Gbagede Yoruba
 



O Sele N'Ilesa, Alice Ko Lo Sile Ore Oko Re, O Loun Lo N Toju Oun Atawon Om
 
Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
Lati Owo Bisi Adesoye, Ilesa

O Sele N'Ilesa, Alice Ko Lo Sile Ore Oko Re, O Loun Lo N Toju Oun Atawon Omo

Ogbeni Babalola ati ore re timotimo lati igba ewe, Odejide, ti koju ija nla sira won bayii niluu Ilesa, bee ni won n fi oogun abenu-gongo wa ara won leyin ti Babalola ti loo fi olopaa mu ekeji re. Ohun to fa ija-ajaku-akata yii ni pe Odejide fi iwa agbere gba Alice, iyawo Babalola, bee oun lo maa n ba won pari ija lasiko ti wahala ba sele ninu ile won. Lesekese ti Babalola fura si iwa agbere ti iyawo re n hu pelu ore re lo ti fi olopaa mu un, tiyen si lo ojo meloo kan lahaamo ki won too da a sile.

Eni ti oro naa soju e so fun akoroyin wa pe gere ti Odejide jade ni ahamo awon olopaa ni Alice, iyawo Babalola ti taku pe eni ti oko oun fesun kan oun pe oun n ba se agbere loun maa fe, iyen leyin omo meta to ti bi fun oko re.



Ka too wi, ka too fo, Alice ti ko kuro nile Babalola, odo ore oko re lo ko lo gege bii iyawo keji. Nigba ti Alice maa se pabambari, nise lo kori sile-ejo ibile kan n'Ilesa lati tu igbeyawo olodun mewaa to wa laarin oun ati Babalola ka.

Nigba ti ile-ejo naa n se idajo re l'Ojobo to koja lo so pe afaimo ki iku ojiji maa sele laarin olupejo ati olujejo ti ile-ejo ba ko lati tu igbeyawo naa ka, nitori esu ti joba ninu igbeyawo naa. Lori eyi ni Adajo tu igbeyawo naa ka, to si ni ki awon omo meteeta, Tunde, Yemi ati Dupe wa lodo iya won.

Nigba ti akoroyin wa n ba Babalola soro leyin idajo ohun, o ni ko soro kankan toun le so nitori ile-ejo ti se idajo re, eyi to te oun lorun, sugbon iyan ogun odun si maa n gbona felifeli.

Ninu oro Alice pelu akoroyin wa lo ti ni oun n gbadura si Olorun lati wo awon omo oun, ki ibagbe oun pelu Odejide si ja si rere. O ni okunkun ko le duro nibi ti imole ba wa, ati pe ti ko ba si itoju to peye latodo oko si iyawo re, iru eleyii le sele.

Alice fi kun un pe asiko kan wa to je pe Odejide lo maa n fun oun atawon omo oun meteeta lowo ounje ati pe nigba mi-in, a maa n san owo ileewe won laise pe oko oun ko nise lowo, sugbon ti ko bikita. O ni gbogbo bi oro naa se n lo loun maa n fi to awon ebi Babalola leti, sugbon sibe, ko si ayipada rere kankan lara re.


 Posted By Ifiranse Eleyi Je Sunday, March 30 @ 05:16:18 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam



Comments 💬 التعليقات
 

For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا

Awọn ọna asopọ ti o jọmọ

· Die sii Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga
· Iroyin Nipasẹ MediaYorubaTeam


Ọpọlọpọ Itan Ka Nipa Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga:
O Sele! Iya Nimota Lo Oogun Ti Oyan E Fi Maa Tobi Si i, Loko Ba Da Eru E Sita: B


Iwọn Abala

Apapọ Dimegilio: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

Jọ̀wọ́ Gba Ẹ̀ẹ̀kejI ki o sI dIbo fun Abala YIi:

O tayọ
O dara pupọ
O dara
Deede
Buburu


Aṣayan


 Ọrẹ-itẹwe Ọrẹ-itẹwe





Akole Atoka Agbo-Oro

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga



"O Sele N'Ilesa, Alice Ko Lo Sile Ore Oko Re, O Loun Lo N Toju Oun Atawon Om" | Buwolu wọle/Ṣẹda Eto Akọsilẹ | 0 Awon Alaiye


Awọn asọye jẹ Ohun ini nipasẹ Iwe ifiweranṣẹ. A Ko Lodidi Fun Akoonu wọn. Nibayi, A Pe Awọn oluka lati jabo Eyikeyi Abusive, Unsuitable And/tabi Islamophobic Content



Ko si awọn ọrọIwoye Ti o gba laaye Fun Aisinisi, Jọwọ Forukọsilẹ
 

Gbagede Yoruba
Akọọlẹ Tirẹ
Ojule Akọkọ  | Awọn Itan Yoruba  | Gbagede Yoruba  | Ifiranṣẹ Ara-ẹni  | Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba  | Koko Mẹwa  | Ẹka Abule  | Ifirohin-Ransẹ  | Iwadi  | Agbeyẹwo  | Ifimufilẹ  | Iwe Akọọlẹ  | Apoti Akọsilẹ  | Isopọ Ọpọnlujara  | Ẹgba Ayelujara  | Ipolongo Wa


Ẹsin Islam الدين الإسلامي Religion of Islam Addinin Musulunci Agama Islam Religión del Islam 伊斯兰教 Dini ya Kiislamu Религия Ислам Religião do Islã イスラム教 Esin Islam 이슬람의 종교 Portal African Muslim Website - Arabic English African Islamic Website For World News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Articles, Radio, Audio, Video, Quran, Hadith, TV Channels, Fatwas, Muslim News, Newspapers, Magazines Headlines, Forums, College, Schools, Universities, Mosques, Quranic, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Ramadan, Vidoes, Books, Fasting, PDFs On EsinIslam.Com And IslamAfrica.Com