayah  114:3  الأية
إِلَٰهِ النَّاسِ
Ilahi annas

Yoruba
 
Ọlọ́hun àwọn ènìyàn,

Ayah  114:4  الأية
مِن شَرِّ الْوَسْوَاسِ الْخَنَّاسِ
Min sharri alwaswasi alkhannas

Yoruba
 
Níbi aburú (Èṣù) oníròyíròyí, olùsásẹ́yìn (fún ẹni tó bá ń dárúkọ Allāhu).

Ayah  114:5  الأية
الَّذِي يُوَسْوِسُ فِي صُدُورِ النَّاسِ
Allathee yuwaswisu fee sudoori annas

Yoruba
 
(Èṣù ni) ẹni tí ó ń kó ròyíròyí sínú àwọn ọkàn ènìyàn.

Ayah  114:6  الأية
مِنَ الْجِنَّةِ وَالنَّاسِ
Mina aljinnati wannas

Yoruba
 
(Èṣù náà) wà nínú àwọn àlùjànnú àti àwọn ènìyàn."





© EsinIslam.Com Designed & produced by The Awqaf London. Please pray for us